Àgbájọ Òṣìṣẹ́ Akáríayé

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Àgbájọ Òṣìṣẹ́ Akáríayé
International Labour Organization
Organisation internationale
du Travail
Organización Internacional
del Trabajo
IrúUN agency
OrúkọkúkúrúILO
OlóríJuan Somavía
Ipòactive
Dídásílẹ̀1919
IbùjókòóGeneva
Ibiìtakùnilo.org

Àgbájọ Òṣìṣẹ́ Káríayé (International Labour Organization; ILO) je ile-ise agbajo akariaye ti Agbajo awon Orile-ede Asokan to je mo oro osise, agaga opagun osise akariaye ati ise to niyi fun gbogbo aye.[1] Bi gbogbo awon omoegbe awon Orile-ede Asokan (185 ninu 193) ni won wa ni ILO.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. ILO Decent Work Agenda. Ilo.org. Retrieved on 2012-06-02.