Jump to content

Ìpínlẹ̀ Nasarawa

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Nassarawa State)
Ìpínlẹ̀ Násáráwá
Nasarawa State
Nickname(s): 
Location of Nasarawa State in Nigeria
Location of Nasarawa State in Nigeria
Country Nigeria
Date created1 October 1996
CapitalLafia
Government
 • Governor[1]Umar Tanko al-Makura (APC)
 • RepresentativesList
Area
 • Total27,117 km2 (10,470 sq mi)
Population
 (2005)
 • Total2,040,097
 • Density75/km2 (190/sq mi)
GDP (PPP)
 • Year2007
 • Total$3.02 billion[2]
 • Per capita$1,588[2]
Time zoneUTC+01 (WAT)
ISO 3166 codeNG-NA
Websitenasarawastate.org

Ìpínlẹ̀ Násáráwá je ikan ninu àwon Ipinle 36 ni orile-ede Naijiria. Oluilu re ni Lafia.

Ítàn Ìdásílẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ìpínlẹ̀ Nasarawa jẹ́ dídásílẹ̀ ní Ọjó kínní, osù kẹwàá, Ọdún 1996 nígbà ìsèjọba Abacha, tí wọ́n pín kúrò ní ìpínlẹ̀ Plateau odè oní.[3]

Awọn ijọba íbílẹ̀ tí ó wà nì ìpínlẹ̀ Nasarawa jẹ́ mẹ́tàlá. (Afìhàn pẹ̀lú ònkà 2006 population[4]):

Nasarawa West Senatorial District 716,802
Karu 205,477
Keffi 92,664
Kokona 109,749
Nasarawa 189,835
Toto 119,077
Nasarawa North Senatorial District 335,453
Akwanga 113,430
Eggon 149,129
Wamba 72,894
Nasarawa South Senatorial District 811,020
Awe 112,574
Doma 139,607
Keana 79,253
Lafia 330,712
Obi 148,874

Awọn orísìrísí èdè tí ó wà ní ìpínlè Nasarawa jẹ́ mókàndínlógbọ̀n.

Awọn èdè na wa nínú tábìlì yi ní nítítò Ijọba ìbílẹ̀ ìpínlè Nasarawa:[5]

LGA Languages
Akwanga Mada;Duhwa; Eggon; Fulani; Gwandara; Hausa; Mama; Ninzo; Numana; Nungu
Awe Hausa; Fulani; Gwandara; Eggon; Goemai; Lijili; Tiv; Wapan
Doma Alago; Tiv; Agatu; Fulani; Hausa;
keffi Hausa; Fulani; :madaGadeEggon;Gbagyi; Gwandara; Koro Wachi
Karu Gbagyi; Gwandara; Gade
Keana Alago; Gwandara Tiv; Fulani
Kokona Gwandara;mada Fulani; Hausa; Eggon
Lafia Bare-Bari; Hausa; Fulani; Ake;mada: Alago; Agatu; Eggon; Goemai; Gwandara; Kofyar; Lijili; Tiv; Wapan
Nasarawa Hausa; Fulani; Agatu; Alago; Basa; Egbura; Eloyi; Gade; Gbagyi; Gwandara; Eggon; Tiv
Nasarawa-Eggon Eggon; Mada; Nungu; Fulani; Hausa
Obi Alago; Hausa; Fulani; Eggon; Tiv
Toto Egbura Agatu; Eggon; Gade; Fulani; Hausa
Wamba Alumu-Tesu;ninzo:mada;rindre Bu; Eggon; Hasha; Fulani; Kantana; Nungu; Toro

Ní ìpínlè Nasarawa, orísìrísí ẹ̀yà marundinlogbon ló wà. Àwọn tí wọn ma n sọ jù nì Miligi (Koro), Alago, Mada, Gwandara, Kunari, Hausa Fulani, Gwari, Rindre, Afo, Eggon and Ebina[6]

Ìpínlẹ̀ Nasarawa ni awọn Ilé ẹ̀kọ́ bí:

  • College of Education, Akwanga
  • Federal Polytechnic Nasarawa
  • College of Agriculture in Lafia
  • Isa Mustapha Agwai I Polytechnic Lafia
  • Nasarawa State University
  • Mewar International University ní Masaka
  • Bingham University at Karu
  • Hill College of Education Gwanje Akwanga
  • NACAP polytechnic Akwanga
  • Command secondary school Lafia
  • Command secondary school Rinze
  • Vocational And Relevant technology board

Ìpínlè Nasarawa ní awọn ilé ẹ̀kọ́ alakobere àti girama bí the Federal Government Girls College, Kea.

Awon èèyàn jànkànjànkàn

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  • Imaan Sulaiman-Ibrahim – Director-General of NAPTIP
  • HRH Alhaji Abdullahi Amegwa Agbo - Osana of Keana
  • HRH Alhaji Ahmadu Aliyu Ogah - Andoma of Doma
  • Sen. Abdullahi Adamu - National Chairman, APC
  • Suleiman Odapu-Public Relations Practitioner
  1. See List of Governors of Nasarawa State for a list of prior governors
  2. 2.0 2.1 "C-GIDD (Canback Global Income Distribution Database)". Canback Dangel. Retrieved 2008-08-20. 
  3. "This is how the 36 states were created". Pulse.ng. 24 October 2017. Retrieved 22 December 2021. 
  4. 2006 Population Census, Federal Republic of Nigeria, National Bureau of Statistics. Archived from the original Archived 2007-07-04 at the Wayback Machine. on 2009-03-25.
  5. "Nigeria". Ethnologue. https://www.ethnologue.com/country/NG. 
  6. "Nasarawa Massacre: 'Barbarians' on rampage, By Dele Agekameh | Premium Times Nigeria" (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). 2013-05-22. Retrieved 2021-12-06.