Àtòjọ àwọn Òjíṣẹ́ Ọlọ́run Pásítọ̀ ní Nàìjíríà
Ìrísí
Orúkọ àwọn gbajúmọ̀ Pásítọ̀ ní Nàìjíríà
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Elijah Abina olùdásílẹ̀ tí ìjọ The Gospel Faith Mission International (GOFAMINT)
- Enoch Adeboye adarí ìjọ Redeemed Christian Church of God (RCCG)
- Paul Adefarasin, olùdásílẹ̀ àti adari ìjọ The House on the Rock
- Godman Akinlabi, olùdásílẹ̀ àti adari ìjọ The Elevation Church
- Matthew Ashimolowo olùdásílẹ̀ àti adari ìjọ Kingsway International Christian Centre
- Olóògbé Joseph Ayo Babalola oludasile Tunde Bakare olùdásílẹ̀ àti adari ìjọ the Latter Rain Assembly.
- Done P. Dabale, Olùdásílẹ̀ ìjọ the United Methodist Church in Nigeria (UMCN).[1]
- Jeremiah Omoto Fufeyin, olùdásílẹ̀ àti adari ìjọ of Christ Mercyland Deliverance Ministry
- David Ibiyeomie, olùdásílẹ̀ àti adari ìjọ Salvation Ministries
- T. B. Joshua olùdásílẹ̀ àti adari ìjọ the Synagogue, Church Of All Nations – SCOAN
- William F. Kumuyi (olùdásílẹ̀ àti adari ìjọ Deeper Christian Life Ministry)
- Chris Kwakpovwe olùdásílẹ̀ àti adari ìjọ
- Lazarus Muoka olùdásílẹ̀ àti adari ìjọ The Lord's Chosen Charismatic Revival Movement.[2]
- Timothy Oluwole Obadare olùdásílẹ̀ àti adari ìjọ the World Soul Winning Evangelistic Ministry.
- Bola Odeleke, olùdásílẹ̀ àti adari ìjọ The Power Pentecostal Church
- Taiwo Odukoya, olùdásílẹ̀ àti adari ìjọ.
- Chris Okotie olùdásílẹ̀ àti adari ìjọ the Household of God Church.
- Gabriel Olutola olùdásílẹ̀ àti adari ìjọ The Apostolic Church Nigeria
- Emmanuel Omale olùdásílẹ̀ àti adari ìjọ Divine Hand of God Prophetic Ministry.
- Lawrence Onochie jẹ pásítọ̀ Nàìjíríà àti alábòójútó gbogbogbòò ti Kings Heritage Church.
- Ayo Oritsejafor olùdásílẹ̀ àti adari ìjọ Life Bible[3]
- Olóògbé Samuel Oshoffa (1909–1985) olùdásílẹ̀ àti adari ìjọ Celestial Church of Christ C. C .C
- Chris Oyakhilome olùdásílẹ̀ àti adari ìjọ Christ Embassy
- Bishop David Oyedepo olùdásílẹ̀ àti adari ìjọ Winners' Chapel
- Johnson Suleman, olùdásílẹ̀ àti adari ìjọ Omega Fire Ministry, Auchi, Ìpínlẹ̀ Edo.
- Isaiah Ogedegbe, elesin aguntan ati oluso buloogi[4]
- Paul Eyefian
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ "First United Methodist Bishop in Nigeria, Done Peter Dabale, Dies in U.S Hospital". umc.org. United Methodist Church. August 27, 2006. Archived from the original on September 24, 2014. Retrieved September 26, 2014.
- ↑ "Pastor Lazarus Muoka speaks In Lord's Chosen apron". Wole Balogun. The Sun News. 12 January 2015. Archived from the original on 13 July 2015. Retrieved 13 July 2015.
- ↑ "Ayo Oritsejafor is CAN President again". vanguardngr.com.
- ↑ Alaka, Gboyega; Ogunlade, Adeola (13 June 2023). "Iginla, TeeMac, others eulogise TB Joshua at posthumous birthday". The Nation Newspaper. Archived from the original on 13 June 2023. Retrieved 4 November 2023.