King of Boys: The Return of the King
King of Boys: The Return of the King | |
---|---|
Fáìlì:King of Boys 2.jpg | |
Genre | Political crime drama |
Created by | Kemi Adetiba |
Directed by | Kemi Adetiba |
Starring | Sola Sobowale Toni Tones |
Country of origin | Nigeria |
Original language(s) | English Igbo Yoruba Hausa |
No. of seasons | 1 |
No. of episodes | 7 |
Production | |
Producer(s) | Remi Adetiba Kemi Adetiba Joy Nnamdi-Yusuf |
Running time | 60 minutes |
Release | |
Original network | Netflix |
Original release | 27 Oṣù Kẹjọ 2021 |
Chronology | |
Related shows | King of Boys |
King of Boys: The Return Of The King jẹ́ fíìmù alápá méje tó jáde ní ọdún 2021,tí Kemi Adetiba jẹ́ olùdarí fún. 27 August 2021 ni wọ́n ṣe àgbéjáde fíìmù yìí[1] lórí Netflix, èyí tó jẹ́ apá kejì King of Boys tó jẹ́ fíìmù adá lórí òṣèlú àti ìwà-ọ̀daràn inú àwùjọ.[2][3] Sola Sobowale àti Toni Tones náà ló ṣe ẹ̀dá ìtàn Eniola Salami pẹ̀lú Reminisce, Illbliss, Akin Lewis, Osas Ighodaro àti Keppy Ekpenyong náà jé ẹ̀dá-ìtàn tí wọ́n ṣe nínú apá kìíní. Àfikún àwọn ẹ̀dá-ìtàn ni Nse Ikpe-Etim, Richard Mofe Damijo, Efa Iwara, Deyemi Okanlawon àti Charly Boy.[2]
Ìtàn ní ṣókí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Eré náà tẹ̀síwájú lẹ́yìn ìgbé-léhìn-odi ti Eniola Salami, tó sì padà wá lẹ́yìn ọdún márùn-ún. Látàrí àìtẹ́lọ́rùn láti bẹ̀rẹ̀ ìgbé ayé tuntun, ó padà sí ìdí òṣèlú, ti ọ̀tè yìí tún wá le ju tàtẹ̀yìnwá lọ.
Àwọn akópa
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Sola Sobowale bí i Eniola Salami
- Toni Tones bí i Young Eniola Salami
- Reminisce bí i Makanaki
- Illbliss bí i Odogwu Malay
- Akin Lewis bí i Aare Akinwande
- Osas Ighodaro bí i Sade Bello
- Titi Kuti bí i Ade Tiger
- Keppy Ekpeyong bí i President Mumusa
- Nse Ikpe Etim bí i First Lady Jumoke Randle
- Richard Mofe-Damijo bí i Reverend Ifeanyi
- Efa Iwara bí i Dapo Banjo
- Deyemi Okanlawon bí i Adetola Fashina
- Charly Boy bí i Odudubariba
- Bimbo Manuel bí i Mr. Mogaji
- Taiwo Ajai-Lycett bí i Chief Mrs Randle
- Lord Frank bí i Tunde Randle
- Lanre Hassan bí i Iyaloja
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Cocomello, Marco (30 July 2021). "Everything New on Netflix This August". www.glitched.online (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 6 August 2021.
- ↑ 2.0 2.1 Adekanye, Modupe (26 July 2021). "King Of Boys: The Return Of The King Returns As 7-Episode Series". The Guardian Nigeria News - Nigeria and World News (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 29 July 2021. Retrieved 6 August 2021.
- ↑ "Kemi Adetiba announces release date for King of Boys sequel". Punch Newspapers (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 26 July 2021. Retrieved 6 August 2021.