Jump to content

2022

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àdàkọ:Ọdún 2022, tí ó bẹ̀rẹ̀ pẹ̀lú ọjọ́ Sátidé nínú kalẹ́ndà Gregori, ọdún 2022 ni ó ṣáájú ọdun 2023, òun sì ni ó ló tẹ̀lé ọdún 2021.

Assassination of Shinzo Abe2022 Sri Lankan protests2022 monkeypox outbreak2022 Russian invasion of UkraineDeath and state funeral of Elizabeth II2022 Kazakh unrest2022 Winter OlympicsJune 2022 Afghanistan earthquake
láti òsì lọ sí ilè(ní yíyí owó aago): Orita Yamato-Saidaiji ní wákàtí dí ẹ̀ lẹ́yìn ìgbà tí wón ṣe ikú pa Shinzo Abe; Ìwóde ifehonuhan lòdì sí ìjọba ní orílè-èdè Sri Lanka ni iwájú ilé Ààrẹ; Ní ọjọ́ kẹfà oṣù kàrún, ìbújáde àrùn Monkey pox béèrè ní United Kingdom; wọ́n gbé Èlísábẹ́tì kejì sí Westminster Hall fún àwọn ènìyàn láti fi ọ̀wọ̀ fun; ọmọ kan dúró sí àárín ilé tí ó ti dàwó ni orílẹ̀-èdè Afghanistan nígbà Ìmìtìtì ilẹ̀ tí ó ṣẹlẹ̀ ní Afghanistan ni osù kẹfà ọdún 2022; foto ibi kan ni ibi ayẹyẹ ìbẹ̀rẹ̀ 2022 Winter OlympicsBeijing, China; Àwọn oluwode ni orita Aktobe nìgbà àìsinmi 2022 ti Kazakh; BMP-3(Ọkọ̀ ijagun) Rosia kan ni ẹ̀gbẹ́ Mariupol tí ó bàjẹ́ nígbà ìkógun Rosia wo Ukraine, odun 2022.

Àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ tó sẹ̀ ní ọdún 2022

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

•Ọjọ́ ìkejì oṣù kíní (January 2): Abdalla Hamdok kọ̀wé iṣẹ́ sílẹ̀ gẹ́gẹ́ bí mínísítà àgbà fún orílẹ̀-èdè Sudan lẹ́yìn ìwọ́de ńlá.[1]

•Ní ọjó keje oṣù Kínní (January 7): Iye àwọn tí ó ti ní àrùn covid-19 kojá ọ̀ọ́dúnrúnr mílíọ́nù.[2]

•Ní ọjọ́ kẹwá oṣù Kínní (January 10): Fún ìgbà àkókò, àwọn Dókítá rí Ọkàn Ẹlẹ́dẹ̀ gbé sínú ènìyàn, ó sì yè. Eléyìí ṣẹlẹ̀ ní Baltimore, Maryland ni orílè-èdè Amerika.[3]

•Ní ọjọ́ kẹtalélógún oṣù kínní (January 23): wọ́n fipá ggbàjọba lọ́wọ́ ààrẹ orílẹ̀-èdè Bùrkínà Fasò Roch Kaboré, wọ́n sọ wípé ìdí tí àwọn fi gba ìjọba náà ni bí ààrẹ náà ṣe kùnà láti panọ́ làásìgbò kọ̀ọ̀kan tí àwọn igun ẹlẹ́sìn Mùsùlùmí kan ń dá sílẹ̀ wà lára ìdí tí wọ́n fi yọ ọ́ kúrò nìpò.[3]

•Ní ọjọ́ kejìdínlọ́gbọ̀n oṣù kíní (Jan 28): Iye abẹ́rẹ́ àjẹsára àrùn covid-19 tí àwọn ènìyàn ti lò lágbàáyé ti lé ní bílíọ́nù mẹ́wá .[2]

•Ní ọjọ́ kọkandínlọ́gbọ̀n oṣù kínní (Jan 29): Wọ́n dìbò yan ààrẹ orílẹ̀-èdèItaly, Sergio Mattarela fún sáà kejì ìjọba. [4]

•Ní ọjọ́ kẹrìndínlọ́gbọ̀n oṣù kejì (26 Feb): Orílẹ̀-èdè Rọ́síà bẹ̀rẹ̀ sí ń kógun ja orílẹ̀-èdè Ukraine.[3]

