Jump to content

Daniel Etim Effiong

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Daniel Etim Effiong
Ọjọ́ìbíDaniel Etim Effiong
Jaji, Kaduna State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Iléẹ̀kọ́ gígaFederal University of Technology, Minna, Niger State, Nigeria •
AFDA Film School, South Africa •
University of Johannesburg, South Africa
Iṣẹ́Chemical engineer, Actor, Scriptwriter, Film director
Gbajúmọ̀ fúnPlan B (2019)
Olólùfẹ́Toyosi Etim-Effiong (née Phillips)

Daniel Etim Effiong, tún ní Daniel Etim-Effiong ó jẹ́ ọ̀ṣèré Nollywood tó jẹ́ ọmọ orílé-èdè Naijiria ó dẹ̀ jẹ́ olùdarí fíìmù .

Ìgbésí ayé àti ètò ẹ̀kọ́

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bíi sí ilu Jaji ni ipinle KadunaNaijiria ó sì ti gbé ní ilu Beninipinle Edo ; Ipinle Eko àti Abuja rí. Bàbá rẹ̀ wá nínu Ẹgbẹ ọmọ ogun Naijiria . Bàbá rẹ̀, Lt Col. Moses Effiong àti àwọn márùn-ún kàn gba ìdáríjì ìjọba ti ipò Ààrẹ láti ọ̀dọọ Ààrẹ Nàìjíríà Muhammadu Buhari lẹ́yìn tí wọ́n fi ẹ̀sùn ṣíṣe "Vasta Coup" kàn wọ́n tí wọ́n sì rán wọn lọ sí ẹ̀wọ̀n gbére ní ọdún 1986 ní àkókò ìjọba Ibrahim Babangida lórí ẹ̀sùn ìwà-ọ̀tẹ̀ àti ọ̀dàlẹ̀ sí ìjọba. ọ́W sì tú wọn sílẹ̀ ní ọdún 1993 ṣùgbọ́n láìsí ìkéde àti dídá ipò padà àti àwọn ẹ̀tọ́. àwọn ọdún èwe rẹ̀, ó lọ sí Ilé-ìwé Alákọbẹ̀rẹ̀ St Mary's Private School. ní ìsàlè èkó. Lẹ́yìn náà, ó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gírámà "Government College, Ikorodu" kí ó tó lọ sí ilé ẹ̀kọ́ gíga Federal University of Technology, Minna, Ipinle Niger, ní ibi tí ó ti kọ́ ẹ̀kọ́ tí ó sì gba òye àkọkọ nínu ẹ̀kọ́ imọ-ẹrọ kemikali . Lẹ́hìn àkókò iṣẹ́ kúkúrú ní ilé -iṣẹ epo rọ̀bìì, Ó pinu láti yí ìṣe padà, ó lọ ka ẹ̀kọ́ nípa ìṣe ère ṣíṣe, ìwé kíkọ àti Ádárì eré ní "AFDA Film School" ní South Africa. Kí ó tó lọ kọ́ ẹ̀kọ́ ìmí nípa ère ṣíṣe ni University of Johannesburg

Ìgbésí ayé rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Effiong ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Toyosi Etim-Effiong láti 4 November, 2017. Wọ́n kọ́kọ́ pàdé ní August 2016 ní ìdí íṣẹ́ kan. Wọ́n bí ọmọ akọ̀kọ̀ wọn ní January 2019