Federal Ministry of Education
Federal Ministry of Education | |
---|---|
Coat of arms of Nigeria | |
Agency overview | |
Jurisdiction | Government of Nigeria |
Headquarters | Federal Secretariat Abuja |
Minister responsible | Professor Tahir Mamman, SAN |
Website | |
education.gov.ng/ |
Àjọ Federal Ministry of Education ni ó jẹ́ ìkan lára àwọn ilé-iṣẹ́ ìjọba Federal Ministries of Nigeria tí wọ́n ń ṣe agbátẹrù fún ètò-ẹ̀kọ́ Nàìjíríà. Àjọ yí wà ní ojúlé Block 5A (8th Floor), ní Federal Secretariat Complex, Shehu Shagari Way, Central Area, P.M.B. 146, Garki, Àbújá.
Ìtàn àjọ náà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ààrẹ Bola Ahmed Tinubu yan Tahir Mamman gẹ́gẹ́ bí Mínísítà fún ètò-ẹ̀kọ́ ní ọjọ́ kẹrìndínlógún oṣù kẹjọ 2023.[1]
Afòjúsùn wọn
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]"Afòjúsùn wa ni láti lo ẹ̀kọ́ gẹ́gẹ̀ bí irinṣẹ́ fún ìdàgbàsókè gbogbo ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà kí wọ́n lè ṣ'àwárí ara wọn, ìrónilágbára fún iṣèjọba àwa ara wa, déédé, ìgbèrú òun ìdàgbàsókè enìkọ̀ọ̀kan àti orílẹ̀-èdè wa lábẹ́ àṣẹ Elédùmarè". [2]
Àgbekalẹ̀ àjọ náà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Gbogbo awọn àjọ ìsàlẹ yi ni wọ́n wà ni abẹ́ àjọ Federal Ministary of Education
- Formulating a national policy on education.
- Collecting and collating data for purposes of educational planning and financing.
- Maintaining uniform standards of education throughout the country.
- Controlling the quality of education in the country through the supervisory role of the Inspectorate Services Department within the Ministry.
- Harmonizing educational policies and procedures of all the states of the federation through the instrumentality of the National Council on Education.
- Effecting co-operation in educational matters on an international scale.
- Developing curricula and syllabuses at the national level in conjunction with other bodies.
- National Board for Technical Education (NBTE Archived 2022-07-19 at the Wayback Machine.), Kaduna.
- National Commission for Colleges of Education (NCCE), Abuja.
- Universal Basic Education Commission (UBEC), Abuja.
- National Commission for Nomadic Education (NCNE), Abuja.
- National Commission for Adult Education Mass Literacy and Non-Formal Education (NMEC), Abuja.
- Nigerian Educational Research and Development Council (NERDC), Sheda, FCT.
- Joint Admissions and Matriculation Board (JAMB), Bwari, Abuja.
- West African Examination Council (WAEC), Lagos.
- National Examination Council (NECO), Minna, State.
- National Business and Technical Examinations Board (NABTEB Archived 2021-06-23 at the Wayback Machine.), Benin-city, Edo.
- National Institute for Educational Planning & Administration (NIEPA Archived 2021-06-24 at the Wayback Machine.), Ondo.
- National Teachers Institute (NTI Archived 2022-05-26 at the Wayback Machine.), Kaduna.
- Nigerian Mathematical Centre (NMC), Sheda, FCT.
- Nigerian French Language Village (NFV)Badagry, Lagos.
- Nigerian Arabic Language Village (NALV) Ngala, Borno.
- National Institute for Nigerian Languages (NINLAN) Aba, Abia.
- Tertiary Education Trust Fund (TET FUND), Abuja.
- National Library of Nigeria (NLN), Abuja.
- Teachers' Registration Council of Nigeria (TRCN Archived 2022-07-13 at the Wayback Machine.), Abuja.
- Computer Professionals Registration Council of Nigeria (CPN), Lagos.
- Federal Scholarship Board, Abuja.
- Librarians' Registration Council of Nigeria (LRCN Archived 2022-06-20 at the Wayback Machine.), Abuja
Ẹ tún lè wo
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- List of education ministers of Nigeria
- Nigerian Civil Service
- List of polytechnics in Nigeria
- List of universities in Nigeria
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "Jubilation at Education Ministry as Adamu takes over". Nigeria. Archived from the original on 2016-03-04. Retrieved 2015-11-14.
- ↑ "Home" (in en-US). FEDERAL MINISTRY OF EDUCATION. https://education.gov.ng/.
afdulrazak JIBRIN IBRAHIM 419-$fmoedu in 1988 to date"; "A" to actually get money from you and protect yourself