•Ní ọjọ́ keje oṣù kẹta (March 7): Iye àwọn tí o ti kú nítorí aàrùn Covid-19 lé ni mílíọ́nù mẹ́fà (6 million). [5]

•Ní ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹrin (April 13): Iye àwon ti o ti ní aàrùn covid-19 lé ni Ẹẹdẹgbẹta millionu.[6]

•Ní ọjọ́ l3rìndínlógún oṣù kẹrin(April 24): Apá kejì ìdìbò orílè-èdè Faransé bẹ̀rẹ̀, ààrẹ Emmanuel Macron sì jáwé olúborí láti ṣe sáà kejì tí olùdíje kejì, Marine Le Pen sì fìdí èémí .[7]

•Ní ọjọ́ kẹfà oṣù karùn ún (6 May): Àjakálẹ̀ aàrùn Monkey Pox gbòde: Aàrùn Monkey Pox nẹ̀rẹ̀ sí ń tàn kálẹ̀, ijọ́ tí wọ́n sì rí ẹni àkọ́kọ́ tí ó ní àrùn yí ní ìlú London, orílè-èdè United Kingdom.[8]

•Ní ọjọ́ kẹsàn án oṣù karùn ún (9 May): Mínísítà àgbà orílẹ̀-èdè Sri Lanka, Mahinda Rajapaksa kọ̀wé fiṣẹ́ sílẹ̀ nítorí ìwọ́de lòdì sí àkóso rẹ̀ gẹ́gẹ́ bí mínísítà Ranil Wickremesinghe ṣe bọ́ sí ipò náà lẹ́yìn ọjọ́ kẹta tí Mahinda kọ̀wé fiṣẹ́ sílẹ̀.[9]

• Ojó keedogun osù karun(May 15): A yan Ààre orílè-èdè Somalia télèrí, Hassan Sheikh Mohamud fún sáà kejì ìjoba rè, ààre Mohamed Abdullahi Mohamed sì fìdíremi.[11]

• Ojo karun ti osù kefa(June 5): Okere jù eyan adota kú sí didun adá oloro to selè ní ìlú Owo, ipinle Ondo, Nàìjirià.[12]

• Ojo kejo osù keje(July 8): Agbenipa kan yin Minisita àgbà orílè-èdè Japan teleri Shinzo Abe pa nígbà ti óun soro si àwon èro ní ìlú Nara.[13]

• Ijó kokanlelogun ti osù Keje(July 21): Àwon asofin orílè-èdè Sri Lanki yan Minisita Àgbà Ranil Wickremesinghe gegebi Ààre orílè-èdè náà léyìn ìgbà tí ààre orílè-èdè náà tele, Gotabaya Rajapaksa kòwé fise sílè tori iwode ifehonuhan ti àwon ará ìlú un se to ri bi nkan se le koko.[14][15]

• Ijo kerin ti osù Kejo(August 4): Minisita àgbà fún orílè-èdè Peru, eni tí a un pè ní Anibal Torres kòwé fise sílè léyìn òpòlopò iwádí nípa iwa odaran tí wón se nípa Ààre orílè-èdè Peru, eni tí a un pè Pedro Castillo.[16]

• Ijo kesan ti osù Kejo(August 9):

° Idibo gbogboogbo ti orílè-èdè Papa New Guinea: Àwon asofin Papa New Guinea yan James Marape gégé bi asofin agba orílè-èdè Papa New Guinea.[17]

°Idibo gbogboogbo ti orílè-èdè Kenya: A yan William Ruto gégé bi Ààre orílè-èdè Kenya, oun ni ààre karun orílè-èdè Kenya. O fi ídí olùtakò rè, Ralia Odinga remi.[18]

• Ijó kerinla osù Kejo(August 12): Afunrasi odaran kan, tí àún pe ní Hadi Matar gún Salmon Rushdie lobe ní òpòlopò ibi, Salmon Rushdie jé olùkòwé omo orílè-èdè Amerika mó United Kingdom tí a bi ní Orílè-èdè India, wón gbé afunrasi náà, ogbeni Hadi Matar lo ilé-ejó ní ojó kejì.[12]

• Ojó ketadinlogbon ti osù kejo si ojó kokanla ti osù kesan(August 27-Sept 11): Won gbá copu Asia odun 2022 ní orílè-èdè United Arab Emirates, orílè-èdè Sri Lanka ló jáwé olúborí.[19]

