Dáníẹ́l O. Fágúnwà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti D.O. Fagunwa)
Jump to navigation Jump to search
Dáníẹ́l O. Fágúnwà

Daniel Olorunfẹmi Fágúnwà tabi D.O. Fágúnwà (19039 December, 1963) je akowe omo Naijiria ti won bi ni Okeigbo ni Ipinle Ondo. O je Oguna gbongbo Onkowe itan aroso, bakanaa o tun je oluko Ede Yoruba. Awon iwe re olokan-o-jokan lo gun opolopo awon onkowe ile Yoruba lonii ni kese ni eyi ti o mu ilosiwaju ba ede Yoruba lapapo.

Àwọn ìwé tó kọ[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]