Funmilayo Ransome-Kuti: Ìyàtọ̀ láàrin àwọn àtúnyẹ̀wò
No edit summary |
Created by translating the page "Funmilayo Ransome-Kuti" |

Ìlà 1: | Ìlà 1: | ||
{{Infobox officeholder|name=Funmilayo Ransome Kuti|honorific-suffix=[[Order of the Niger|MON]]|image=70 year old Funmilayo Ransome-Kuti on her birthday.png|birth_date={{birth date |df=yes|1900|10|25}}|birth_place=[[Abeokuta]], [[Southern Nigeria Protectorate|Southern Nigeria]]
('''now''': Abeokuta, Ogun State)|death_date={{death date and age|df=yes|1978|4|13|1900|10|25}}|death_place=[[Lagos]], [[Lagos State]], Nigeria|spouse=[[Israel Oludotun Ransome-Kuti]]|children=[[Olikoye Ransome-Kuti]] (son)
[[Beko Ransome-Kuti]] (son)
[[Fela Anikulapo-Kuti]] (son)
Dolapo Ransome-Kuti (daughter)|occupation=Educator, women's rights activist}}'''Funmilayo Ransome Kuti''', MON (Ọjọ́ karùndílógún oṣù kẹwá ọdún 1900 [[Abẹ́òkúta|Abeokuta]], [[Nàìjíríà]] - ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹrin ọdún 1978 Ìpínlẹ̀ Èkó, [[Nàìjíríà]]),<ref name="nigerianstatesmen">{{Cite web|url=http://nigerianstatesmen.com/?p=77|title=Funmilayo Ransome Kuti Nigerian Statesmen}}</ref> jẹ́ olùkọ́, olóṣèlú, ajàfẹ́tọ́ ọmọ ènìyàn àti agbé ìṣẹ̀ṣe lárugẹ. Ó jẹ́ ọkàn gbọ̀ọ́n lára àwọn olórí nígbà ayé rẹ̀. Ó jẹ́ obìrin àkọ́kọ́ tí ó |

{{Infobox officeholder|name=Funmilayo Ransome Kuti|honorific-suffix=[[Order of the Niger|MON]]|image=70 year old Funmilayo Ransome-Kuti on her birthday.png|birth_date={{birth date |df=yes|1900|10|25}}|birth_place=[[Abeokuta]], [[Southern Nigeria Protectorate|Southern Nigeria]]
('''now''': Abeokuta, Ogun State)|death_date={{death date and age|df=yes|1978|4|13|1900|10|25}}|death_place=[[Lagos]], [[Lagos State]], Nigeria|spouse=[[Israel Oludotun Ransome-Kuti]]|children=[[Olikoye Ransome-Kuti]] (son)
[[Beko Ransome-Kuti]] (son)
[[Fela Anikulapo-Kuti]] (son)
Dolapo Ransome-Kuti (daughter)|occupation=Educator, women's rights activist}}'''Funmilayo Ransome Kuti''', MON (Ọjọ́ karùndílógún oṣù kẹwá ọdún 1900 [[Abẹ́òkúta|Abeokuta]], [[Nàìjíríà]] - ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹrin ọdún 1978 Ìpínlẹ̀ Èkó, [[Nàìjíríà]]),<ref name="nigerianstatesmen">{{Cite web|url=http://nigerianstatesmen.com/?p=77|title=Funmilayo Ransome Kuti Nigerian Statesmen}}</ref> jẹ́ olùkọ́, olóṣèlú, ajàfẹ́tọ́ ọmọ ènìyàn àti agbé ìṣẹ̀ṣe lárugẹ. Ó jẹ́ ọkàn gbọ̀ọ́n lára àwọn olórí nígbà ayé rẹ̀. Ó jẹ́ obìrin àkọ́kọ́ tí ó m,áa kọ́kọ́ wa ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ ní orílẹ̀ èdè rẹ̀ |

