Susan Peter's (Òṣèrébìnrin ọmọ Nàìjíríà)
Susan Peters | |
---|---|
Susan Peters lọ́dún 2011 | |
Ọjọ́ìbí | 30 May 1980 Ado, Ìpínlẹ̀ Benue, Nàìjíríà | (ọmọ ọdún 44)
Ọmọ orílẹ̀-èdè | Nàìjíríà |
Iṣẹ́ | òṣèrébìnrin |
Website | realsusanpeters.com |
Susan Peters tí wọ́n bí lọ́gbọ̀n ọjọ́ oṣù karùn-ún ọdún 1989 (30 May 1980) jẹ́ gbajúmọ̀ Òṣèrébìnrin ọmọ Nàìjíríà tí ó ti gba ọ̀pọ̀lọpọ̀ àmìn-ẹ̀yẹ tí ó ju àádọ́ta lọ.[1] Ó jẹ́ gbajúmọ̀ atọ́kùn orí tẹlifíṣàn, afoge-ṣojú, atúnnúleṣe àti aṣerunlóge.[2] Láìpẹ́ yìí, ó gbàmìn ẹ̀yẹ Òṣèrébìnrin tó dára jù lọ nínú sinimá àgbéléwò lédè òyìnbó, 2011 Afro Hollywood Best Actress (English) Award fún ipa tó kó nínú sinimá tí àkọlé rẹ̀ ń jẹ́ Bursting Out, àmìn-ẹ̀yẹ [3] NAFCA Archived 2014-06-16 at the Wayback Machine. fún Òṣèré (Nollywood ati African Film Critics Awards) North Carolina Nigerian Oscars: Best Actress in Supporting Role 2011[4] àmìn ẹ̀yẹ BON Archived 2012-01-20 at the Wayback Machine. (amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ Òṣèrébìnrin tó dára jù lọ lọ́dún 2011,[5] bẹ́ẹ̀ ló tún gbàmìn ẹ̀yẹ Òṣèrébìnrin tó dára jù lọ fún ọdún 2010, àti Òṣèrébìnrin tí fáàrí rẹ̀ dáńtọ́ jùlọ lọ́dún 2012 láti ọwọ́ City People Magazine Archived 2020-07-29 at the Wayback Machine..[6] Lọ́dún 2011, wọ́n yàn án fún àwòrán ìbẹ̀rẹ̀ tí ìwé-ìròyìn olóṣoooṣù àṣà àti ìṣé tí oṣù Kejìlá. Zen Archived 2012-01-05 at the Wayback Machine..[7] Olóòtú Said Zen Magazine, Ọ̀gbẹ́ni Arinze Nwokolo, júwe báyìí "... Susan Peters jẹ́ Òṣèrébìnrin tó lẹ́bùn àrà ọ̀tọ̀, tí ó sìn máa ń tẹpá mọ́ iṣẹ́ tó yàn láàyò dáadáa..." [8]
Àṣàyàn àwọn àmìn-ẹ̀yẹ tó gba
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Àmìn-ẹ̀yẹ City People: Òṣèré tó dára jù lọ lọ́dún 2010
- Àmìn-ẹ̀yẹ NAFCA (Nollywood and African Film Critics Awards) àríwá Carolina
- Àmìn-ẹ̀yẹ Nigerian Oscars: Amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹ̀dá ìtàn tó dára jù lọ fún ọdún 2011
- Àmìn-ẹ̀yẹ Afro-Hollywood Awards, UK: 16th African Film Awards 2011, Òṣèrébìnrin tó dára jù lọ nínú sinimá àgbéléwò èdè òyìnbó fún ipa tó kó nínú eré Bursting Out[9]
- Àmìn-ẹ̀yẹ Best of Nollywood 2011: Amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹ̀dá ìtàn tó dára jù lọ nínú Bursting Out
- Àmìn-ẹ̀yẹ DIVA 2011: fún idagbasoke ilé iṣẹ́ sinimá àgbéléwò
- Àmìn-ẹ̀yẹ City People Magazine Beauty and Fashion 2012: Òṣèrébìnrin tí fáàrí rẹ̀ dára jù
- Àmìn-ẹ̀yẹ Golden Icons Academy Movie Award (GIAMA) 2012, Houston, USA: Amúgbálẹ́gbẹ̀ẹ́ ẹ̀dá ìtàn tó dára jù lọ
Àtẹ àṣàyàn àwọn sinimá àgbéléwò rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọdún | Àkọlé | Ipa | Olùdarí | Àwọn Òṣèré mìíràn |
---|---|---|---|---|
2002 | Wasted Effort | Masie Ayoade | Andy Amanechi | Ramsey Nouah, Rita Dominic, Muna Obiekwe |
2002 | The Hammer | Izu Ojukwu | ||
2002 | Songs of Sorrow | Kabat Esosa Egbon | Tunde Alabi, Ini Edo, Pat Attah, Maureen Solomon, Muna Obiekwe | |
2002 | 11 days, 11 Nights | Kabat Esosa Egbon | Pat Attah, Dakore Egbuson, Yemi Blaq | |
2003 | Squad 23 | Tarila Thompson | Saint Obi, Liz Benson, Enebeli Elebuwa, Gentle Jack, Ejike Asiegbu | |
2003 | State of Emergency 2 | Teco Benson | Ejike Asiegbu, Bimbo Manuel and Saint Obi | |
2003 | The Begotten | E. O'Squires Ogbonnaya | Ini Edo, Rita Dominic, Ngozi Ezeonu | |
2003 | The President Must Not Die | Zeb Ejiroz | Ufuoma Ejenobor | |