• Ojó karun ti osù kesan(Sept 6): A yan Liz Truss gégé bi minisita àgbà fún orílè-èdè United Kingdom.[20]

• Ojo kejo ti osu Kesan(Sept 8) – Charles keta di oba United Kingdom àti orílè-èdè merinla mirán léyìn ìgbà tí Ayaba Elisabeti keji kú.[3]

• Ojo Kerinla si kerindinlogun osu kesan(September 14–16) – Ija wáyé Kyrgyzstan ati Tajikistan lori oro àlà, òpòlopò àwon omo ogun Kyrgyz ati Tajik ni oba isele náà lo.[16]

 • Ọjọ́ kerindinlogun oṣù Kesan(Sept 16) – Ìwóde ifehonuhan bẹ̀rẹ̀ ni orílẹ̀ èdè Iran lórí ikú ní akete àwọn Ọlọpa tó ún dojú kọ "ìwà kọòtọ̀".[21]
 • Ọjọ́ kọkàndínlógún oṣù kesan(Sept 19) – Ìsìnkú Èlísábẹ́tì kejì wáyé ní Westminster Abbey, London. Wọ́n sì gbé posi rẹ lọ sí Windor Castle lọ sin pẹ̀lú ọkọ àti òbí rẹ ni King George VI Memorial Chapel.[22]
 • Ọjọ́ kedogbon ti oṣù Kẹ̀sán(Sept 30): _Àwọn ológun Burkina Faso fi idite gba ìjọba, Ọ̀gá ológun Ibrahim Traore ni ó darí àwọn ológun yí. [23]
 • Ọjọ́ kẹfà oṣù Kẹ̀wá(Oct 6): Ọlọpa tẹ́lẹ̀ ri kan ṣekú pa àwọn ènìyàn merinlelogoji, èyí tí àwọn ọmọ mẹ́tàlélógún wà nínú wọn, ní ilé ìwé nosiri Na Klang district, orílè-èdè Thailand.[24]
 • Ọjọ́ karundinlogbon oṣù kewa(Oct 25) – Rishi Sunak di mínísítà àgbá tí orílẹ̀ èdè isokan gẹ̀ẹ́sì(United Kingdom) lẹ́yìn tí Liz Truss kọ̀wé fí ipò náà sílè.[25]
 • Ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kewa(Oct 28) - Elon Musk di alákóso ìtàkùn ayélujára Twitter lẹ́yìn tí ó rà á ní bilionu merinlelogoji dola.[26]
 • Ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kọkànlá(Nov 18) : Iye àwọn ènìyàn lagbaye pé bilionu mẹ́jọ [27]

Ìsèlè 2022 ní Nàìjíríà

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
 • Ijó kerin sí ijó kefa osù kinni(4-6 Jan): Àwon agbebon pa ènìyàn tó lé ni igba(200) ní ìpínlè Zamfara.[4]
 • Ijó kerinla sí ijó karunla osù kinni(14-15Jan): Àwon agbebon pa ènìyàn to lé ní Aadota(gegebi àwon iroyin kan se fi léde) ní ipínlè Kebbi, àwon olopa padà fi lede pé àwon ènìyàn mérìndilógún ni won pa, pèlú òpòlopò ti won ji gbé.[28][29]
 • Ojó karun ti osù kejì(5 Feb): Idibo àwon ìjoba ìbílè Kebbi waye.[30]
 • Ojo kewa ti osù kejì(10 Feb)

° Àwon agbebon pa ènìyàn marun ní ìlú Rogoji, Bakura ní ìpínlè Zamfara.[31] Iroyin gbe pé ìyá kan ti àwon vigilante pa omo refers níbí ní kí awon agbebon náà se nkan ti wón se.[32]

° Àwon olè agbebon kan se ìkolù sí moto tó ún gbodo kan, won pa ènìyàn mefa, olopa meji wà lara awon ti wón pa.[33]

 • Ojó kejìlá ti osù Kejì(12 Feb)- Idibo àwon ìjoba ìbílè Abuja ti odún 2022 wáyé.[34]
 • Ojó ketalelogun ti osù kejì(23 Feb) - Idibo ìjoba ìbílè ti ìpinlè Enugu fún odun 2022 wáyé.[35]
 • Ojó kejo ti osù keta(March 8): Àwon agbebon pa òpòlopò eniyan ní ìpínlè Kebbi.[36][37]
 • Ojó kéjìlá ti osù keta(March 12): Idibo awon ìjoba ìbílè Imo fún odun 2022.[38]