.<ref>{{Cite book|url=https://books.google.com.ng/books?id=VMi3AAAAIAAJ&q=|title=The Nigerian woman: her economic and socio-political status in time perspective|author=Modupeolu Faseke|publisher=Agape Publications|year=2001|isbn=978-9-783-5626-53}}</ref> Wọ́n maa ń pe Ransome-Kuti ní ògbóntà obìrin ajàfẹ́tọ́ ọmọ ènìyàn látàrí ipa tí ó kó nínu ìjàfẹ́tọ́ ọmọ ènìyàn, tí wọ́n sì tún maa ń pèé ní |

"Ìyá Ilẹ̀ Aláwọ̀ Dúdú." Ní ìbẹ̀ẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀, ó jẹ́ alágbára tí ó ń jà fún ẹ̀tọ́ àwọn obìrin ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ní ọdún 1947, wọ́n pèé ní ''West African Pilot'' pèé ní "Abo kìnìún ti Lisabi" fún ipa tí ó kó gẹ́gẹ́ bí olórí àwọn obírin ní Ẹ̀gbá láti ríi wípé àwọn obìrin kò sanwó orí mọ́. Làlà kokofẹ̀fẹ̀ yìí ní ó jẹ́ kí Ọba Ademola ẹ̀ẹ̀kejì fi orí ìtẹ́ sílẹ̀ ní ọdún 1949. |

Kuti jẹ́ ìyá ajàfún ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn, [[Fela Kuti|Fela Anikulapo Kuti]], olórin; [[Beko Ransome-Kuti]], dòkítà àti ọ̀jọ̀gbọ́n Olikoye Ransome-Kuti, tí ó jẹ́ dókítà àti mínísítà.<ref name="familytree">{{Cite web|url=http://jibolu-taiwo-of-egbaland.com/4.html|title=Family tree: jibolu-taiwo-of-egbaland}}</ref> Ó jẹ́ ìyá-ìyà olórin [[Seun Kuti]] àti [[Femi Kuti]]. |

Ìlà 9: | Ìlà 12: | ||
Ó lọ sí ilé ìwé Abeokuta Grammar school, ó sì kẹ́kọ́ sí ní orílẹ̀ èdè England. Kòpẹ́ kòjìnàn tí ó padà sí Nàìjíríà tí ó sì bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ olùkọ́. Ní ọjọ́ ogún oṣù kínín ọdún 1925, ó fẹ́ Àlùfáà Israel Oludotun Ransome-Kuti. Ó jẹ́ olùgbèjà fún àwọn aláìlẹ́nìkan, ó sì jẹ́ olùdásílẹ̀ Nigeria Union of Teachers àti Nigerian Union of Students.<ref name="Cheryl">{{Cite book|last=Johnson-Odim|first=Cheryl|authorlink=|first2=Emma|last2=Mba|editor=|others=|title=For Women and the Nation: Funmilayo Ransome-Kuti of Nigeria|origyear=|url=|format=|accessdate=|edition=|series=|volume=|year=1997|publisher=University of Illinois Press|location=|language=|isbn=0-252-06613-8|oclc=|doi=|id=|pages=|chapter=|chapterurl=|quote=|ref=}}</ref> |

Ransome-Kuti gba ẹ̀bùn Order of Nigeria ní ọdún 1965. Yunifásítì Ìlú Ìbàdan fi ẹ̀bùn ọ̀mọ̀wé ìmọ̀ òfin dáa lọ́lá ní ọdún 1968. Ó sì tún jẹ́ ìkan lára àwọn olóyè ní ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bí olóyè ní ilẹ̀ yorùbá. |

== Àwọn ìtọ́kasí == |

[[Àwọn ọmọ Yorùbá|

== Ìjàfẹ́tọ́ ọmọ ènìyàn == |

Ní gbogbo ìgbé ayé rẹ̀, wọ́n mọ̀ọ́ sí olùkọ́ àti ajàfẹ́tọ́ ọmọ ènìyàn. Oun àti Elizabeth Adekogbe jẹ́ àwòkọ́ṣe olórí fún ìjàfẹ́tọ́ àwọn obìrin ní bíi ọdún 1950. Ó dá ẹgbẹ́ obìrin sílẹ̀ ní ìlú Abeokuta tí iye wọn sí jú ẹgbẹ̀rú lọ́nà ogún lọ, àwọn tó kàwé àti àwọn tí kò kà ló wà nínú ẹgbẹ́ náà.<ref>{{Cite web|url=http://www.nigerianbiography.com/2015/10/funmilayo-ransome-kuti-biography-and.html|title=Nigerian Biography: Funmilayo Ransome-Kuti. Biography and Activism.|website=www.nigerianbiography.com|access-date=2016-05-13}}</ref> |

