Jump to content

Ibukun Awosika

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Ibukun Oluwa Abiodun Awosika)
Ibukun Awosika
Ọjọ́ìbíBilkisu Abiodun Motunrayo Omobolanle Adekola
24 Oṣù Kejìlá 1962 (1962-12-24) (ọmọ ọdún 62)
Ibadan, Oyo State, Nigeria
Orílẹ̀-èdèNigerian
Orúkọ mírànBlessing Ibukun Awosika
Iléẹ̀kọ́ gíga
Iṣẹ́
Ìgbà iṣẹ́1989–present
EmployerFirst Bank of Nigeria
OrganizationSOKOA Chair Centre Limited
TelevisionBusiness – His Way
Board member ofWomen in Management, Business and Public Service
Websiteibukunawosika.org

Ibukunoluwa Abiodun Awosika (tí wọ́n bí ní Bilkisu Abiodun Motunrayo Omobolanle Adekola ní 24, oṣù kọkànlá 1962) jẹ́ obìnrin oníṣòwò Nàìjíríà, abáni-sọ̀rọ̀-ìyànjú àti òǹkọ̀wé. Ó jẹ alága tẹ́lẹ̀rí First Bank of Nigeria.[1]

Ìbẹ̀rẹ̀ ìgbésí-ayé àti Ẹ̀kọ́

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Wọ́n bí i gẹ́gẹ́ bí i ọmọ kẹta nínú ọmọ méje ní Ìbàdàn, olú-ìlú Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́, Ibukun parí ẹ̀kọ́ alákọ̀ọ́bẹ̀rẹ̀ àti ẹ̀kọ́ gíga ní St. Paul's African Church Primary School, Èkó àti Methodist Girls' High School, Yábàá láfarabara kí ó tó tẹ̀síwájú sí Yunifásítì Ifẹ̀(tí a mọ̀ ní báyìí sí Yunifásítì Obafemi Awolowo) níbi tí ó ti kẹ́kọ̀ọ́ jáde pẹ̀lú BSc nínú Chemistry bí ó tilẹ̀ jẹ́ pé Architecture ni ó ti fẹ́ kọ́kọ́ kẹ́kọ̀ọ́ nípa rẹ̀ láti ìbẹ̀rẹ̀, ó sì tún ṣe àwọn kọ́ọ̀sì tí ó yàn nínú Accounting.[2][3] Ó ní àwọn ìwé ẹ̀rí post graduate àti MBA lẹ́yìn tí ó parí ọ̀pọ̀lọpọ̀ àwọn ẹ̀kọ́ ìdókòwò ní Lagos Business School àti IESE Business SchoolUniversity of Navarra.[4]

  1. Ogwu, Michael (September 11, 2015). "As Ibukun Awosika scores another first for women in Nigeria". Daily Trust Nigeria. http://www.dailytrust.com.ng/news/women-enterpreneurs/as-ibukun-awosika-scores-another-first-for-women-in-nigeria/110327.html. 
  2. Ajagu, Ausbeth (2005). The Entrepreneur. Betcy Media. ISBN 978-978-067-168-6. https://books.google.com/books?id=bJLCAAAAIAAJ. 
  3. Woman.NG (April 5, 2015). ""Nobody Realized That We Were A Tiny, Little Dot" - Ibukun Awosika On How She Used The Little She Had To Build The Successful Business She Wanted". Woman.NG (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2021-04-30. Retrieved 2021-04-30. 
  4. "Ibukun Awosika –Entrepreneur Par Excellence". FinIntell. Archived from the original on October 20, 2020. Retrieved March 2, 2016. 

Nígbà tí ó ń ṣe ó-pọn-dandan ọdún-kan National Youth Service Corps ìsìnlú (NYSC) ní ìpínlẹ̀ Kano, Ìbùkún Awóṣìkà ṣiṣẹ́ gẹ́gẹ́ bí i akọ́ṣẹ́ auditAkintola Williams & Co tí ó padà di Deloitte, ṣùgbọ́n padà sílé lẹ́yìn ìsìnlú náà, ó sì dára pọ̀ mọ́ Alibert Nigeria Ltd., ilé-iṣẹ́ furniture, gẹ́gẹ́ bí i aṣàkóso yàrá-ìfihàn.[1][2] Nínú ìlépa rẹ̀ láti dá dúró, ó dá ilé-iṣẹ́ tí í ṣẹ̀dá furniture tí ó pè ní Quebees Limited[3] ní 1989 kí ó tó yí padà sí The Chair Centre Limited àti SOKOA Chair Centre Limited lẹ́yìn náà lẹ́yìn àpapọ̀ ìdókòwò pẹ̀lú SOKOA S.A[4] àti Guaranty Trust Bank in 2004.[5]

Ó jẹ́ ọ̀kan lára African Leadership Initiative àti Aspen Global Leadership Network, Ibukun Awosika jẹ́ ọmọ ẹgbẹ́ Nigerian Economic Summit Group, ọ̀kan lára àjọ Nigerian Sovereign Wealth Fund àti alága tẹ́lẹ̀rí, àjọ olùtọ́jú ohun ìní Women in Management, Business and Public Service.[6][7] Ní 2011, ó pẹ̀lú ẹlòmíràn dá Afterschool Graduate Development Centre, ibi iṣẹ́ tí wọ́n dá sílẹ̀ láti bójútó iye àìríṣẹ́ṣe tí ó ga ní Nàìjíríà.[5]

