Làìbéríà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Republic of Liberia)
Jump to navigation Jump to search
Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Làìbéríà
Republic of Liberia
Àsìá Àmì ọ̀pá àṣẹ
Motto"The love of liberty brought us here"
Orin-ìyìn orílẹ̀-èdèAll Hail, Liberia, Hail!
Olúìlú
(àti ìlú títóbijùlọ)
Monrovia
6°19′N 10°48′W / 6.317°N 10.8°W / 6.317; -10.8
Èdè àlòṣiṣẹ́ English
Orúkọ aráàlú Ará Làìbéríà
Ìjọba Presidential republic
 -  Aare Ellen Johnson Sirleaf
 -  Igbakeji Aare Joseph Boakai
 -  Chief Justice|Onidajo Agba Johnnie Lewis
Formation| Idasile ile Làìbéríà by African-Americans 
 -  ACS colonies    consolidation 1821-1842 
 -  Ilominira (latowo Àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà) 26 July 1847 
Ààlà
 -  Àpapọ̀ iye ààlà 111,369 km2 (103rd)
43,000 sq mi 
 -  Omi (%) 13.514
Alábùgbé
 -  Ìdíye 2009 3,955,000[1] 
 -  2008 census 3,476,608 (130th)
 -  Ìṣúpọ̀ olùgbé 35.5/km2 (180th)
92.0/sq mi
GIO (PPP) ìdíye 2009
 -  Iye lápapọ̀ $1.556 billion[2] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $424[2] 
GIO (onípípè) Ìdíye 2009
 -  Àpapọ̀ iye $876 million[2] 
 -  Ti ẹnikọ̀ọ̀kan $239[2] 
HDI (2007) 0.442 (low) (169th)
Owóníná Liberian dollar1 (LRD)
Àkókò ilẹ̀àmùrè GMT
 -  Summer (DST) not observed (UTC)
Ìwakọ̀ ní ọwọ́ otun
Àmìọ̀rọ̀ Internet .lr
Àmìọ̀rọ̀o tẹlifóònù 231
1 United States dollar also in common usage.

Làìbéríà tabi Orile-ede Olominira ile Làìbéríà je orile-ede ni Iwoorun Afrika. O fi ègbé kan Ilè Sàró tí a mò si Sierra Leone ní ìwǫ oòrùn, orílę èdè Guinea ni gúúsù ati orílę èdè Côte d'Ivoire ní ìlà oòrùn. Etí Òkun Làìbéríà kún fún ijù igi mangrove nìbitì ilę nínú loun pęlú èrò kékeré ję kìkì ijù tí ó na apá sí ìtélè ewéko gbígbe. Ilu naa ni o ni 40% ninu eyi ti o seku ni igi Iju Guinea ti Apa Guusu. Afefe ilu Làìbéríà je ti gbigbona ila idameji aye, pelu òjo pupo ni osu May titi di osu October ni asiko òjò ati afefe oye lile fun iyoku odun.


Àwọn Ìtọ́ka sí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Department of Economic and Social Affairs Population Division (2009) (PDF). World Population Prospects, Table A.1. 2008 revision. United Nations. http://www.un.org/esa/population/publications/wpp2008/wpp2008_text_tables.pdf. Retrieved 2009-03-12. 
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 "Liberia". International Monetary Fund. Retrieved 2010-04-21.