* Ojó kejidinlogbon ti osù keta(March 28): Àwon agbebon se ìkolù si oko oju irin kan ti óún lo láti Abuja sí Kaduna.[39]

 • Ojó kesan ti osù kerin(April 9): Idibo awon ìjoba ìbílè Adamawa wáyé.[40]
 • Ojó kèwá ti osù kerin(April 10): Àwon agbebon pa òpòlopò ní ìpinlè Plateau, won si tun ji òpòlopò gbé.[41]
 • Ojó kokanla ti osù kerin(April 11): Idibo àwon ijoba ìbílè ti Kastina wáyé.[42]
 • Ojó kéjìlá ti osù karun(12 May): Àwon kan sekú pa Deborah Yakubu tori wipe won ni o soro òdì sí Woli Mohammadu, wón soko lu pa, won sì tun dana sun.[43]
 • Ojó karun ti osù kefa(June 5): Àwon agbebon se ìkolù sí ijo kan ní ìlú Owo, ìpínlè Ondo, wón sì pa òpòlopò olùjósìn.[1]
 • Ojó kejidinlogun ti osù kefa(June 18): Idiboyan Gomina titun wáyé ni ìpinlè Ekiti.[45]
 • Ojó karundinlogbon osù keje(July 25): Tobi Amusan jáwé olubori ninú idije 100m hurdle. O gba àmì-èye golu.[47]
 • Ọjọ́ kẹjọ oṣù kewa(Oct 8): Ọ̀kẹ́rẹ́ jù, ènìyàn márùn-ún lé ní àádọ́rin pàdánù ẹ̀mí wọn nígbà tí ọ̀kọ̀ ojú omi kan yí sọ́dọ̀ ni ìpínlè Anambra.[48]
 • Ọjọ́ karundinlogbon oṣù kọkànlá(25 November) – gbajugbaja olórin èmi Sammie Okposo, ẹni tí ó jé ọmọ ọdún ọkàn lé li adota(51), fi ayé sílè. [49]
 • Ojó keje oṣù Kejìlá(7 Dec): Banki àpapò ti Nàìjíríà ti fi gbedeke owó tí ènìyàn lè gbà ní ọ̀sẹ̀ kan sí ọgọrun ẹgbẹrun Naira(100,000) láti dojú ìjà kọ ṣíṣe àwọn ayida owó àti gbígbé owó fún àwọn gbemogbemo.

Àwon ènìyàn tó papòdà ni 2022

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
 • Ojo kokanla osù kinni(11 Jan): Olori orílè-èdè Nàìjirià télèrí, Ernest Shonekan papòdà.[50]
 • Ojó kejilelogun ti osù kerin(22 April): Alafin Oyo, Oba Lamidi Adeyemi III fayé sílè.[51]
 • Ọjọ́ kẹjọ oṣù kẹsàn(Sept 8): Èlísábẹ́tì II fayẹ́ sílè.[52]

Ìdíje ife-ẹ̀yẹ agbáyé ọdún 2022

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
 • Ogúnjọ́ oṣù kọkànlá ọdún 2022 ni ìdíje bọ́ọ̀lù àláfẹ̀sẹ̀gbá ti gbogbo àgbáyé wáyé orílẹ̀-èdè Qatar nígbà tí àwọn orílẹ̀-èdè méjìlélọ́gbọ̀n tí wọ́n pegedé jùlọ kópa nínú ìdíje ife ẹ̀yẹ agbáyé náà. Àwọn orílẹ̀-èdè tí wọ́n gbégbá orókè ni ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kejìá ọdún 2022.
 1. Orílẹ̀-èdè Argentina (Ipò kíní)
 2. Orílẹ̀-èdè Faransé ( Ipò kejì)
 3. Orílẹ̀-èdè Crotia (Ipò Kẹtà)
 4. Orílẹ̀-èdè Morocco (ipò kẹrin).