2004 | Stolen Bible | Emeka Nwabueze | Emeka Ani, Kate Henshaw-Nuttal, Benedict Johnson, Chinyere Nwabueze | |
2004 | War Front 2 | Teco Benson | Festus Aguebor, Sam Dede, Steve Eboh, Enebeli Elebuwa | |
2004 | Saving the Crown | Lancelot O. Imasuen | Patience Ozokwor, Jim Iyke, Festus Aguebor, Emmanuel Francis | |
2004 | Wild Wind | |||
2004 | Second Adam | Theodore Anyanji | Chioma Chukwuka, Eucharia Anunobi and Mike Ezuruonye | |
2005 | Life is Beautiful | Pete Edochie, Stephanie Okereke | ||
2005 | Immoral Act | Obi Okor | Kanayo O Kanayo, Moses Armstrong | |
2005 | 30 Days | Mildred Okwo | Genevieve Nnaji, Joke Silva, Segun Arinze | |
2005 | Moment of Truth | Lancelot Oduwa Imasuen | Chioma Chukwuka, Mike Ezuruonye and Benedict Johnson | |
2006 | Behind the Plot | Nonso Emekaekwue, Ikechukwu Onyeka | Desmond Elliot, Benedict Johnson and Stephanie Okereke | |
2006 | Young Masters | Ikechukwu Onyeka | Osita Iheme, Chinedu Ikedieze and Benedict Johnson | |
2006 | Ghetto Language | Sunny Okwori | Kelvin Books, Ini Edo and Desmond Elliot | |
2006 | Good Mother | Amayo Uzo Philips | Stephen Ahanaonu, Ifeanyi Egbulie and Osita Iheme | |
2006 | Nollywood Hustlers | Pauline | Moses Inwang | Uche Jombo, Charles Inojie, Monalisa Chinda, Ramsey Nouah, Ejike Asiegbu |
2009 | Timeless Passion | Desmond Elliot | Desmond Elliot, Ramsey Nouah, Uche Jombo, Mona Lisa Chinda | |
2009 | Bursting Out | Ibiere | Desmond Elliot, Daniel Ademinokan | Genevieve Nnaji, Majid Michel, Desmond Elliot, Omoni Oboli |
2010 | Catwalk Series (TV) | Frank Rajah Arase | Monalisa Chinda, Uru Eke, Memory Savanhu, | |
2010 | Black Heat | Tricia Esiegbe | ||
2011 | The Ransom | Aquila Njamah | Patience Ozorkwor, Funke Akindele, Jerry Amilo, Victor Esezobor | |
2011 | Love Entrapped | Wendy and Desmond Elliot | ||
2014 | Champagne | Emem Isong | Majid Michel, Alexx Ekubo, Tana Adelana | |
2017 | Celebrity Marriage | Pascal Amanda | Toyin Abraham, Odunlade Adekola, Tonto Dikeh, Jackie Appiah, Kanayo O. Kanayo |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Interview in Daily Sun, posted at naijarules, August 24, 2010 http://www.naijarules.com/vb/nollywood-movie-stars/38252-acting-nude-not-part-my-culture-nollywood-actress-susan-peters.html Archived 2012-09-04 at Archive.is
- ↑ E4PR Celebrity Management http://www.e4pr.com/about-e4-pr/susan-peters
- ↑ Nigeria Films, 11 October 2011 http://www.nigeriafilms.com/news/14027/17/halima-abubakarsusan-peterssaheed-balogun-win-afro.html
- ↑ Modern Ghana, September 24, 2011 http://www.modernghana.com/movie/14821/3/tears-of-joy-as-susan-peters-wins-nafca-awards.html
- ↑ Bola Aduwo in Golden Icons http://www.goldenicons.com/2011/11/14/best-of-nollywood-awards/ Archived 2012-01-19 at the Wayback Machine.
- ↑ Nigeria Films, December 21st 2011 http://nigeriafilms.com/news/15086/26/celebrity-quote-actress-susan-peters.html
- ↑ Bola Aduwo, 3 December 2011 http://www.nollywooduncut.com/hot-nollywood-news/925-susan-peters-covers-zen-magazine Archived 2012-01-05 at the Wayback Machine.
- ↑ Zen Magazine Facebook page December 2011 http://www.facebook.com/media/set/?set=a.318642784814821.86338.130777576934677&type=3
- ↑ Nigeria Films, October 11, 2011 http://www.nigeriafilms.com/news/14027/17/halima-abubakarsusan-peterssaheed-balogun-win-afro.html