Jump to content

Àjàkálẹ̀ Àrùn COVID-19 ní orílẹ̀-èdè Mozambique

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àjàkálẹ̀ Àrùn COVID-19 ní orílẹ̀-èdè Mozambique
Cases per Province[1]
    Provinces with 30 to 299 cases reported by the National Institute of Health
    Provinces with 3 to 29 cases reported by the National Institute of Health
    Provinces with 1 or 2 cases reported by the National Institute of Health
ÀrùnCOVID-19
Irú kòkòrò èrànSARS-CoV-2
IbiMozambique
Ìjásílẹ̀ àkọ́kọ́Wuhan, China
Arrival date22 March 2020
(4 years, 8 months and 6 days)
Gbogbo iye àwọn ẹ̀sùn1,720 (as of 28 July)[2]
Active cases1,107 (as of 28 July)
Iye àwọn tí ara wọn ti yá602 (as of 28 July)
Iye àwọn aláìsí
11 (as of 28 July)

The Àjàkálẹ̀ àrùn COVID-19 ní tàn kálẹ̀ dé orílẹ̀-èdè Mozambique ní àárín oṣù kẹ́ta ọdún 2020.[3]

Bí ó ṣe bẹ̀rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kíní ọdún 2020, Àjọ ìṣọ̀kan tí ó ń rí sí ìlera ní àgbáyé fìdí àrùn Kòrónà tí a tún ń pè ní Kofid-19 ní orílẹ̀-m àgbáyé ní ọjọ́ Kejìlá oṣù Kínní ní ọdún 2020. Tí wọ́n sì fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé àrùn yí bẹ̀rẹ̀ ní ìlú kan tí wọ́n ń pè ní Wuhan, ní ẹkùn Hubei ní orílẹ̀-èdè China. Àmọ́ ó tó ọjọ́ Kẹtalélọ́gbọ̀n oṣù Kejìlá ọdún 2019 kí wọ́n tó fi tó àjọ ìṣòkan àgbáyé létí .[4][5]

Wọ́n tún fìdí rẹ̀ múlẹ̀ siwájú si wípé bí àrùn yí bá ti mú ènìyàn, oun ni ó ń fa ìfúnpinpin ní ní inú káà ọ̀fun ati àyà, tí ó sì ma ń fa kàtá tàbí kí ènìyàn ó ma wú ikọ́ tàbí sín léra léra. Iye ìjàmbá tí àrùn Kòrónà ti fà lágbáyé kéré sí iye ìjàmbá tí àìsàn àrùn ọ̀fun SARS ti fà láti ọdún 2003. Àmọ́ iye àwọn ènìyàn tí wọ́n tó àrùn Kòrónà látàrí ríràn tí ó ń ràn kálẹ̀ ti.pọ̀ ju ti SARS lọ, bí ó ti lẹ̀ jẹ́ wípé ìtànkálé àrùn COVID-19 ń gbópọn si lójojúmọ́ tí ó sì ti ṣekú pa ọ̀pọ̀lọpò ènìyàn lágbáyé.[6][7][8][6]</ref>

Àwọn àsìkò kọ̀ọ̀kan tí ó ń ṣẹlẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Oṣù Kẹ́ta ọdún 2020

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Orílẹ̀-èdè Mozambique ní akọsílẹ̀ akọ́kọ́ ní ọjọ́ kejìlélógún oṣù kẹ́ta ọdún 2020. Wọ́n rí àrùn yí lára ẹnìkan tí ó jẹ́ ẹni ọdún márùdínlọ́gọ́sàán tí ó ń darí bọ̀ láti ilẹ̀ United Kingdom.[9] nínú oṣù yí, àwọn ènìyàn mẹ́jọ ni ó tún rí tí ayẹ̀wò sì fìdí rẹ̀ múlẹ̀ wípé wọ́n ní àrùn aṣekú pani Kòrónà.[10]

Oṣù Kẹrin ọdún 2020

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹrin ọdún 2020, wọ́n tún ṣàwárí àwọn ènìyàn méje mìíràn tí ó ti fara kó jogbo àrùn COVID-9 ní orílẹ̀-èdè náà tí ó mú kí gbogbo àwọn tí eọ́n ti ní àrùn yí ti jẹ́ mẹ́tàdínlógún, ní èyí tí àwọn ènìyàn mẹ́sàán kó àrùn náà ran ara wọn.[11] Kí oṣù kẹrin tó parí, wọ́n ti rí tó àwọn ènìyàn tí ó tó mẹ́rìndínlọ́gọ́jọ tí wọ́n ní arùn Kòrónà. Àwọn méjìlá nínú wọn ni wọ́n rí ìtọ́jú gbà tí ó sì ku àwon mèrìnlélọ́gọ́ta ènìyàn tí àìsàn yí ṣì wà lára wọn. [12]

