Jump to content

Óscar Arias

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Óscar Arias Sánchez)
Óscar Arias
President of Costa Rica
In office
8 Ọṣù Kàrún 2006 – 8 Ọṣù Kàrún 2010
AsíwájúAbel Pacheco
Arọ́pòLaura Chinchilla
In office
8 Ọṣù Kàrún 1986 – 8 Ọṣù Kàrún 1990
AsíwájúLuis Alberto Monge
Arọ́pòRafael Ángel Calderón Fournier
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí13 Oṣù Kẹ̀sán 1940 (1940-09-13) (ọmọ ọdún 84)
Heredia, Costa Rica
Ẹgbẹ́ olóṣèlúNational Liberation Party
Alma materBoston University
University of Costa Rica
London School of Economics
University of Essex

Óscar Rafael de Jesús Arias Sánchez (ojoibi 13 September 1940) je oloselu ara orile-ede Kosta Rika to di Aare ile Kosta Rika lati odun 2006 de 2010. Teletele o tun je Aare lati 1986 de 1990 o si gba Ebun Nobel ni 1987 fun iyanju re lati mu opin ba awon ogun abele ti won nlowo nigbana ni opo awon orile-ede Aarin Amerika.