Àṣekágbá ìdíje ife ẹ̀yẹ agbáyé náà wáyé ní ọjọ́ kejìdínlógún oṣù Kejìlá ọdún 2022 yí kan náà. [53]

 1. 1.0 1.1 "Sudan: Abdalla Hamdok resigns as prime minister - 03.01.2022". DW.COM. Retrieved 2022-08-17. 
 2. 2.0 2.1 "Covid News: Known Global Coronavirus Cases Top 300 Million". The New York Times. 2022-01-06. Retrieved 2022-08-11. 
 3. 3.0 3.1 3.2 3.3 "Man gets genetically-modified pig heart in world-first transplant". BBC News. 2022-01-11. Retrieved 2022-08-13. 
 4. 4.0 4.1 "Italian President Sergio Mattarella re-elected, ending impasse - Politics News". Al Jazeera. 2022-01-29. Retrieved 2022-08-12. 
 5. McPhillips, Deidre (2022-03-07). "Global Covid-19 deaths surpass 6 million". CNN. Retrieved 2022-08-12. 
 6. Falconer, Rebecca (2022-04-13). "World surpasses half a billion confirmed COVID cases". Axios. Retrieved 2022-08-12. 
 7. DODMAN, Benjamin (2022-04-24). "Macron re-elected as French voters hold off Le Pen’s far right once more". France 24. Retrieved 2022-08-12. 
 8. "Monkeypox - United Kingdom of Great Britain and Northern Ireland". WHO. 1900-01-01. Retrieved 2022-08-13. 
 9. "Prime Minister Mahinda Rajapaksa resigns". NewsWire. 2022-05-09. Retrieved 2022-08-13. 
 10. "The son of late dictator Marcos has won the Philippines' presidential election". NPR.org. 2022-05-10. Retrieved 2022-08-13. 
 11. Africanews, Rédaction (2022-05-16). "Somalia re-elects former leader Hassan Sheikh Mohamud as president". Africanews. Retrieved 2022-08-13. 
 12. 12.0 12.1 "Over 50 feared dead in Nigeria church attack, officials say". AP NEWS. 2022-06-05. Retrieved 2022-08-13. 
 13. "(Updated with pictures) Japan ex-Prime Minister, Shinzo Abe, shot, feared dead". Vanguard News. 2022-07-08. Retrieved 2022-08-13. 
 14. Mao, Frances; Lanka, Sri (2022-07-20). BBC News https://www.bbc.com/news/world-asia-62202901. Retrieved 2022-08-16.  Missing or empty |title= (help)
 15. Ellis-Petersen, Hannah (2022-07-15). "Sri Lanka’s president Gotabaya Rajapaksa officially resigns". the Guardian. Retrieved 2022-08-16. 
 16. 16.0 16.1 "Peru PM resigns as investigations target President Castillo". Reuters. 2022-08-03. Retrieved 2022-08-16. 
 17. Togiba, Lyanne (2022-08-09). "James Marape returned as prime minister in Papua New Guinea after fraught election". the Guardian. Retrieved 2022-08-16. 
 18. Wasike, Maxwell (2022-08-16). "IEBC officially gazettes William Ruto as the President-Elect". KBC. Retrieved 2022-08-16. 
 19. "Format, venue of Asia Cup 2022 and 2023 confirmed". Cricketpakistan.com.pk. October 15, 2021. Retrieved February 7, 2022. 
 20. Hughes, David (September 5, 2022). "Truss wins Tory leadership race and faces daunting challenge as PM". The Independent. Retrieved September 8, 2022. 
 21. "The Protests in Iran Have Shaken the Islamic Republic to Its Core". Time. Retrieved 2022-09-25. 
 22. "Queen's funeral plans: What will happen on the day" (in en-GB). BBC News. 2022-09-16. https://www.bbc.com/news/uk-60617519. 
 23. Reuters (2022-09-30). "Burkina Faso army captain announces overthrow of military government" (in en). Reuters. https://www.reuters.com/world/africa/burkina-faso-army-captain-announces-overthrow-military-government-2022-09-30/. 
 24. "37 dead, mostly preschoolers, in Thai day care rampage". AP NEWS (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2022-10-06. Retrieved 2022-10-06. 
 25. "Sunak is next PM as Mordaunt drops out of leadership race". BBC News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 24 October 2022. Retrieved 24 October 2022. 
 26. "Elon Musk completes $44bn Twitter takeover". BBC News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 28 October 2022. Retrieved 28 October 2022. 
 27. "8 Billion: A World of Infinite Possibilities". 8 Billion. 2022-01-01. Retrieved 2022-12-29. 
