Jump to content

Àtòjọ àwọn ẹ̀yà ní Nàìjíríà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àwọn ẹ̀yà ilẹ̀ Áfríkà lé ní ẹgbẹ̀rún, oríṣiríṣi ibi sì ni ó ní èdè àti àṣà wọn, bí ó tilè jẹ́ wípé kò sí àkọsílẹ̀ tó dájú nípa iye àwọn ènìyàn tí ó ń sọ àwọn oríṣiríṣi èdè ní Áfríkà nítorí pé kò sí àwọn ohun èlò tí wọ́n nílò láti ka àwọn ènìyàn ní àwọn ibi kan ní Áfríkà àti nítorí pé iye àwọn olùgbé Áfríkà ńapọ̀ si lójojúmọ́.

Àtòjọ àwọn ẹ̀yà Áfríkà

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Èyí ni àtòjọ àwọn ẹ̀yà ní Áfríkà(àwọn tí ó lé ní mílíọ̀nù mẹ́wàá tàbí jù bẹ́ẹ̀ lọ.):

Àwọn ẹ̀yà Ibi tí wọ́n wà Àwọn orílẹ̀ èdè tí wọ́n wà Ìdílé edè tí wọ́n ń sọ Pop. (millions)
(year)
Akan Ìwọ oòrùn Áfríkà Ghana, Ivory Coast Niger–Congo, Kwa 20Àdàkọ:Year needed
Amhara Ìho Áfríkà Ethiopia Afro-Asiatic, Semitic 22 (2007)
Arabs Àríwá Áfríkà Algeria, Libya, Morocco, Tunisia, Mauritania Afro-Asiatic, Semitic 100+ (2013)[1]
Berbers Àríwá Áfríkà Algeria, Libya, Morocco, Mauritania Afro-Asiatic, Berber 36 (2016)[2][3][4]
Chewa Àárín Áfríkà Malawi, Zambia Niger–Congo, Bantu 12 (2007)
Fulani Ìwọ oòrùn Áfríkà Mauritania, Gambia, Guinea-Bissau, Guinea, Nigeria, Cameroon, Senegal, Mali, Burkina Faso, Benin, Niger, Chad, Sudan, Central African Republic, Ghana, Togo, Sierra Leone Niger–Congo, Senegambian 20Àdàkọ:Year needed
Hausa Ìwọ oòrùn Áfríkà Nigeria, Niger, Benin, Ghana, Cameroon, Chad, Sudan Afro-Asiatic, Chadic 78 (2019)[5]
Hutu Àárín Áfríkà Rwanda, Burundi, Democratic Republic of the Congo Niger–Congo, Bantu 15Àdàkọ:Year needed
Igbo Ìwọ oòrùn Áfríkà Nigeria, Equatorial Guinea, Cameroon, Gabon Niger–Congo, Volta–Niger 34 (2017)
Kanuri Àárín Áfríkà Nigeria,[6] Niger,[7] Chad,[8] Cameroon[9] Nilo-Saharan, Saharan 10
Kongo Àárín Áfríkà Democratic Republic of the Congo, Angola, Republic of the Congo Niger–Congo, Bantu 10Àdàkọ:Year needed
Luba Àárín Áfríkà Democratic Republic of the Congo Niger–Congo, Bantu 15Àdàkọ:Year needed
Mongo Àárín Áfríkà Democratic Republic of the Congo Niger–Congo, Bantu 15Àdàkọ:Year needed
Mossi Ìwọ oòrùn Áfríkà Burkina Faso, Ivory Coast, Niger, Ghana, Mali, Togo Niger–Congo, Bantu 11Àdàkọ:Year needed
Nilotes Nile Valley, Ìlà-Oòrùn Áfríkà, àárín Afrika South Sudan, Sudan, Chad, Central African Republic, Kenya, Uganda, Tanzania, Ethiopia Nilo-Saharan, Nilotic 22 (2007)
Oromo Ìho Áfríkà Ethiopia, Kenya Afro-Asiatic, Cushitic 42 (2022)
Shona Ilà-oòrùn Áfríkà Zimbabwe and Mozambique Niger–Congo, Bantoid 15 (2000)
Somali Ìho Áfríkà Somalia, Djibouti, Ethiopia, Kenya Afro-Asiatic, Cushitic 20 (2009)
Yoruba Ìwọ̀ oòrùn Áfríkà Nigeria, Benin, Togo, Ghana, Ivory Coast, Sierra Leone Niger–Congo, Volta–Niger 40Àdàkọ:Year needed
Zulu Gúúsù Áfríkà South Africa Niger–Congo, Bantu 12 (2016)

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. Group, The Diagram (2013-11-26) (in en). Encyclopedia of African Peoples. Routledge. ISBN 978-1-135-96341-5. https://books.google.com/books?id=xJQuAgAAQBAJ&q=Numbering+over+100+million%2C+Arabs+are+the+most+numerous+ethnic+group+in+North+Africa.. 
  2. Steven L. Danver (10 March 2015). Native Peoples of the World: An Encyclopedia of Groups, Cultures and Contemporary Issues. Routledge. p. 23. ISBN 978-1-317-46400-6. https://books.google.com/books?id=vf4TBwAAQBAJ&pg=PA23. "The Berber population numbers approximately 36 million people." 
  3. "Berber people". Retrieved 2016-08-17. 
  4. "North Africa's Berbers get boost from Arab Spring". Fox News. 5 May 2012. Retrieved 8 December 2013. 
  5. Ososanya, Tunde (2020-06-15). "Hausa tribe is Africa's largest ethnic group with 78 million people". Legit.ng - Nigeria news. (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2022-02-17. 
  6. "The World Factbook: Nigeria". World Factbook. Central Intelligence Agency. Retrieved 2013-12-31. 
  7. "The World Factbook: Niger". World Factbook. Central Intelligence Agency. Retrieved 2013-12-31. 
  8. "The World Factbook: Chad". World Factbook. Central Intelligence Agency. Retrieved 2013-12-31. 
  9. Peter Austin, One Thousand Languages (2008), p. 75, https://books.google.com/books?isbn=0520255607:"Kanuri is a major Saharan language spoken in the Lake Chad Basin in the Borno area of northeastern Nigeria, as well as in Niger, Cameroon, and Chad (where the variety is known as Kanembul[)]."