Chinedu Ikedieze

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Chinedu Ikedieze
MFR
Ikedieze níbi ayẹyẹ àmì ẹ̀yẹ ìdánilọ́lá
Ikedieze atníbi ayẹyẹ àmì ẹ̀yẹ ìdánilọ́lá 2014 Africa Magic Viewers Choice Awards
Ọjọ́ìbíChinedu Ikedieze
Oṣù Kejìlá 12, 1977 (1977-12-12) (ọmọ ọdún 46)
Iluoma Uzuakoli, Bende, Ìpínlẹ̀ Abia , Nigeria
Iṣẹ́Òṣèrékùnrin
Ìgbà iṣẹ́Láti 2000 títí di àkókò yìí
Olólùfẹ́Nneoma Ikedieze

Chinedu Ikedieze, MFR[1][2] tí wọ́n bí ní Ọjọ́ Kejìlá oṣù Kejìlá ọdún 1977 (12 December 1977 ní ìlú Bende, ní ìpínlẹ̀ Abia, lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà jẹ́ gbajúmọ̀ òṣèré sinimá àgbéléwò ọmọ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà. Ó di gbajúmọ̀ nípa ipa tí ó máa ń kó pẹ̀lú Osita Iheme nínú àwọn sinimá àgbéléwò pàápàá jùlọ sinimá àgbéléwò kan tí àkọ́lé rẹ̀ ń jẹ́ Aki na Ukwa.[3]

Lọ́dún 2007, Ikedieze gba àmì ẹ̀yẹ ìdánilọ́lá Lifetime Achievement AwardAfrican Movie Academy Awards.[4]

Àtòjọ àwọn sinimá-àgbéléwò rẹ̀[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ọdún àkọ́lé ẹ̀dá-ìtàn àkíyèsí
2002 Spanner Spanner pẹ̀lú Nkem Owoh
Okwu na uka pẹ̀lú Osita Iheme àti Patience Ozokwor
Aka Gum pẹ̀lú Osita Iheme
2003 The Tom and Jerry pẹ̀lú Osita Iheme
The Catechist pẹ̀lú John Okafor
Show Bobo: The American Boys Kizzito pẹ̀lú Osita Iheme
School Dropouts pẹ̀lú Osita Iheme
Pipiro pẹ̀lú Osita Iheme
Onunaeyi: Seeds of Bondage pẹ̀lú Pete Edochie, Osita Iheme, Patience Ozokwor àti Clem Ohameze
Lagos Boys pẹ̀lú Osita Iheme
Family Crisis
Charge & Bail pẹ̀lú Osita Iheme
Back from America pẹ̀lú Rita Dominic
'am in Love pẹ̀lú Osita Iheme
Akpu-Nku
Aki na ukwa pẹ̀lú Osita Iheme
2 Rats pẹ̀lú Osita Iheme, Patience Ozokwor àti Amaechi Muonagor
2004 Spanner Goes to Jail pẹ̀lú Nkem Owoh
Not by Height pẹ̀lú Osita Iheme
Igbo Made
Big Daddies pẹ̀lú Osita Iheme
Across the Niger pẹ̀lú Pete Edochie, Kanayo O. Kanayo àti Ramsey Nouah
2005 Village Boys pẹ̀lú Osita Iheme
Spoiler pẹ̀lú Osita Iheme
Secret Adventure pẹ̀lú Osita Iheme
Reggae Boys pẹ̀lú Osita Iheme
One Good Turn pẹ̀lú Osita Iheme
I Think Twice pẹ̀lú Osita Iheme
Final World Cup pẹ̀lú Osita Iheme
Colours of Emotion Ebony pẹ̀lú Osita Iheme
2006 Young Masters pẹ̀lú Osita Iheme
Winning Your Love pẹ̀lú Osita Iheme àti Patience Ozokwor
'U' General pẹ̀lú Osita Iheme àti Patience Ozokwor
Sweet Money pẹ̀lú Osita Iheme
Royal Messengers pẹ̀lú Osita Iheme
Magic Cap pẹ̀lú Osita Iheme
Last Challenge pẹ̀lú Kanayo O. Kanayo àti Osita Iheme
Kadura pẹ̀lú Osita Iheme
Jadon pẹ̀lú Osita Iheme
Games Men Play pẹ̀lú Chioma Chukwuka, Kate Henshaw-Nuttal, Ini Edo, Mike Ezuruonye & Jim Iyke
Criminal Law Hippo with Osita Iheme
Brain Masters pẹ̀lú Osita Iheme
Brain Box pẹ̀lú Kanayo O. Kanayo àti Osita Iheme
Boys from Holland pẹ̀lú Osita Iheme
Blessed Son pẹ̀lú Osita Iheme
2007 Thunder Storm pẹ̀lú Osita Iheme
Stubborn Flies pẹ̀lú Osita Iheme
Spirit of a Prophet pẹ̀lú Osita Iheme ati Clem Ohameze
Powerful Civilian pẹ̀lú Osita Iheme
Power as of Old pẹ̀lú Osita Iheme àti Clem Ohameze
Escape to Destiny pẹ̀lú Osita Iheme
Cain & Abel pẹ̀lú Osita Iheme

Àwọn Ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Njoku, Ben (23 July 2010). "Stakeholders hail Aki's MFR award, plead for Paw-paw". The Vanguard (Lagos, Nigeria: Vanguard Media). http://www.vanguardepaper.com/2010/07/23/stakeholders-hail-aki%E2%80%99s-mfr-award-plead-for-paw-paw/. Retrieved 7 September 2010. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  2. "Aki Without Pawpaw". AllAfrica.com (AllAfrica Global Media). 6 August 2010. http://allafrica.com/stories/201008060225.html. Retrieved 5 September 2010. 
  3. Katende, Jude (27 January 2008). "Nigeria’s funny little men come to Kampala". New Vision (Kampala, Uganda: New Vision Printing & Publishing Company Limited). Archived from the original on 10 September 2012. https://web.archive.org/web/20120910063752/http://www.newvision.co.ug/D/9/34/608674. Retrieved 5 September 2010. 
  4. Coker, Onikepo (4 May 2007). "Africa Celebrates Film Industry at AMAA 2007". Mshale Newspaper (Minneapolis, USA: Mshale Communications). Archived from the original on 3 March 2012. https://web.archive.org/web/20120303204433/http://www.mshale.com/article.cfm?articleID=1407. Retrieved 5 September 2010.