Jump to content

Chief Daddy (Fíìmù Nàìjíríà)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́

 

Chief Daddy
Fáìlì:Chief Daddy Poster.jpg
AdaríNiyi Akinmolayan
Olùgbékalẹ̀Temidayo Abudu
Àwọn òṣèré
Ìyàwòrán sinimáMuhammad Atta Ahmed
OlóòtúVictoria Akujobi
Ilé-iṣẹ́ fíìmùEbonyLife Films
OlùpínEbonyLife Films
FilmOne Distributions
Déètì àgbéjáde
  • 14 Oṣù Kejìlá 2018 (2018-12-14)
Àkókò99 minutes
Orílẹ̀-èdèNigeria
ÈdèEnglish
Yoruba
Owó àrígbàwọléN387.5 million [1]

Chief Daddy jẹ́ fíìmù apanilẹ́rìn-ín ti orílẹ̀-èdè Nàìjíríàtó jáde ní ọdún 2018, tí olùdarí rẹ̀ sì jẹ́ Niyi Akinmolayan, tí Bode Asianbi sì ṣe àkọsílẹ̀ rẹ̀, tí Mosunmola Abudu àti Temidayo Abudu sì ṣàgbéjáde, ní oṣù kejìlá, ọdún 2018.[2][3] Ọ̀pọ̀ àwọn ògbóǹtarìgì òṣèré bí i Funke Akindele Bello, Kate Henshaw, Nkem Owoh, Joke Silva, Patience Ozokwor, Richard Mofe Damijo àti Racheal Oniga ló kópa nínú rẹ̀.[4][5]

Chief Daddy dá lórí ìtàn olóyè kan, tó lówó, tó lọ́là, tó sì ní ọ̀pọ̀ ilé-iṣẹ́, tó tún máa ń fi owó rẹ̀ ṣàánú fún ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìdílé, àwọn òṣìṣẹ́ rẹ̀ àti àwọn ìyáwó rè. Sàdédé ló kú tí ikú rẹ̀ sì fa wàhálà fún ìdílé rẹ̀.[6]

Ìṣàfihàn àti àgbéjáde

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Chief Daddy jáde ní orílẹ̀-èdè Nàìjíríà, ní oṣù kejìlá ọdún 2018, àti ní Netherlands ní oṣù kẹta ọdún 2019, tipasẹ̀ Netflix.[7][8] Wọ́n ṣàfihàn àkọ́kọ́ fún fíìmù náà níí Oriental Hotel, ní ìlú Eko, pẹ̀lú àọn ògbóǹtarìgì òṣèré bí i Olu Jacobs, Joke Silva àti Richard Mofe Damijo.[9][10]

Ìgbóríyìn fún ilé-iṣé àti àwọn olùpín

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Ebony Life Films ní ó ṣá̀gbéjáde fíìmù yìí, tí Film One Entertainment sì pin káàkiri ní Nàìjíríà àti ní Netherlands.[11]

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Top 20 WA Films of 2019". Retrieved 7 January 2020. 
  2. "Chief Daddy - EbonyLife Films". Ebonylifefilms.com. Archived from the original on 4 November 2021. Retrieved 20 May 2019. 
  3. "Chief Daddy - Netflix". Netflix.com. Retrieved 20 May 2019. 
  4. "Brace Yourselves! "Chief Daddy" Is Coming To Netflix". Guardian.ng. 4 March 2019. Archived from the original on 17 May 2019. Retrieved 20 May 2019. 
  5. "Chief Daddy full movie cast (2018 Nigerian film)". YouTube. 10 December 2018. Retrieved 20 May 2019. 
  6. "Chief Daddy could have been so much more but at least it will make you laugh a little". Pulse.ng. 10 December 2018. Retrieved 20 May 2019. 
  7. "Chief Daddy grosses N115.7 million in the first ten days of release". Pulse.ng. 26 December 2018. Retrieved 20 May 2019. 
  8. "EbonyLife Films' Chief Daddy Netflix release party - EbonyLife TV". Ebonylifetv.com. Archived from the original on 17 May 2019. Retrieved 20 May 2019. 
  9. "Nigerian traditional outfits take centre-stage at ‘Chief Daddy’ premiere". Premiumtimesng.com. 3 December 2018. Retrieved 20 May 2019. 
  10. "Chief Daddy Premiere: Nigerian Traditional Attire Outshines - NTA.ng - Breaking News, Nigeria, Africa, Worldwide". Nta.ng. Retrieved 20 May 2019. [Ìjápọ̀ tí kò ṣiṣẹ́ mọ́]
  11. "Netflix acquires ‘Chief Daddy’ – Tribune Online – Friday Treat". Tribuneonlinemg.com. 8 March 2019. Archived from the original on 17 May 2019. Retrieved 20 May 2019.