Bọ́lájí Akínyẹmí
Ìrísí
Bolaji Akinyemi | |
---|---|
External Affairs Minister of Nigeria | |
In office 1985–1987 | |
Ààrẹ | Ibrahim Babangida |
Asíwájú | Ibrahim Gambari |
Arọ́pò | Ike Nwachukwu |
Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | January 4, 1942 Ilesa, Osun State |
Ọmọorílẹ̀-èdè | Nigerian |
(Àwọn) olólùfẹ́ | Rowena Akinyemi |
Àwọn ọmọ | Atinuke Akinyemi, Tosin Akinyemi, Tolu Akinyemi, Benjamin Akinyemi |
Profession | Professor of political science |
Website | www.profbolajiakinyemi.com |
Akínwándé Bọ́lájí Akínyẹmí tí wọ́n bí ní Ọjọ́ kẹrin oṣù kìíní ọdún 1942 (January 4, 1942) jẹ́ ọ̀jọ̀gbọ́n onímọ̀ sáyẹ́nsì, olóṣèlú ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà[1] to di Alakoso Oro Okere Naijiria lati 1985[2] titi de opin 1987.[3] Ohun ni Alaga National Think Tank.[4]
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Shaw, Timothy M.; Julius Omozuanvbo Ihonvbere. Illusions of Power: Nigeria in Transition. Africa World Press. p. 190. ISBN 0865436428.
- ↑ Oloyede, Dokun (2002-01-06). "Bolaji Akinyemi, the Seagull, at 60". Thisday online (Leaders & Company). Archived from the original on 2007-12-08. https://web.archive.org/web/20071208041700/http://www.thisdayonline.com/archive/2002/01/06/20020106tri01.html. Retrieved 2007-10-27.
- ↑ Shaw, 127.
- ↑ "National Think Tank pledges support for Omehia". The Tide Online (Rivers State Newspaper Corporation). 2007-10-10. http://www.thetidenews.com/article.aspx?qrDate=10/10/2007&qrTitle=National%20Think%20Tank%20pledges%20support%20for%20Omehia&qrColumn=FRONT%20PAGE. Retrieved 2007-10-27.