Wikipedia:Àwọn Ìṣẹ̀lẹ̀ Bíi Ọjọ́ Òní/Ọjọ́ 4 Oṣù Kejì
Ìrísí
- 1789 – George Washington jẹ́ dídíbòyàn láìlólódì bíi Ààrẹ àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà àkọ́kọ́ látọwọ́ Ẹgbẹ́ Oníbò Amẹ́ríkà.
- 1794 – Ilé Aṣòfin Fránsì f'òfin pa oko-erú rẹ́ káàkiri agbègbè Orílẹ̀-èdè Fránsì.
- 1859 – Ìwé Codex Sinaiticus jẹ́ wíwárí ní Egypt.
- 1969 – Yasser Arafat di alága PLO.
Àwọn ọlọ́jọ́ìbí lóòní...
- 1913 – Rosa Parks (fọ́tò), alákitiyan ẹ̀tọ́ aráàlú ará Amẹ́ríkà (al. 2005)
- 1725 – Dru Drury, aṣeọ̀rọ̀kòkòrò ará Ilẹ̀gẹ̀ẹ́sì (al. 1804)
- 1947 – Dan Quayle, Igbákejì Ààrẹ àwọn Ìpínlẹ̀ Aṣọ̀kan Amẹ́ríkà 44k.
Àwọn aláìsí lóòní...
- 1928 – Hendrik Lorentz, aṣefísíksì ará Hóllándì àti ẹlẹ́bùn Nobel (ib. 1853)
- 2001 – J. J. Johnson, olórin jazz ará Amẹ́ríkà (ib. 1924)
- 2005 – Ossie Davis, Òṣeré àti alákitiyan ará Amẹ́ríkà (ib. 1917)