Meles Zenawi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Lọ sí: atọ́ka, àwárí
Meles Zenawi
መለስ ዜናዊ
Meles Zenawi - World Economic Forum Annual Meeting 2012.jpg
Alakoso Agba ile Ethiopia
Lórí àga
23 August 1995 – 20 August 2012
President Negasso Gidada
Girma Wolde-Giorgis
Asíwájú Tamirat Layne (Agbaaye)
Arọ́pò Hailemariam Desalegn
Aare ile Ethiopia
Lórí àga
28 May 1991 – 22 August 1995
Aṣàkóso Àgbà Tesfaye Dinka
Tamirat Layne
Asíwájú Tesfaye Gebre Kidan (Acting)
Arọ́pò Negasso Gidada
Ẹ̀kúnrẹ́rẹ́
Ìbí Legesse Zenawi Asres
8 Oṣù Kàrún, 1955(1955-05-08)
Adwa, Ethiopia
Aláìsí 20 Oṣù Kẹjọ, 2012 (ọmọ ọdún 57)
Brussels, Belgium[1]
Ẹgbẹ́ olóṣèlú Ethiopian People's Revolutionary Democratic Front
Àwọn ìbáṣe
olóṣèlú mìíràn
Tigrayan People's Liberation Front
Tọkọtaya pẹ̀lú Azeb Mesfin
Alma mater Open University
Erasmus University Rotterdam
Ẹ̀sìn Ethiopian Orthodoxy

Àdàkọ:Contains Ethiopic text Meles Zenawi Asres (Ge'ez: መለስ ዜናዊ አስረስ Mäläs Zenawi Äsräs; 8 May 1955 – 20 August 2012, abiso bi Legesse Zenawi Asres)[2] ni Alakoso Agba orile-ede Ethiopia. Lati 1985, ohun ni alaga Tigrayan Peoples' Liberation Front (TPLF), ati lowolowo olori Ethiopian People's Revolutionary Democratic Front (EPRDF).


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]