Ọbàtálá
Ìrísí
(Àtúnjúwe láti Obatala)
Obatala jẹ́ ọ̀kan lára àwọn òrìṣà ilẹ̀ Yorùbá tí àwọn Yorùbá gbàgbọ́ pé ó ní agbára láti dá ayé àmọ́ tí kò ri ṣe nítorí ó mu ẹmu yó, tí àbúrò rẹ̀, ìyẹnOduduwa wá padà ṣe. Lẹ́yìn náà ni wọ́n wá fún un ní iṣẹ́ láti máa dá ènìyàn. Bàbá rè, tí í ṣe Olódùmarè ló gbé iṣẹ́ yìí lé e lọ́wọ́, tí orúkọ rẹ̀ wá fi di Ọbàtálá, amọrí.[1]
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Probst, Peter (2011). Osogbo and the Art of Heritage. Bloomington: Indiana University Press. p. 17. ISBN 978-0-253-22295-4.