Jump to content

Shehu Shagari

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Alhaji Sheu Shagari)
Shehu Shagari
Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà 6k
In office
October 1, 1979 – December 31, 1983
Vice PresidentAlex Ekwueme
AsíwájúOlusegun Obasanjo (Military)
Arọ́pòMuhammadu Buhari (Military)
Additional positions
Federal Commissioner for Finance
In office
1971–1975
AsíwájúObafemi Awolowo
Arọ́pòAsumoh Ete Ekukinam
Federal Commissioner for Economic Development, Rehabilitation, and Reconstruction
In office
1970–1971
Federal Minister of Works
In office
1965–1966
Arọ́pòS.O. Williams as Minister of Works and Housing[1]
Federal Minister of Internal Affairs
In office
1962–1965
AsíwájúShettima Ali Monguno
Arọ́pòUsman Sarki
Federal Minister of Pensions
In office
1960–1962
Federal Minister of Economic Development
In office
1959–1960
Federal Minister of Commerce and Industries
In office
1958–1959
Arọ́pò
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1925-02-25)Oṣù Kejì 25, 1925
Shagari, Northern Region, British Nigeria
(now Shagari, Nigeria)
AláìsíDecember 28, 2018(2018-12-28) (ọmọ ọdún 93)
Abuja, Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúNational Party of Nigeria
Àwọn ọmọMuhammad Bala Shagari
Aminu Shehu Shagari
Abdulrahman shehu shagari
RelativesBello Bala Shagari (Grandson)

Shehu Usman Aliyu Shagari (bíi ní ọjọ́ karùndínlọ́gbọn Oṣù Keji Ọdún 1925-2018) jẹ̣́ olóṣèlú ọmọ ilẹ̀ Nàìjíríà àti Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà lati ọjọ́ kínni oṣù Kẹwá ọdún 1979 títí di ọjọ́ Ọ̀kàndínlọ́gbọ̀n Oṣù Kejìlá ọdún 1983 nígbàtí àwọn ológun gba ìjọba.

Shehu Shagari Fẹ́ ìyàwó Mẹta:Amina, Aisha, àti Hadiza. Shagari bí ọmọ púpò lára wọn ni:Muhammad Bala Shagari àti Aminu Shehu Shagari. Ní Ọdún 2001 Ọjọ́ kẹfà dín ni ọgbọ́n ,Ìyàwó rè Aisha Shagari, kú ní ilé ìwòsàn kàn ní Lọ dòní íLẹ́yìn sì kí nesi kékeré gan.Àìsàn Covidi ni ó pá Ìyàwó Shehu Shagari Ní ọdún 2021.

Ni ó jọ méjì dín lọ gbọn oṣù Kejìlá ni ọdún 2018 ni ọwọ irole. Ìṣàn rán pé ní o pá Ogbeni Shehu Shagari ni ìwòsàn àpapọ̀ kàn ní Abuja.

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "The old Bureaucracy is coming back – Eric Teniola". Nigerian Insight. Archived from the original on 19 June 2015. Retrieved 19 June 2015.