J. E. A. Wey

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Vice Admiral/Igbakeji Adarioko-ogunojuomi Joseph Edet Akinwale Wey
JEAWey.JPG
2nd Vice President of Nigeria
Lórí àga
July 29, 1966 – July 29, 1975
President Yakubu Gowon
Asíwájú Babafemi Ogundipe
Arọ́pò Olusegun Obasanjo
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ọmọorílẹ̀-èdè Nigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlú None (military)

Joseph Edet Akinwale Wey (ojoalaisi 12 December 1990) [1] je omose ologun ojuomi orile-ede Naijiria to figba kan je, bi olori Ile-ise Ologun Ojuomi Naijiria,[2] adipo Alakoso Oro Okere,[3] ati Oga Gbogbo Omose Ologun ni Ibujoko Togajulo,[4] eyi to so di de facto Igbakeji Aare ile Naijiria nigba ijoba Yakubu Gowon. O fi tipatipa feyinti nigba ti Murtala Mohammed fitipagbajoba lowo Gowon.[4]


References[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]