Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 20 Oṣù Keje
Ìrísí
- 1968 – Ìdásílẹ̀ Ìdíje Olimpiki Pàtàkì.
- 1969 - Wọ́n sọ pé Apollo 11 balẹ̀ sórí Òṣùpá.
- 1980 – Ìgbìmọ̀ Ìṣẹàbò Ìṣọ̀kan àwọn Orílẹ̀-èdè dìbò 14-0 pé àwọn orílẹ̀-èdè tó jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ kò ní gba ìlu Jerusalem gẹ́gẹ́ bíi oluìlu orílẹ̀-èdè Israel.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1822 – Gregor Mendel, onímọ̀sáyẹ́nsì ará Jẹ́mánì (al. 1884)
- 1925 – Frantz Fanon, oníwòsàn àti olukọ̀wé ará Fransi (al. 1961)
- 1956 – Thomas N'Kono, agbábọ́ọ̀lu-ẹlẹ́sẹ̀ ará Kamẹrunu
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1953 – Dumarsais Estimé, Haitian lawyer and politician, 33rd President of Haiti (b. 1900)
- 1973 – Bruce Lee (fọ́tò), American actor and martial artist (b. 1940)
- 1982 – Okot p'Bitek, Ugandan poet (b. 1931)