Victoria (nigba miran won npe ni Port Victoria) ni oluilu ile Seychelles (oun ni oluilu Afrika to kerejulo). O budo si egbe ariwa-apailaorun erekusu Mahé, to je erekusu gbangba ni isupoerekusu na. Ilu na koko je didasile bi ibujoko ijoba alamusinBritani. Ni 2009, olugbe re je 25,000 (fun Victoria Berekete, lmupo mo awon itosi-ilu), ninu apapo olugbe 84 000. Victoria ni Papa Ofurufu Akariaye Seychelles (to je pipari ni 1971.)