=== Ẹ̀tọ́ àwọn obìrin === |

[[Fáìlì:Funmilayo_Ransome-Kuti_thinks.png|left|thumb|Funmilayo Ransome-Kuti àti Ẹgbẹ́ Ìṣọ̀kan Àwọn Obìrin ti ìlú Abeokuta<ref name="unesco">[http://www.unesco.org/new/fileadmin/MULTIMEDIA/HQ/CI/CI/pdf/publications/frk_en.pdf Funmilayo Ransome-Kuti And The Women’s Union of Abeokuta], Illustrations: Alaba Onajin, Script and text: Obioma Ofoego, UNESCO, 2014</ref>]] |

== References == |

{{Reflist|30em}} |
{{Reflist|30em}} |

[[Ẹ̀ka:Àwọn ọjọ́ìbí ní 1900]] |
[[Ẹ̀ka:Àwọn ọjọ́ìbí ní 1900]] |
Àtúnyẹ̀wò ní 21:53, 20 Oṣù Èrèlé 2017
Funmilayo Ransome Kuti | |

Àwọn àlàyé onítòhún | |
Ọjọ́ìbí | Abeokuta, Southern Nigeria (now: Abeokuta, Ogun State) | 25 Oṣù Kẹ̀wá 1900
Aláìsí | 13 April 1978 Lagos, Lagos State, Nigeria | (ọmọ ọdún 77)
(Àwọn) olólùfẹ́ | Israel Oludotun Ransome-Kuti |
Àwọn ọmọ | Olikoye Ransome-Kuti (son) Beko Ransome-Kuti (son) Fela Anikulapo-Kuti (son) Dolapo Ransome-Kuti (daughter) |
Occupation | Educator, women's rights activist |
Funmilayo Ransome Kuti, MON (Ọjọ́ karùndílógún oṣù kẹwá ọdún 1900 Abeokuta, Nàìjíríà - ọjọ́ kẹtàlá oṣù kẹrin ọdún 1978 Ìpínlẹ̀ Èkó, Nàìjíríà),[1] jẹ́ olùkọ́, olóṣèlú, ajàfẹ́tọ́ ọmọ ènìyàn àti agbé ìṣẹ̀ṣe lárugẹ. Ó jẹ́ ọkàn gbọ̀ọ́n lára àwọn olórí nígbà ayé rẹ̀. Ó jẹ́ obìrin àkọ́kọ́ tí ó m,áa kọ́kọ́ wa ọkọ̀ ayọ́kẹ́lẹ́ ní orílẹ̀ èdè rẹ̀
.[2] Wọ́n maa ń pe Ransome-Kuti ní ògbóntà obìrin ajàfẹ́tọ́ ọmọ ènìyàn látàrí ipa tí ó kó nínu ìjàfẹ́tọ́ ọmọ ènìyàn, tí wọ́n sì tún maa ń pèé ní "Ìyá Ilẹ̀ Aláwọ̀ Dúdú." Ní ìbẹ̀ẹ̀rẹ̀ pẹ̀pẹ̀, ó jẹ́ alágbára tí ó ń jà fún ẹ̀tọ́ àwọn obìrin ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ní ọdún 1947, wọ́n pèé ní West African Pilot pèé ní "Abo kìnìún ti Lisabi" fún ipa tí ó kó gẹ́gẹ́ bí olórí àwọn obírin ní Ẹ̀gbá láti ríi wípé àwọn obìrin kò sanwó orí mọ́. Làlà kokofẹ̀fẹ̀ yìí ní ó jẹ́ kí Ọba Ademola ẹ̀ẹ̀kejì fi orí ìtẹ́ sílẹ̀ ní ọdún 1949.
Kuti jẹ́ ìyá ajàfún ẹ̀tọ́ ọmọ ènìyàn, Fela Anikulapo Kuti, olórin; Beko Ransome-Kuti, dòkítà àti ọ̀jọ̀gbọ́n Olikoye Ransome-Kuti, tí ó jẹ́ dókítà àti mínísítà.[3] Ó jẹ́ ìyá-ìyà olórin Seun Kuti àti Femi Kuti.
Ìgbésíayé rẹ̀