Oṣù karùún ọdún 2020

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní ọjọ́ karùndínlọ́gbòn àti ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù Karùún, orílẹ̀-èdè Mozambique pàdánù ènìyàn méjì àkọ́kọ́ sí ọwọ́ àrùn COVID-9.[13] Ní àárín oṣù yí, orílẹ̀-èdè Mozambique ti ní akọsílẹ̀ iye ènìyàn tí ó tó ọgọ́rùún kan ó lé méjìdínlọ́gọ́rin, èyí mú kí iye àwọn tí wọ́n ti ní àrùn náà lápapọ̀ láti Ìbẹ̀rẹ̀ ó jẹ́ ọgọ́rùún méjì ó lé mèrìléláàdọ́ta. Àwọn ènìyàn 91 ni wọ́n rí ìtọ́jú tí ara wọn sì yá tí wọ́n pada sí ilé wọn. Ẹnikẹ́ni kò kú nínú oṣù yí yàtọ̀ sí àwọn tí wọ́n ti kọ́kọ́ kú tẹ̀lẹ̀. Tí àwọn ọgọ́rùún kan ó lé mọ́kànlélélọ́gọ́ta ènìyàn tí àìsàn yí ṣì wà lára wọn. <[14]

Oṣù Kẹfà ọdún 2020

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìyalẹ́nu ni ó jẹ́ bí iye àwọn tí àrùn náà tún kọlù jẹ́ ìlọ́po ènìyàn tí ó ti mú tẹ́lẹ̀ nínú oṣù Karùún pẹ̀lú àwọn ènìyàn mẹ́rìlélógójì ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù Karùún nìkan. Nígbà tí ó di ọjọ́ kẹrìnlá, wọ́n pàdánù ẹnìka tí ó jẹ́ ẹni ọdún mẹ́rìnléláàdọ́jọ tí ó jẹ́ ọmọ agbègbè Nampula Province. After ending May with 254 confirmed cases, the number of confirmed cases had doubled by 13 June, with a further 44 cases confirmed on that day alone.[15][16] Àwọn mẹ́fà ni ó papò dà nínú oṣù Kẹfà nígbà tí àwọn ọgọ́rùún méjì ó lé mẹ́jìlélọ́gbọ̀n rí ìwòsàn gbà. Iye àwon ènìyàn tí àìsàn yí ṣì wà lára wọn jẹ́ ọgọ́rùún mẹ́fà àti méjìléláàdọ́ta.[17]

Ààtò àwọn dátà

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Confirmed cases
Confirmed new cases

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "COVID-19 - Fica Atento". Retrieved 2020-06-08. 
  2. "Início". COVID 19 - Fica Atento (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-07-28. 
  3. "World Health Organization: A case of COVID-19 confirmed in Mozambique". WHO | Regional Office for Africa (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2020-05-26. 
  4. Elsevier. "Novel Coronavirus Information Center". Elsevier Connect. Archived from the original on 30 January 2020. Retrieved 15 March 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  5. Reynolds, Matt (4 March 2020). "What is coronavirus and how close is it to becoming a pandemic?". Wired UK. ISSN 1357-0978. https://www.wired.co.uk/article/china-coronavirus. 
  6. 6.0 6.1 "Crunching the numbers for coronavirus". Imperial News. Archived from the original on 19 March 2020. Retrieved 15 March 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  7. "High consequence infectious diseases (HCID); Guidance and information about high consequence infectious diseases and their management in England". GOV.UK (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 3 March 2020. Retrieved 17 March 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. "World Federation Of Societies of Anaesthesiologists – Coronavirus". www.wfsahq.org. Archived from the original on 12 March 2020. Retrieved 15 March 2020.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  9. "Mozambique confirms first coronavirus case". National Post. 22 March 2020. Retrieved 22 March 2020. 
  10. "Coronavirus disease (COVID-19) situation report 72" (PDF). World Health Organization. 1 April 2020. p. 8. Retrieved 18 July 2020. 
  11. "World Health Organization: 17 cases of COVID-19 confirmed in Mozambique" (in en). WHO | Regional Office for Africa. https://www.afro.who.int/news/world-health-organization-17-cases-covid-19-confirmed-mozambique. Retrieved 9 April 2020. 
  12. "Coronavirus disease (COVID-19) situation report 102" (PDF). World Health Organization. 1 May 2020. p. 6. Retrieved 18 July 2020. 
  13. "Moçambique regista segundo óbito e eleva total para 233" (in pt). RTP. 28 May 2020. https://www.rtp.pt/noticias/mundo/mocambique-regista-segundo-obito-e-eleva-total-para-233_n1232612. Retrieved 18 July 2020. 
  14. "Coronavirus disease (COVID-19) situation report 133" (PDF). World Health Organization. 1 June 2020. p. 7. Retrieved 18 July 2020. 
  15. MENAFN. "Mozambique confirms 44 more coronavirus infections". menafn.com. Retrieved 2020-06-14. 
  16. "Mozambique registers one more COVID-19 death - China.org.cn". www.china.org.cn. Retrieved 2020-06-14. 
  17. "Coronavirus disease (COVID-19) situation report 163" (PDF). World Health Organization. 1 July 2020. p. 7. Retrieved 18 July 2020. 

Àdàkọ:COVID-19 pandemic


Àdàkọ:COVID-19-stub Àdàkọ:Mozambique-stub