City Hall, Lagos

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
City Hall, Lagos

Lagos City Hall tí a mọ̀ sí Gbọ̀gán ìlú Èkó di dídásílẹ̀ ní ọdún 1900.[1] Ó kalẹ̀ sí agbègbè àwọn ará Brazil, ní àárín èkò níbi tí ọrọ̀ ajé ti ń lọ. Ó wà ní ẹ̀gbẹ́ King's College, Lagos, St. Nicholas Hospital, Lagos àti Cathedral of the Holy Cross, Lagos. [2]

Gbọ̀ngán ìlú yìí jẹ́ olú ilé ìjọba ìbílẹ̀ tí àwọn àgbègbè míràn sì wà fún ìṣètò ìjọbaìjọba ìbílẹ̀ ti ìletò Èkó lẹ̀yìn tí orílẹ̀ èdè Nàìjíríà gba òmìnira. Gbọ̀ngán ìlú yìí ní àkọ́kọ́ ìjọba ìbílẹ̀ ní orílẹ̀ èdè Nàìjíríà tí ó sì jẹ́ olú ilé  ìjọba ìbílẹ̀ Gúúsù Èkó níbi tí ètò ìjọba ti bẹ̀rẹ̀ ní Nàìjíríà láti ọdún 1900. Gbọ̀ngán yìí jẹ́ ohun ìtàn, òṣèlú, tí ó sì ní ṣe pẹ̀lú àṣà Ìlú Èkó. [3][4]

Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]