Àkójọ àwọn ìpínlẹ̀ Nàìjíríà bíi ọjọ́ ìdásílẹ̀

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

The following table presents a listing of Nigeria's states and the dates of their creation.

Ìpínlẹ̀ Date Created Preceding Entity
Ìpínlẹ̀ Ábíá Ọjọ́ 27 Oṣù Kẹjọ 1991 Ìpínlẹ̀ Ímò
Ìpínlẹ̀ Adámáwá Ọjọ́ 27 Oṣù Kẹjọ 1991 Ìpínlẹ̀ Gòngólà
Ìpínlẹ̀ Akwa Íbọm Ọjọ́ 23 Oṣù Kẹ̀sán 1987 Ìpínlẹ̀ Cross River
Ìpínlẹ̀ Anámbra Ọjọ́ 27 Oṣù Kẹjọ 1991 (old) Ìpínlẹ̀ Anámbra
Ìpínlẹ̀ Bauchi Ọjọ́ 3 Oṣù Kejì 1976 North-Eastern State
Ìpínlẹ̀ Bàyélsà Ọjọ́ 1 Oṣù Kẹ̀wá 1996 Ìpínlẹ̀ Rivers
Ìpínlẹ̀ Bẹ́núé Ọjọ́ 3 Oṣù Kejì 1976 Ìpínlẹ̀ Bẹ́núé-Plateau
Ìpínlẹ̀ Bọ̀rnó Ọjọ́ 3 Oṣù Kejì 1976 North-Eastern State
Ìpínlẹ̀ Cross River Ọjọ́ 27 Oṣù Kàrún 1967 Agbègbè Apáìlàoòrùn; known as South-Eastern State from 1967 to 1976.
Ìpínlẹ̀ Dẹ́ltà Ọjọ́ 27 Oṣù Kẹjọ 1991 Bendel State
Ìpínlẹ̀ Ẹ̀bọ́nyì Ọjọ́ 1 Oṣù Kẹ̀wá 1996 Ìpínlẹ̀ Ẹnúgu and Ìpínlẹ̀ Ábíá
Ìpínlẹ̀ Ẹdó Ọjọ́ 27 Oṣù Kẹjọ 1991 Bendel State
Ìpínlẹ̀ Èkìtì Ọjọ́ 1 Oṣù Kẹ̀wá 1996 Ìpínlẹ̀ Òndó
Ìpínlẹ̀ Ẹnúgu Ọjọ́ 27 Oṣù Kẹjọ 1991 (old) Ìpínlẹ̀ Anámbra
Ìpínlẹ̀ Gòmbè Ọjọ́ 1 Oṣù Kẹ̀wá 1996 Ìpínlẹ̀ Bauchi
Ìpínlẹ̀ Ímò Ọjọ́ 3 Oṣù Kejì 1976 East Central State
Ìpínlẹ̀ Jígàwà Ọjọ́ 27 Oṣù Kẹjọ 1991 Ìpínlẹ̀ Kánò
Ìpínlẹ̀ Kàdúná Ọjọ́ 27 Oṣù Kàrún 1967 Agbègbè Apáàríwá; known as North-Central State from 1967 to 1976.
Ìpínlẹ̀ Kánò Ọjọ́ 27 Oṣù Kàrún 1967 Agbègbè Apáàríwá
Ìpínlẹ̀ Kàtsínà Ọjọ́ 23 Oṣù Kẹ̀sán 1987 Ìpínlẹ̀ Kàdúná
Ìpínlẹ̀ Kébbí Ọjọ́ 27 Oṣù Kẹjọ 1991 Ìpínlẹ̀ Sókótó
Ìpínlẹ̀ Kogí Ọjọ́ 27 Oṣù Kẹjọ 1991 Ìpínlẹ̀ Kwárà; Benue State
Ìpínlẹ̀ Kwárà Ọjọ́ 27 Oṣù Kàrún 1967 Agbègbè Apáàríwá; known as West Central State from 1967 to 1976.
Ìpínlẹ̀ Èkó Ọjọ́ 27 Oṣù Kàrún 1967 Federal Territory of Lagos and Colony Province
Ìpínlẹ̀ Násáráwá Ọjọ́ 1 Oṣù Kẹ̀wá 1996 Ìpínlẹ̀ Plateau
Ìpínlẹ̀ Niger Ọjọ́ 3 Oṣù Kejì 1976 North-Western State
Ìpínlẹ̀ Ògùn Ọjọ́ 3 Oṣù Kejì 1976 Western State
Ìpínlẹ̀ Òndó Ọjọ́ 3 Oṣù Kejì 1976 Western State
Ìpínlẹ̀ Ọ̀ṣun Ọjọ́ 27 Oṣù Kẹjọ 1991 Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́
Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Ọjọ́ 3 Oṣù Kejì 1976 Western State
Ìpínlẹ̀ Plateau Ọjọ́ 3 Oṣù Kejì 1976 Ìpínlẹ̀ Bẹ́núé-Plateau
Ìpínlẹ̀ Rivers Ọjọ́ 27 Oṣù Kàrún 1967 Agbègbè Apáìlàoòrùn
Ìpínlẹ̀ Sókótó Ọjọ́ 3 Oṣù Kejì 1976 North-Western State
Ìpínlẹ̀ Tàràbà Ọjọ́ 27 Oṣù Kẹjọ 1991 Ìpínlẹ̀ Gòngólà
Ìpínlẹ̀ Yòbè Ọjọ́ 27 Oṣù Kẹjọ 1991 Ìpínlẹ̀ Bọ̀rnó
Ìpínlẹ̀ Zamfara Ọjọ́ 1 Oṣù Kẹ̀wá 1996 Ìpínlẹ̀ Sókótó
Agbègbè Olúìlú Ìjọba Àpapọ̀ Ọjọ́ 3 Oṣù Kejì 1976 Ìpínlẹ̀ Bẹ́núé-Plateau, North-Central, and North-Western States

See also[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]