Jump to content

DJ Cuppy

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
DJ Cuppy
Cuppy ní àjòdún Global Citizen: Power The Movement
Cuppy ní àjòdún Global Citizen: Power The Movement
Background information
Orúkọ àbísọFlorence Ifeoluwa Otedola.
Ọjọ́ìbí11 Oṣù Kọkànlá 1992 (1992-11-11) (ọmọ ọdún 32)
Lagos, Nigeria
Irú orinAfrobeats
Occupation(s)
InstrumentsMixer
Years active2013 dí lówólówó
LabelsRed Velvet Music Group
Websitehttp://djcuppy.com/

Florence Ifeoluwa Otedola (á bí ní ójó kókànlá Osù Kòkànlá ódún 1992), tí á mọ̀ ní ọ̀jọ̀gbọ̀n sí DJ Cuppy, tàbì Cuppy nìkán, ó jẹ́ disc jockey Nàíjíríà àtí ólùpílẹ́ṣẹ́. Ó jé ómọ́bínrín ónísòwò Nàíjíríà Femi Otedola. [1] Ó dágbà ní ìlù Èkò ó sí lọ́ sí Ìlù Lọndọn ní ọ́mọ́ ọ́dún kétàlà.

Ígbésí áyé ìbẹ̀rẹ̀ àtì ẹ̀kọ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Cuppy gbé ní Ilupeju fún ọ́dún mẹ́fà kí ó tó lọ́ sí Ikeja níbítí ó tí lọ́ sí Grange School, Ikeja . Lẹ́hìnnà ó tún pádà sí Ìlù Lọndọn fún àwọ́n GCSE rẹ̀ àtí àwọ́n ìpélé A. Ó párí ílé-ìwè gígà ní King's College London ní Óṣù Kéjé ọ́dún 2014, pẹ̀lú óyè nínù íṣòwò àtí ètò-ọ́rọ̀ ájé. Ó tún gbá ìwè èrí gígá sí ní ìṣòwò órín látí Yúnífásítì New York ní ọ́dún 2015. Cuppy kọ́ ẹ̀kọ́ fún ìwè èrì gígà sí ní àwọ́n ẹ̀kọ́ Áfíríká ní Yúnífásítì tí Oxford, ó wólé ní 2021 [2] ó sì párì nì 2022.

Ìṣẹ́-ṣíṣé

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní 2014 Cuppy nì DJ ólùgbè ní MTV Africa Music Awards ní Durban . Lẹ́hìnnà ó ṣéré ní Tatler àtí Christie's Art Ball ní Ìlù Lọndọn, àtì ní Ìpàdè Ìgbàdùn Financial Times Business ni Ílù Mexico .

Ní Óṣù Kéjé ọ́dún 2014, ó sé àgbékálè House of Cuppy sílẹ̀ gẹ́gẹ́bì ákójọ̀pọ̀ àkòpò àkọ̀kọ̀ rẹ̀ ní Ìlù Lọndọn àtí Èkò, ṣáájú ṣíṣé ìfìlọ́lẹ̀ rè ní Ìlù New York ní ọjọ́ kéjì Óṣù Kẹ́san ọ́dún 2014. Pèlú House of Cuppy, ó ṣé àgbéjádè àwọ́n àtúnṣè EDM-esque ti àwọ́n orín nípásẹ̀ àwọ́n òṣèrè afropop tí wón táyo.

Ní ọ́dún kánnà, Cuppy tún ṣe ifílọ́lẹ̀ ìṣákósó órín tí ó wá ní Ìlù Lọndọn àtí ìṣòwò íṣélọ́pọ̀ akóònù, Red Velvet Music Group.

Ní Óṣù Kíní ọ́dún 2015, Cuppy jé ìfìhàn lórí òjú tí ìwè ìròhìn Life Guardian . Ójú ìwè náà jé áyẹ́yẹ́ ìrán túntún tí àwọ́n óbìnrìn Áfíríká. Ní Óṣù Kẹ̀tá Odún 2015, Cuppy ni òsìsè DJ fún 2015 Oil Barons Charity ni Dubai, ó sí jé òlórín Áfríkà akọkọ lati kórín ní íbí áyéyé náà. O jẹ́ àfíhán ní 2015 ósù Kẹ́rìn / ósù kárúùn atejade ti Forbes Woman Africa . [3] [4]

Ni Oṣu Kárúùn ọ́dún 2015, Cuppy gbé House Cuppy II kálè.

Ní Òṣù Kẹ́jọ̀ ọ́dún 2015, Cuppy ṣétò sí ìr̀in-àjò DJ ákọ́kọ́ rẹ́ sí àwọ́n órílé-édè méjò ni Afirika, tí àkólé rè jé “Cuppy Takes Africa”. Ó ṣàbẹ̀wò sí Náìjíríà, Senegal, Ghana, Kenya, Tanzania, Rwanda, Uganda ati South Africa . Irin-ajo "Cuppy Takes Africa" pẹ̀lú àwọ́n ìṣẹ́ ṣíṣé, àwọ́n ìfówósòwòpó ólórín pàtàkì, àtí àwọ́n ìṣẹ́-ọ̀fẹ́ tí ó nì àtìlẹ́yín GTB Bank ati Dangote Foundation . Léyín ígbá díè ní ódún kánnà, ó dáwón láràyà ni Jay-Z 's Roc Nation . [5]

Ní Óṣù Kẹ́wà Ọ́dún 2016, ìrìn-àjò “Cuppy Takes Africa” sé àfíhàn lòrí Fox Life Africa gẹgẹbi jara iwe-ipinlẹ Ní ódún 2016, Cuppy jẹ́ òlúgbé DJ fun Uncommon Sense MTV2 pèlú Charlamagne Tha God .

Ó ṣé áwọ́n órín méjì, "Vibe" ati "The way I am", èyítí ó jé àfíhàn lori "Afrobeats" EP nípàsẹ̀ Young Paris èyìtì ó gbé jádè ni òjó kérìn-lé-lógún ósù kétá ódún 2017. [6]

Ní ọ́jọ́ kétàláà Óṣù Kẹ́wà Ọ́dún 2017, ó sé ágbékálè "Green Light”, ísé órín éléyókán àkókó rẹ̀. Órín náà sé áfíhán óhùn nlá ólórín àtí ólùpịlèsè Tekno látì Náijíríà.

Ní ọ̀jọ́ ógbòn óṣù Kẹ́tá ọ́dún 2018, ó gbe\ “Vybe” silẹ, Ìsé órín éléyókaln ékéjì rẹ. Órín náà sé áfíhàn óhuln nlá látì Ghana Sarkodie.

Ní òjó kérìn-lé-lógún Óṣù Kẹ̀jọ̀ ọ̀dún 2018, ó gbé Currency sítá, Ìsé órín éléyókaln kẹ́tá rẹ̀ tí ó sé àfíhàn LAX.

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "DJ Cuppy congratulates dad on sale of Forte Oil, asks what is next for him" (in en). Legit.ng. 21 June 2019. https://www.legit.ng/1244742-dj-cuppy-congratulates-dad-on-sale-of-forte-oil-wonders.html. 
  2. Olonilua, Ademola (18 October 2021) DJ Cuppy celebrates matriculation into Oxford University. The Punch. Retrieved October 18, 2021.
  3. Empty citation (help) 
  4. Empty citation (help) 
  5. Empty citation (help) 
  6. Empty citation (help)