Mòsámbìk

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Republic of Mozambique
República de Moçambique
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèPátria Amada
(formerly Viva, Viva a FRELIMO)
Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Maputo
25°57′S 32°35′E / 25.95°S 32.583°E / -25.95; 32.583
Èdè oníbiṣẹ́ Portuguese
Vernacular languages Swahili, Makhuwa, Sena
Orúkọ aráàlú Ará Mozambique
Ìjọba Republic
 -  President Armando Guebuza
 -  Prime Minister Aires Ali
Independence
 -  from Portugal June 25, 1975 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 801,590 km2 (35th)
309,496 sq mi 
 -  Omi (%) 2.2
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2009 22,894,000[1] (54th)
 -  2007 census 21,397,000 (52nd) 
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 28.7/km2 (178th)
74.3/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2008
 -  Iye lápapọ̀ $18.740 billion[2] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $903[2] 
GIO (onípípè) Ìdíye 2008
 -  Àpapọ̀ iye $9.897 billion[2] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $477[2] 
Gini (1996–97) 39.6 (medium
HDI (2007) 0.402 (low) (172nd)
Owóníná Mozambican metical (Mtn) (MZN)
Àkókò ilẹ̀àmùrè CAT (UTC+2)
 -  Summer (DST) not observed (UTC+2)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ left
Àmìọ̀rọ̀ Internet .mz
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 258
1 Estimates for this country explicitly take into account the effects of excess mortality due to AIDS; this can result in lower life expectancy, higher infant mortality and death rates, lower population and growth rates, and changes in the distribution of population by age and sex than would otherwise be expected.

Mozambique, fun ibise Olominira ile Mozambique (Pọrtugí: Moçambique tabi República de Moçambique, pípè [ʁɛˈpublikɐ di musɐ̃ˈbiki]), je orile-ede ni apaguusuilaorun Africa to ni bode mo Okun India ni ilaorun, Tanzania ni ariwa, Malawi ati Zambia ni ariwaiwoorunt, Zimbabwe ni iwoorun ati Swaziland ati Guusu Afrika ni guusuiwoorun.

Abe Portugal ni Mozambique wa tele. Bèbè gúsù-ìlà-oòrùn Aáfíríkà ni Mozambique wa. Ó tóbi ju Portugal gan-an lo. Àwon ìlú tí ó wà ní bèbè Mozambique bíi Laurence Marquis (tí ó jé olú-ìlú Mozambique) àti Beira ni àwon okò ojú omi ti n gúnlè. Okò ojú irín ni ó so àwon ìlú wònyí mó àwon ilè tí ó kan Mozambique gbàngbàn. Àwon ènìyàn tí ó wà ní Mozambique tó 7,376,000. Púpò nínú won ni ó jé Bantu. Púpò nínú won ni ó n sisé ní South Africa níbi tí wón ti n wa ohun àlùmó-ónni ilè (minerals). Àwon mìíràn n se isé àgbè. Wón n gbe òwú, kasú, ìrèké àti béè béè lo. Orí ilè peere ni wónm ti n gbin àwon wònyí. Orí òkè ni wón tí n gbin tíì (tea).

Vasco da Gama ni ó se àwárí Mozambique ní 1498. Àwon ara Portugal bèrè síí wá sí ibè ní nnkan bí 1500. Mozambique sì bèrè síí se pàtàkì fún òwò erú. Àwon ilé-isé (companies) ni ó n darí ilè yìí láti 1891 sí 1942. Odún 1942 ni ìjoba Portugal bèrè síí darí ilè yìí. Ní 1960 àti 1970, Portugal kó òpòlopò omo ogun lo sí Mozambique láti bá àwon tí ó n jà fún òmìnira jà.Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]