Up North
Ìrísí
Up North | |
---|---|
Fáìlì:Up North Poster.jpg Theatrical release poster | |
Adarí | Tope Oshin |
Olùgbékalẹ̀ |
|
Àwọn òṣèré | Àdàkọ:Startplainlist |
Orin |
|
Ìyàwòrán sinimá | Pindem Lot Kagho Bichop Idhebor |
Olóòtú | Banjo Onyekachi Ayodele |
Ilé-iṣẹ́ fíìmù | Anakle Films Inkblot Productions |
Olùpín | FilmOne Entertainment |
Déètì àgbéjáde | 28 December 2018 |
Orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Èdè |
|
Owó àrígbàwọlé | ₦94 million[1] |
Up North jẹ́ fíìmù àgbéléwò tí ó jáde láti ọwọ́ Anakle Films and Inkblot Productions [2]ní ọdún 2018 ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí diTope Oshin[3] ṣe olùdarí rẹ̀. Naz Onuzo and Bunmi Ajakaiye ló kọ ire náà látàrí itan tí Editi Effiong kọ.[4] Ní ìlú Bauchi ni wọ́n ya iṣẹ́ náà, pẹ̀lú yíya ọ̀sẹ̀ kan ní ìlú Èkó Lagos.[5]
Àwọn akópa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Banky W bíi Bassey Otuekong
- Rahama Sadau bíi Mariam
- Kanayo O. Kanayo bíi Chief Otuekong
- Adesua Etomi bíi Zainab
- Michelle Dede bíi Idara Otuekong
- Hilda Dokubo bíi Mrs Otuekong
- Ibrahim Suleiman bíi Sadiq
- Rekiya Attah bíi Principal Hassan
- Akin Lewis bíi Otunba
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Top 20 WA Films of 2019 - Cinema Exhibitors Association of Nigeria". www.ceanigeria.com. Retrieved 2020-06-29.
- ↑ "Up North Featuring Adesua And Banky W" (in en-US). Archived from the original on 2021-11-01. https://web.archive.org/web/20211101133659/https://guardian-ng.cdn.ampproject.org/v/s/guardian.ng/life/film/up-north-featuring-adesua-and-banky-w/amp?amp_js_v=a2&_gsa=1&usqp=mq331AQHCAFYAYABAQ==#aoh=15428763220309&_ct=1542876392736&referrer=https://www.google.com&_tf=From%20%251$s&share=https://guardian.ng/life/film/up-north-featuring-adesua-and-banky-w/.
- ↑ "Up North: Tope Oshin's thrilling joy ride". TheCable Lifestyle (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2019-01-19. Retrieved 2019-01-19.
- ↑ "TBoss, Kanayo O Kanayo, Rahama Sadau Banky W in Up North". amp-pulse-ng.cdn.ampproject.org (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2020-10-14. Retrieved 2018-11-18.
- ↑ "Making Nigeria’s biggest scale film: Producer Zulumoke Oyibo reflects on Up North". The Guardian Nigeria Newspaper - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2018-12-27. Archived from the original on 2019-04-10. Retrieved 2018-12-27.