Jump to content

Mohammed Yunus

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Muhammad Yunus
মুহাম্মদ ইউনুস
Welfare economics , Development economics , Public Health , Gender Studies , Political Philosophy , Utilitarianism
Muhammad Yunus at World Economic Forum in Davos, Switzerland, 31 January 2009
Born28 Oṣù Kẹfà 1940 (1940-06-28) (ọmọ ọdún 84)
Chittagong, Bangladesh
Nationality Bangladeshi
InstitutionChittagong University
Shahjalal University of Science and Technology
Middle Tennessee State University
FieldMicrocredit, Welfare economics, ethics
Alma materUniversity of Dhaka
Vanderbilt University
ContributionsGrameen Bank
Microcredit
AwardsIndependence Day Award (1987)
World Food Prize (1994)
Nobel Peace Prize (2006)
Presidential Medal of Freedom (2009)

Muhammad Yunus (Bẹ̀ngálì: মুহাম্মদ ইউনুস, pipe [Muhammôd Iunus] error: {{lang}}: text has italic markup (help)) (ojoibi 28 June 1940) je omo ilè Bangladesh. Wón bí i ní 1940 fún ebí olówó kan ní Chittagong. Gosimíìtì ni bàbá rè. Ìyá rè jé Sofia Khatun. Mama rè yìí máa n ran àwon òtòsì lówó. Ìwà yìí sì ran Mohammed. Nígbà tí òun náà dàgbà, ó dí ilé-ìfowópamó tí a ti lè máa yá àwon òtòsì lówó sílè. Won kò nílò láti ní ìdúró kankan. Irú bánkì yìí ni í wá di community Bank lóde òní Mohammed Yunus ló kókó dá a sílè. Yunus tí ní irú bánkì yìí nínú abúlé tó tó 35,000 nínú abúlé 68,000 tí ó wà ní Bangladesh. Ó ti yá òpòlopò ènìyán kówó. Obìnrin ló pò jù nínú àwon tí ó n yáwó lówó rè. Òun ni ó gba Ẹ̀bùn Nobel ti 2006