Àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19 ní Kepu Ferde: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Kò ní yàtọ̀)

Àtúnyẹ̀wò ní 20:22, 31 Oṣù Kẹjọ 2020

Àjàkálẹ̀-àrùn COVID-19 ní Cape Verde
    Municipalities with 300 to 2999 cases reported by the National Institute of Public Health
    Municipalities with 30 to 299 cases reported by the National Institute of Public Health
    Municipalities with 3 to 29 cases reported by the National Institute of Public Health
    Municipalities with 1 or 2 cases reported by the National Institute of Public Health[1]
ÀrùnCOVID-19
Irú kòkòrò èrànSARS-CoV-2
IbiCape Verde
Arrival date20 March 2020
(4 years, 1 month and 6 days)
Gbogbo iye àwọn ẹ̀sùn2,354 (as of 28 July)[2]
Active cases716 (as of 28 July)
Iye àwọn tí ara wọn ti yá1,616 (as of 28 July)
Iye àwọn aláìsí
22 (as of 24 July)
Official website
COVID 19 — Corona Vírus - Official site about COVID-19 in Cape Verde

Àjàkálẹ-àrùn COVID-19 ni wọ́n fìdí rẹ múlẹ̀ pé ó dé orílẹ̀-èdè Cape Verde ní oṣù kẹta ọdún 2020.

Ìpìnlẹ̀

Ní ọjọ́ kejìlá oṣù èkíní ọdún 2020, àjọ tí ó ń rí sí ètò ìlera ní àgbáyé (World Health Organization) fìdí rẹ múlẹ̀ pé kòkòrò àrùn ẹ̀rànkòrónà ni ó fa àrùn atẹ́gùn ní àárín ọ̀pọ̀ àwọn ènìyàn ní ìlú Wuhan ní agbègbè Hube, orílẹ̀-èdè China, èyí tí wọ́n jábọ̀ rẹ fún àjọ tí ó ń rí sí ètò ìlera ní àgbáyé ní ọjọ́ kọkànlélọ́gbọ̀n oṣù kejìlá ọdún 2019.

Ìṣẹ̀lẹ̀ àrùn COVID-19 kéré púpọ̀ sí ti SARS tí ó wáyé ní ọdún 2003 ṣùgbọ́n bí àrùn COVID-19 ṣe ń tàn káríayé pọ̀ púpọ̀ ní pàtàkì tí a bá wo iye àwọn tí wọ́n ti jẹ́ aláìsí.

Itokasi

  1. "COVID 19 – Corona Virus" (in Èdè Pọtogí). Retrieved 2020-05-23. 
  2. "COVID 19 – Corona Virus" (in Èdè Pọtogí). Retrieved 2020-07-22.