Wọ́n bí Francis Abigail Olufunmilayo Thomas ní ọjọ́ karùndílógún oṣù kẹwá ọdún 1900, ní ilú Abeokuta, fún Daniel Olumeyuwa Thomas àti Lucretia Phyllis Omoyeni Adeosolu. Bàbá rẹ̀ jẹ́ ọmọ ẹrú tí ó wálé láti Sierra Leone, tí orísun rẹ̀ jẹ́ Abeokuta tí a mọ̀ sí Ìpínlẹ̀ Ògùn lóde òní, Nàìjíríà.[4] Ó jẹ́ ọmọ elẹ́sìn ìjọ Anglican faith, tí ó sì padà lọ bá àwọn ẹlẹgbẹ́ rẹ̀ tí ó jẹ́ ọmọ Ẹ̀gbá.
Ó lọ sí ilé ìwé Abeokuta Grammar school, ó sì kẹ́kọ́ sí ní orílẹ̀ èdè England. Kòpẹ́ kòjìnàn tí ó padà sí Nàìjíríà tí ó sì bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ olùkọ́. Ní ọjọ́ ogún oṣù kínín ọdún 1925, ó fẹ́ Àlùfáà Israel Oludotun Ransome-Kuti. Ó jẹ́ olùgbèjà fún àwọn aláìlẹ́nìkan, ó sì jẹ́ olùdásílẹ̀ Nigeria Union of Teachers àti Nigerian Union of Students.[5]
Ransome-Kuti gba ẹ̀bùn Order of Nigeria ní ọdún 1965. Yunifásítì Ìlú Ìbàdan fi ẹ̀bùn ọ̀mọ̀wé ìmọ̀ òfin dáa lọ́lá ní ọdún 1968. Ó sì tún jẹ́ ìkan lára àwọn olóyè ní ìwọ̀ oòrùn Nàìjíríà gẹ́gẹ́ bí olóyè ní ilẹ̀ yorùbá.
Ìjàfẹ́tọ́ ọmọ ènìyàn
Ní gbogbo ìgbé ayé rẹ̀, wọ́n mọ̀ọ́ sí olùkọ́ àti ajàfẹ́tọ́ ọmọ ènìyàn. Oun àti Elizabeth Adekogbe jẹ́ àwòkọ́ṣe olórí fún ìjàfẹ́tọ́ àwọn obìrin ní bíi ọdún 1950. Ó dá ẹgbẹ́ obìrin sílẹ̀ ní ìlú Abeokuta tí iye wọn sí jú ẹgbẹ̀rú lọ́nà ogún lọ, àwọn tó kàwé àti àwọn tí kò kà ló wà nínú ẹgbẹ́ náà.[6]
Ẹ̀tọ́ àwọn obìrin
References
- ↑ "Funmilayo Ransome Kuti Nigerian Statesmen".
- ↑ Modupeolu Faseke (2001). The Nigerian woman: her economic and socio-political status in time perspective. Agape Publications. ISBN 978-9-783-5626-53. https://books.google.com.ng/books?id=VMi3AAAAIAAJ&q=.
- ↑ "Family tree: jibolu-taiwo-of-egbaland".
- ↑ Margaret Strobel, "Women agitating internationally for change".
- ↑ Johnson-Odim, Cheryl; Mba, Emma (1997). For Women and the Nation: Funmilayo Ransome-Kuti of Nigeria. University of Illinois Press. ISBN 0-252-06613-8.
- ↑ "Nigerian Biography: Funmilayo Ransome-Kuti. Biography and Activism.". www.nigerianbiography.com. Retrieved 2016-05-13.
- ↑ Funmilayo Ransome-Kuti And The Women’s Union of Abeokuta, Illustrations: Alaba Onajin, Script and text: Obioma Ofoego, UNESCO, 2014