The Smart Money Woman
The Smart Money Woman | |
---|---|
Fáìlì:The Smart Money Woman poster.jpg | |
Written by | Jola Ayeye |
Directed by | Bunmi Ajakaiye |
Starring | Osas Ighodaro Kemi Lala Akindoju Timini Egbuson Toni Tones |
Country of origin | Nigeria |
Original language(s) | English |
No. of seasons | 1 |
No. of episodes | 7 |
Production | |
Executive producer(s) | Arese Ugwu |
Producer(s) | Kemi Lala Akindoju |
Production location(s) | Lagos, Lagos State, Nigeria |
Release | |
First shown in | Nigeria |
Original release | present |
The Smart Money Woman Jẹ fíìmù orílẹ̀-èdè Nàìjíríà oloṣeṣe ti o da lórí aramada 2016 ti orukọ n je Arese Ugwu.[1] Afihan akoko rẹ̀ jàde lórí AfricanMagic Showcase ní oṣù kẹsan ní ọdún 2020.[1] A ṣè àwọn fíìmù náà lati ṣe iṣe iyasọtọ ati mu ohun ti o wa nínú iwe aramada náà wa si oju aye.[2] Akoko Afihan ise yi, jàde ní ori AfricanMagic gege bi ise oni'pele mẹtala.[1][3] Onkọwe Arese Ugwu àti Kemi Lala Akindoju lo gbe jàde. O ya Osas Ighodaro, Timini Egbuson, Ini Dima-Okojie, Kemi Lala Akindoju àti ọpọlọpọ àwọn miiran.[1][4]
Agbékalẹ̀ Eré
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]The Smart Money Woman jẹ́ ìtàn àwọn obìnrin marun àti bí wọ́n se n ṣé iṣakoso inawo àti dukia, ìtàn aramada náà dale lórí eto inawo àwọn obìnrin ati bí o nse nipa ribiribi lori ojo iwaju inawo won..[5] ìtàn aramada náà tun sọrọ nípa àwọn ọrẹ, iwa nípa afarawe, àti bí àwọn ipa awujọ se n ṣé akoso inawo lawo li 'jo iwaju.[6]
Àwọn òṣèré
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Osas Ighodaro as Zuri
- Kemi Lala Akindoju as Adesuwa
- Toni Tones as Lara
- Ebenezer Eno as Ladun
- Eku Edewor as Banke
- Timini Egbuson as Bobby
- Ini Dima-Okojie as Tami
- Seun Ajayi as Soji
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 1.2 1.3 "Arese Ugwu's 'Smart Money Woman' series is coming to Netflix". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2021-07-28. Retrieved 2021-10-06.
- ↑ "'The Smart Money Woman' official trailer". Pulse Nigeria (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-08-13. Retrieved 2021-10-06.
- ↑ Odusola, Aby (2020-08-13). "The Smart Money Woman Series Is Coming To Our Screens In September!". The Culture Custodian (Est. 2014) (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-10-07.
- ↑ "The Smart Money Woman | Netflix". www.netflix.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-10-06. Retrieved 2021-10-06.
- ↑ Tv, Bn (2021-02-03). "The Cast of Arese Ugwu’s “The Smart Money Woman” Answer Questions on their Roles, Relationships & Finances". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-10-06.
- ↑ BellaNaija.com (2021-07-30). "Arese Ugwu’s “The Smart Money Woman” is Coming to Netflix". BellaNaija (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-10-06.