Venus Williams
Ìrísí
Orílẹ̀-èdè | USA |
---|---|
Ibùgbé | Palm Beach Gardens, Florida |
Ọjọ́ìbí | 17 Oṣù Kẹfà 1980 Lynwood, California, U.S. |
Ìga | 1.85 m (6 ft 1 in) |
Ìgbà tódi oníwọ̀fà | October 31, 1994 |
Ọwọ́ ìgbáyò | Right-handed (two-handed backhand) |
Ẹ̀bùn owó | $ 28,460,747 (2nd in overall earnings) |
Ẹnìkan | |
Iye ìdíje | 617–156 (80.3%) |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 45 (Tied for 7th in overall rankings) |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 1 (February 25, 2002) |
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 41 (October 8, 2012) |
Grand Slam Singles results | |
Open Austrálíà | F (2003) |
Open Fránsì | F (2002) |
Wimbledon | W (2000, 2001, 2005, 2007, 2008) |
Open Amẹ́ríkà | W (2000, 2001) |
Àwọn ìdíje míràn | |
Ìdíje WTA | W (2008) |
Ìdíje Òlímpíkì | Gold medal (2000) |
Ẹniméjì | |
Iye ìdíje | 163–24 |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 20 |
Ipò rẹ̀ gígajùlọ | No. 1 (June 7, 2010) |
Ipò rẹ̀ lọ́wọ́ | No. 34 (October 8, 2012) |
Grand Slam Doubles results | |
Open Austrálíà | W (2001, 2003, 2009, 2010) |
Open Fránsì | W (1999, 2010) |
Wimbledon | W (2000, 2002, 2008, 2009, 2012) |
Open Amẹ́ríkà | W (1999, 2009) |
Àwọn ìdíje Ẹniméjì míràn | |
Ìdíje Òlímpíkì | Gold medal (2000, 2008, 2012) |
Àdàpọ̀ Ẹniméjì | |
Iye ìdíje | 25–6 (80.6%) |
Iye ife-ẹ̀yẹ | 2 |
Grand Slam Mixed Doubles results | |
Open Austrálíà | W (1998) |
Open Fránsì | W (1998) |
Wimbledon | F (2006) |
Open Amẹ́ríkà | QF (1998) |
Last updated on: October 8, 2012. |
Iye ẹ̀ṣọ́ Olympiki | |||
Women's tennis | |||
---|---|---|---|
Adíje fún the USA | |||
Wúrà | 2000 Sydney | Singles | |
Wúrà | 2000 Sydney | Doubles | |
Wúrà | 2008 Beijing | Doubles | |
Wúrà | 2012 London | Doubles |
Venus Ebony Starr Williams[1] (ojoibi 17 Osu Kefa, 1980) je ara Amerika agba tenis alagbase to wa ni ipo karun lagbaye fun awon adije enikan ati ipo kinni lagbaye fu awon adije enimeji. O ti wa ni ipo kinni lagbaye fun awon adije enikan latowo WTA ni emeta otooto. O bo si ipo akoko lagbaye ni igba akoko ni ojo 25 Osu Keji, 2002. Venus ni egbon Serena Williams to un na je agba tenis.
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Àwọn ẹ̀ka:
- Pages using duplicate arguments in template calls
- Pages with non-numeric formatnum arguments
- Pages using deprecated image syntax
- Àwọn ọjọ́ìbí ní 1980
- Àwọn ènìyàn alààyè
- Àwọn ará Amẹ́ríkà
- Àwọn ọmọ Áfríkà Amẹ́ríkà
- Àwọn agbá tẹ́nìs ará Amẹ́ríkà
- Àwọn ayọrí Ìdíje Wimbledon
- Àwọn ayọrí Open Amẹ́ríkà
- Àwọn tó gba ẹ̀ṣọ́ wúrà Òlímpíkì fún Orílẹ̀-èdè Amẹ́ríkà