Ní oṣù kẹsàn-án, 2015, Ibukun di obìnrin àkókọ́ tí wọ́n máa yàn gẹ́gẹ́ bí i alága First Bank of Nigeria lẹ́yìn ìkọ̀wéfiṣẹ́lẹ̀ Ọmọọba Prince Ajibola Afonja.[6][8]

Ibukun Awosika jẹ́ ọ̀kan lára IESE's International Advisory Board (IAB).[9] Ó tún ń jókòó lórí àjọ Digital Jewel Limited àti Cadbury Nig Plc.[10]

Ẹ̀rọ amóhùn-máwòrán

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ní 2008, Ibukun Awosika jẹ́ ọ̀kan lára àwọn olókòwò Nàìjíríà tí wọ́n farahàn nínú ẹ̀dà Dragon's Den Áfíríkà àkọ́kọ́. Ó tún máa ń ṣe olùgbàlejò ètò orí ẹ̀rọ amóhùn-máwòrán tí wọ́n pè ní Business His Way. Ó tún ṣeré nínú Citation 2020 pẹ̀lúTemi OtedolaKunle Afolayan gbé jáde.[11]

  • The "Girl" Entrepreneurs[12]
  • Business His Way[13]
  • The 'Girl' Entrepreneurs: Our Stories So Far Kindle Edition[14]

Àmì-ẹ̀yẹ àti ìdánimọ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Year Award ceremony Prize Result
2005 THISDAY Newspaper Annual Merit Award style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
Success Digests Magazine's Annual Enterprise Award style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
2006 Financial Standard and Pan-African Organisation for Women Recognition style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
FATE Foundation Awards FATE Model Entrepreneur Award of the Year Gbàá
2007 International Women Society Award Golden Heart Award Gbàá
2008 International Women Entrepreneurial Challenge Award Gbàá
2015 style="background: #FDD; color: black; vertical-align: middle; text-align: center; " class="no table-no2"|Wọ́n pèé
2020 Africa Forbes Woman Awards 2020 Forbes Woman Africa Chairperson Award Gbàá

Ibukun Awosika fẹ́ Abiodun Awosika, ẹni tí òun pẹ̀lú rẹ̀ ní ọmọ mẹ́ta.

  1. "I live on the plane – Ibukun Awosika". The Punch Newspaper. March 13, 2016. http://punchng.com/i-live-on-the-plane-ibukun-awosika/. 
  2. ""Nobody Realized That We Were A Tiny, Little Dot" – Ibukun Awosika On How She Used The Little She Had To Build The Successful Business She Wanted". Woman.NG. April 5, 2015. Archived from the original on March 7, 2016. https://web.archive.org/web/20160307123452/http://woman.ng/2015/04/nobody-realized-that-we-were-a-tiny-little-dot-ibukun-awosika-on-how-she-used-the-little-she-had-to-build-the-successful-business-she-wanted/. 
  3. "Ibukun Awosika olùdásílẹ̀ àti aláṣẹ Chair Centre Group àti alága, First Bank of Nigeria àti Imperial Gate School, Lekki". enterprise network. March 21, 2019. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]Àdàkọ:Cbignore
  4. "I live on the plane – Ibukun Awosika". Punch. March 13, 2016. https://punchng.com/i-live-on-the-plane-ibukun-awosika/. 
  5. 5.0 5.1 Anugwara, Boldwin (July 4, 2013). "Ibukun Awosika: Imparting youths for employment". Newswatch Times. Archived from the original on March 6, 2016. https://web.archive.org/web/20160306042401/http://www.mynewswatchtimesng.com/ibukun-awosika-imparting-youths-for-employment/. 
  6. 6.0 6.1 Sotubo, Jola (September 10, 2015). "Ibukun Awosika: 3 reasons why her appointment as First Bank Chair is epic". Pulse Nigeria. Archived from the original on March 7, 2016. https://web.archive.org/web/20160307142601/http://pulse.ng/business/ibukun-awosika-3-reasons-why-her-appointment-as-first-bank-chair-is-epic-id4154597.html. 
  7. "» Ibukun Awosika". test.firstbanknigeria.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Archived from the original on 2017-12-31. Retrieved 2017-12-30.  Unknown parameter |url-status= ignored (help)
  8. Olapoju, Kolapo (September 7, 2015). "Ibukun Awosika becomes the first female chairman of First Bank". YNaija. http://ynaija.com/ibukun-awosika-first-bank-female-chairman/. 
  9. Members of IESE's International Advisory Board, iese.edu
  10. "I live on the plane – Ibukun Awosika" (in en-US). Punch Newspapers. https://punchng.com/i-live-on-the-plane-ibukun-awosika/. 
  11. Okafor, Lovelyn (September 9, 2015). "Ibukun Awosika- The New Face of First Bank of Nigeria Holdings (FBNH)". Konnect Africa. Retrieved March 2, 2016. 
  12. "Amazon.com : ibukun awosika". www.amazon.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-05-20. 
  13. "Amazon.com : ibukun awosika". www.amazon.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-05-20. 
  14. "Amazon.com : ibukun awosika". www.amazon.com (in Èdè Gẹ̀ẹ́sì). Retrieved 2021-05-20. 

Àwọn Ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]