 28. "Massacre in Nigeria Armed attackers attack the village: 50 dead". 2022-01-17. Retrieved 2022-08-17. 
 29. Akpan, Samuel (2022-01-17). "Many killed, 'dozens abducted' as gunmen raid Kebbi community". TheCable. Retrieved 2022-08-17. 
 30. "Kebbi: KESIEC declares APC winners of 21 LGA chairmanship, 225 councillorship seats". The Sun Nigeria. 2022-02-07. Retrieved 2022-08-17. 
 31. Babangida, Mohammed (2022-02-11). "Bandits storm Zamfara community for supporting security agents, kill five residents". Premium Times Nigeria. Retrieved 2022-08-18. 
 32. Abubakar, Abdullahi (February 11, 2022). "Woman Instigating Attacks Against Her Village In Northwest Nigeria To Avenge Son’s Death". HumAngle Media. Retrieved August 18, 2022. 
 33. "Ibadan bank robbery: Police tok how armed robbers wey reach 10 attack bullion van for Oyo State". BBC News Pidgin. February 10, 2022. Retrieved August 18, 2022. 
 34. "Area Council Elections Hold In FCT". Channels Television. February 12, 2022. Retrieved August 18, 2022. 
 35. "Enugu State declares February 23 work-free day for LG polls - Nigeria and World News". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News. February 20, 2022. Archived from the original on August 18, 2022. Retrieved August 18, 2022. 
 36. Muhammad, Garba (March 8, 2022). "Gunmen kill at least 62 vigilantes in Nigeria's Kebbi state". Reuters. Retrieved August 18, 2022. 
 37. France-Presse, Agence (March 9, 2022). "Gunmen in Northwest Nigeria Kill 19 Security Personnel". VOA. Retrieved August 18, 2022. 
 38. "Imo to conduct LG election in March 2022". TheCable. October 22, 2021. Retrieved August 18, 2022. 
 39. Nseyen, Nsikak (March 28, 2022). "Bandits bomb rail track, attack Abuja-Kaduna train". Daily Post Nigeria. Retrieved August 19, 2022. 
 40. Ochetenwu, Jim (2022-01-20). "Adamawa reschedules local govt election for April 9". Daily Post Nigeria. Retrieved 2022-08-19. 
 41. Carter, Sarah (April 13, 2022). "Nigeria leader vows "no mercy" for gunmen behind massacre that left more than 150 dead in country's north". CBS News. Retrieved August 19, 2022. 
 42. Ibrahim, Tijjani (2022-01-12). "Katsina fixes April 11 for LG polls". Daily Trust. Retrieved 2022-08-19. 
 43. Abdullahi, Maryam (2022-05-14). "Deborah Samuel, Sokoto student killed for alleged blasphemy, buried amid tears". TheCable. Retrieved 2022-08-20. 
 44. Princewill, Nimi (2022-05-28). "More than 30 people, including children, killed in stampede at church event in Nigeria". CNN. Retrieved 2022-08-20. 
 45. Online, Tribune (2022-01-05). "June 18 date stands for Ekiti governorship election ― INEC". Tribune Online. Retrieved 2022-08-20. 
 46. "Situating July Governorship Poll in Osun – THISDAYLIVE". THISDAYLIVE – Truth and Reason. 2022-06-28. Retrieved 2022-08-20. 
 47. Kazeem, Kolawole (2022-07-25). "Tobi Amusan wins 100m hurdles gold medal, sets new World record". OJB SPORT. Archived from the original on 2022-08-20. Retrieved 2022-08-20. 
 48. Khalid, Ishaq (2022-10-09). "Nigeria boat accident kills at least 76 fleeing floodwater in Anambra". BBC News. Retrieved 2022-12-30. 
 49. [Ella, Chioma (November 25, 2022). "Gospel Singer, Sammie Okposo reportedly dies at 51". Kemifilani. 
 50. Shibayan, Dyepkazah (2022-01-11). "Ernest Shonekan, former head of interim government ousted by Abacha, is dead". TheCable. Retrieved 2022-08-20. 
 51. Olaitan, Kemi (2022-04-23). "Breaking : Alaafin, Oba Lamidi Adeyemi, Dies at 83 – THISDAYLIVE". THISDAYLIVE – Truth and Reason. Retrieved 2022-08-20. 
 52. "Queen Elizabeth II's Death Certificate Shows Date, Time, and Cause". Harper's BAZAAR. September 29, 2022. Retrieved October 11, 2022. 
 53. "World Cup 2022: Dates, draw, schedule, kick-off times, final for Qatar tournament - Sky Sports". Sky Sports. 2022-11-21. Retrieved 2022-12-30.