Jump to content

Oùnjẹ Wíwá Yorùbá

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

Oùnjẹ wíwá Yorùbá jẹ oúnjẹ ti o pọju ti ó sì ní onírúurú tí i ṣe ti àwọn eniyan ilẹ̀ Yorùbá(àwọn agbègbè Yorùbá ní Nigeria). Lára àwọn oúnjẹ ìlúmọ̀ọ́ká Yorùbá nì wọ̀n yìí; Ọ̀fadà, Àsáró, Moin moin, Ọbẹ̀ Ẹ̀gúsí , Àbùlà, Àkàrà, Ilá Alásèpọ̀, Ẹ̀fọ́ rírò pẹ̀lú Òkèlè, abbl.

Àsáró
Mọ́í-mọ́í
Ọbẹ̀ Ẹ̀gúsí
Ìrẹsì Ọ̀fadà
Diẹ ninu awọn Díẹ̀ nínú àwọn oúnjẹ Yorùbá mìíràn ló wà nísàlẹ̀ yìí:

Díẹ̀ nínù àwọn oúnjẹ Yorùbá:

  • 1. Àkàrà
  • 2. Àsun
  • 3. Ọ̀fadà
  • 4. Àbùlà
  • 5. Àsáró
  • 6. Èkuru/Ofúlójú
  • 7. Ekusu/Ṣapala
  • 8. Ẹ̀fọ́ rírò
  • 9. Bọ̀ọ̀lì
  • 10. Gízídòdò
  • 11. Ìkọ́kọrẹ́/Ìfọ́kọrẹ́
  • 12. Àdàlù
  • 13. Mọ́í-mọ́í/Ọ̀lẹ̀lẹ̀
  • 14. Ìrẹsì Ẹyin
  • 15 . Ìrẹsì àti ọbẹ̀ ata díndín
  • 16. Ayamase
  • 17. Ẹ̀wàgọ̀yìn
  • 18. Ewédú
  • 19. Ṣọkọ
  • 20. Òkèlè (Iyán, Ẹ̀bà, Láfún, Àmàlà/Ọkà, Fùfú, Púpúrúetc.)
  • 21. Ilà alásèpọ̀
  • 22. Dòdò-Ìkirè
  • 23 Ègbo àti Ẹ̀wà
  • 24. Gúre ọlọ́bọ̀rọ́
  • 25. Kókóró
  • 26. Gúgúrú àti ẹ̀pà
  • 27. Àádùn
  • 28. Mósò
  • 29. Jọ̀lọ́
  • 30. Ẹ̀gúsí
  • 31. Ìpékeré
  • 32. Dùn Dún Oníyẹ̀rì
  • 33. Wàrà
  • 34. Ẹ̀fọ́ Tẹ̀tẹ̀
  • 35. Sisí pẹlẹbẹ
  • 36. Ìrẹsì díndín)
  • 37. Bàbá dúdú
  • 38. Ọbẹ̀ irú
  • 39. Dòdò
  • 40. Ẹ̀kọ
  • 41. Ògì
  • 42. Àpọ̀n
  • 43. Ẹ̀gúsí Ìjẹ̀bú
  • 44. Gurundi
  • 45. Búrẹ́dì Agége
  • 46. Ìrẹsì alágbọn
  • 47. Gúre
  • 48. Ọbẹ̀ ẹja díndín
  • 49. Márúgbó àti púpùrú
  • 50. Èbìrìpò
  • 51. Iṣu àti ẹyin
  • 52. Dùndún
  • 53. Ọbẹ̀ ata Búkà
  • 54. Sùpàgẹ́tì oní jọ̀lọ́fù
  • 55. Àgbàdo sísun
  • 56. Ìgbín díndín
  • 57. Zóbò
  • 58. Ògi bàbà
  • 59. Gbẹ̀gìrì
  • 60. Róbó
  • 61. Ẹmu
  • 62. Ilá àti ọbẹ̀ díndín
  • 63. Gàrrí
  • 64. Ọ̀gbọ̀lọ̀/oro
  • 65. Iṣu àti ọbẹ̀ díndín
  • 66. Amẹ́yidùn
  • 67. pọfu pọfu
  • 68. Ṣápùmáànì
  • 69. Bọ́ùnsì
  • 70. Àgbàdo àti àgbọn
  • 71. Ẹyin Awó
  • 72. Mọ́ímoí elépo
  • 73. Àkàrà elépo
  • 74. Iṣu sísun
  • 75. Àkàrà Ẹ̀gùdí
  • 76. Ọkà bàbà
  • 77. Tìnkó
  • 78. Esunsun
  • 79. Èékánná Gowon
  • 80. Ewédú Ẹ̀lẹ́gúsí
  • 81. Ẹ̀wà Pakure
  • 82. Ẹ̀fọ́ Ẹlẹ́gúsí
  • 83. Báléwá
  • 84. Búgan
  • 85. Alàpà / Jogi
  • 86. Ìṣápá
  • 87. Kundi
  • 88. Ọ̀jọ̀jọ̀
  • 89. Bẹ́síkẹ́ / Wàrà
  • 90. Àbàrí
  • 91. Páfun
  • 92. Ilá àti ọbẹ̀ ata
  • 93. Pọfu pọfu
  • 94. Ìgbín pẹ̀lú Ọbẹ̀ ata
  • 95. Ànọ̀mọ́/Ọ̀dùnkún
  • 96. Obẹ̀ Ọ̀fadà
  • 97. Ọbẹ̀ Adìyẹ
  • 98. Ìlasà
  • 99. Àkàrà Kèngbè
  • 98. Àkàrà Kókò
  • 99. súrú
  • 100. Ẹ̀kọ Eléwé
  • 101. Jálókè/jáálòkè
  • 102. Lápata / Ìpékeré
  • 103. Ọbẹ̀ ilá funfun
  • 104. Àbùlà
  • 105. Luru
  • 106. Ọ̀runlá
  • 107. Ìmóóyò
  • 108. Ẹ̀fọ́( Ṣọkọ, gbagba, Ebòlò, Yanrin, Odu, Wọ́rọ́wọ́, Tẹ̀tẹ̀, Gúre, Ajẹ́fáwo, Ìyànà-Ìpájà)
  • 109. Mọ́í Mọ́í Ẹlẹ́mí Méjì
  • 110. Yọyọ
  • 111. Ọbẹ̀ Ẹyin

Oùnjẹ Yorùbá tí wọ́n n sè ní ọ̀nà Yorùbá pẹ̀lú èròjà àjèjì. Èyí yàtọ̀ sí oúnjẹ àjèjì tí a rí ní ẹkùn ilẹ̀ Yorùbá tí a ṣe gẹ́gẹ́ bí ó ti rí ní àwọn ilẹ̀ ìbílẹ̀ rẹ̀.

Àṣà Yorùbá:

  • Àwọn ègé kékeré (Samosa ati àwọn èyí tí a lọ́ ní ìlànà Yorùbá)
  • Ẹran páíì/ Mínsí páíì
  • Yípo ẹyin
  • Sàmósà
  • Dónọ́ọ́tì
  • Sọ́séji roolù
  • Fíṣí ròòlù
  • Fíṣí páíì
  • Róólù
  • páíì aládìyẹ
  • Ṣàwámà
  • Ẹyin onísúkọ́ọ́ṣì
  • Àwọn pásítírísì àti àwọn àkàrà òyìnbó lóríṣiríṣi
  • Sàláádì + Cósílọ̀
  • Núdusù díndín
  • Sùpàgẹ́tì díndín

Oúnjẹ òwúrọ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]