Jump to content

Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní orílẹ̀-èdè Sudan

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ìbúrẹ́kẹ́ Àjàkálẹ̀ Àrùn Kofid-19 ní orílẹ̀-èdè Sudan
ÀrùnKofid-19
Irú kòkòrò èrànSARS-CoV-2
IbiSudan
Index caseKhartoum
Arrival date13 March 2020
(4 years, 9 months, 2 weeks and 1 day)
Active cases4,179 (as of 14 July)

Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní orílẹ̀-èdè Sudan jẹ́ ọ̀kan lára Ìbúrẹ́kẹ́ àjakálẹ̀ àrùn Kòrónà tí a tún mọ̀ sí Kofid-19 tí ó bẹ́ sílẹ̀ ní gbogbo àgbáyé. Ohun tí ó ń ṣokùnfà àìsàn yí ni àrùn ọ̀fun, àyà, ati imú tí wọ́n ń pè ní [1]

Bí àrùn Kòrónà ṣe wọ orílẹ̀-èdè Sudan

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àjọ ìṣọ̀kan tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn Kòrónà tí a tún ń pè ní Kofid-19 ní orílẹ̀-m àgbáyé ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kínní ní ọdún 2020. Tí wọ́n sì fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé àrùn yí bẹ̀rẹ̀ ní ìlú kan tí wọ́n ń pw ní ìgboro Wuhan, ní ẹkùn Hubei ní orílẹ̀-èdè China. Wón tún fìdí rẹ̀ múlẹ̀ siwájú si wípé bí àrùn yí bá ti mú ènìyàn, oun ni ó ń fa ìfúnpinpin ní ní inú káà ọ̀fun ati àyà, tí ó sì ma ń fa kàtá tàbí kí []ènìyàn]] ó ma wú ikọ́ tàbí sín léra léra. [2][3] Iye ìjàmbá tí àrùn Kòrónà ti fà lágbáyé kéré sí iye ìjàmbá tí àìsàn àrùn ọ̀fun SARS ti fà láti ọdún 2003.[4][5] Àmọ́ iye àwọn ènìyàn tí wọ́n tó àrùn Kòrónà látàrí ríràn tí ó.ń ràn kálẹ̀ ti.pọ̀ ju ti SARS lọ. [6][4]

Àwọn àsìkò kọ̀ọ̀kan tí ó ṣẹlẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Oṣù Kẹ́ta ọdún 2020

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọjọ́ Kẹtàlá oṣù kẹ́tà, orílẹ̀-èdè Sudan ní akọsílẹ̀ Kòrónà akọ́kọ́ ní agbègbè Khartoum. Aláìsàn náà ti kọ́kọ́ndé orílẹ̀-èdè United Arab Emirates ṣáájú kí ó ṣe aláìsí ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kẹ́ta ọdún 2020.[7] Lẹ́yìn ìṣẹ̀lẹ̀ yí, orílẹ̀-èdè Sudan fopin sí fífún àwọn èró láti ilé òkèrè ìwé ìrìnà ìkíni sí àwọn orílẹ̀-èdè tí àrùn náà nti pọ̀ jùlọ, tí ó fi mọ́ orílẹ̀-èdè Italy àti orílẹ̀-èdè Ijíbítì tí ó jẹ́ alámùúké tì wọn nítorí ìbérù àjakálẹ̀ àrùn Kòrónà. [8]

Oṣù Karùún ọdún 2020

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Nígbà tí ó di ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù Karùún, àwọn ìròyìn ikú ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn látàrí Ìbúrẹ́kẹ́ àjakálẹ̀ àrùn Kòrónà, dá ìbẹ̀rù-bojo sílẹ̀ ní orílẹ̀-èdè Sudan, bí ó tilẹ̀ jẹ́ wípé ìgbésẹ̀ ayẹ̀wò àrùn aṣekúpani náà mẹ́hẹ. [9]

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Federal Ministry Of Health". Federal Ministry Of Health. 3 April 2020. 
  2. Elsevier. "Novel Coronavirus Information Center". Elsevier Connect. Archived from the original on 30 January 2020. Retrieved 15 March 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  3. Reynolds, Matt (4 March 2020). "What is coronavirus and how close is it to becoming a pandemic?". Wired UK. ISSN 1357-0978. https://www.wired.co.uk/article/china-coronavirus. 
  4. 4.0 4.1 "Crunching the numbers for coronavirus". Imperial News. Archived from the original on 19 March 2020. Retrieved 15 March 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. "High consequence infectious diseases (HCID); Guidance and information about high consequence infectious diseases and their management in England". GOV.UK (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 3 March 2020. Retrieved 17 March 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  6. "World Federation Of Societies of Anaesthesiologists – Coronavirus". www.wfsahq.org. Archived from the original on 12 March 2020. Retrieved 15 March 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. "Sudan reports first coronavirus case". The East African. Agence France Presse. 13 March 2020. 
  8. "Sudan stops visas and flights for eight countries including Egypt over coronavirus: statement" (in en). Reuters. 12 March 2020. https://www.reuters.com/article/us-health-coronavirus-sudan-idUSKBN20Z36I. 
  9. "Surge in deaths in North Darfur raises fears of disastrous Covid-19 outbreak". the Guardian (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2020-05-29. Retrieved 2020-05-29. 

Àdàkọ:COVID-19 pandemic

Àdàkọ:COVID-19-stub Àdàkọ:Sudan-stub