Dáníẹ́l O. Fágúnwà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Dáníẹ́l O. Fágúnwà

Daniel Olorunfẹmi Fagunwa tabi D.O. Fágúnwà (19039 December, 1963) je olukowe omo Naijiria ti a bi ni Oke-Igbo ni ipinle Ondo. O je Oguna gbongbo Onkowe itan aroso, bakanaa O tun je Oluko Ede Yoruba. Awon iwe re olokan-o-jokan lo gun opolopo awon onkowe ile Yoruba lonii ni kese ni eyi ti o mu ilosiwaju ba ede Yoruba lapapo.

Àwọn ìwé tó kọ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]


Itokas[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]