Tsad

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Republic of Chad

[République du Tchad] error: {{lang}}: text has italic markup (help)
جمهورية تشاد
Jumhūriyyat Tshād
Motto: "[Unité, Travail, Progrès] error: {{lang}}: text has italic markup (help)"  (French)
"Unity, Work, Progress"
Orin ìyìn: "[La Tchadienne] error: {{lang}}: text has italic markup (help)"
Location of Chad
Olùìlú
àti ìlú tótóbijùlọ
N'Djamena
Àwọn èdè ìṣẹ́ọbaFrench, Arabic
Orúkọ aráàlúChadian
ÌjọbaRepublic
• President
Mahamat Idriss Déby Itno (محمود بن إدريس ديبي إتنو)
Succès Masra (سوكسيه ماسرا)
Independence
• from France
August 11, 1960
Ìtóbi
• Total
1,284,000 km2 (496,000 sq mi) (21st)
• Omi (%)
1.9
Alábùgbé
• 2009 estimate
10,329,208[1] (74th)
• 1993 census
6,279,921
• Ìdìmọ́ra
8.0/km2 (20.7/sq mi) (212th)
GDP (PPP)2009 estimate
• Total
$16.074 billion[2]
• Per capita
$1,611[2]
GDP (nominal)2009 estimate
• Total
$6.854 billion[2]
• Per capita
$687[2]
HDI (2007) 0.392
Error: Invalid HDI value · 175th
OwónínáCFA franc (XAF)
Ibi àkókòUTC+1 (WAT)
• Ìgbà oru (DST)
UTC+1 (not observed)
Àmì tẹlifóònù235
ISO 3166 codeTD
Internet TLD.td

Chad (Faransé: Tchad, Lárúbáwá: تشادTshād), fun ibise gege bi orile-ede Olominira ile Chad, je orile-ede tileyika ni arin Afrika. O ni bode pelu Libya ni ariwa, Sudan ni ilaorun, orile-ede Arin Afrika Olominira ni guusu, Kameroon ati Naijiria si guusuiwoorun, ati Nijer si iwoorun. Nitori ijinna re si okun ati asale to gbabe ka, Tsad je mimo bi "Okan Kiku Afrika" ("Dead Heart of Africa").


  1. Central Intelligence Agency (2009). "Chad". The World Factbook. Archived from the original on April 24, 2020. Retrieved January 28, 2010. 
  2. 2.0 2.1 2.2 2.3 "Chad". International Monetary Fund. Retrieved 2010-04-21.