Richard Mofe Damijo
Richard Mofe-Damijo | |
---|---|
Mofe-Damijo at the premiere of Love Is War | |
Ọjọ́ìbí | Richard Mofe-Damijo 6 Oṣù Keje 1961 Aladja, Ípínlẹ̀ Delta, Nigeria |
Iṣẹ́ | Òṣèré, former Olóṣèlú |
Ìgbà iṣẹ́ | 1980s-present |
Olólùfẹ́ | Jùmọ̀bí Adégbẹ̀san |
Àwọn ọmọ | 4 |
Website | https://www.rmdtheactor.com |
Richard Èyímofẹ́ Evans Mofẹ́-Damijo ni wọ́n bí ní ọjọ́ Kẹfà oṣù Keje ọdún 1961 ni gbogbo ènìyàn mọ̀ sí RMD, jẹ́ òṣèré orí-ìtàgé àti sinimá, olùkọ̀tàn, agbẹjọ́rò olùgbéré-jáde àti olóṣèlú ọmọ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà. Ó ti fìgbà kan tẹ́lẹ̀ jẹ́ Kọmíṣọ́nà fún àti àti ìgbafẹ́ fún Ìpínlẹ̀ Delta nígbà kan rí. Ní ọdún 2005, ó gba àmì-ẹ̀yẹ ti Africa Movie Academy Award fún Best Actor in a Leading Role.[1][2] Ó gba àmì-ẹ̀yẹ títí láé láé ti 12th Africa Movie Academy Awards fún ipa rẹ̀ nínú eré sinimá ní ọdún 2016.[3][4]
Ìbẹ̀rẹ̀ ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n bí Richad ní àdúgbò Aladja ní ìlú Udu Kingdom, ìlú tí ó súnmọ́ Warri pẹ́kí pẹ́kí ní Ìpínlẹ̀ Delta. Ó lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ ti Midwest College, ní ìlú Warri, àti ilé-ẹ̀kọ́ ti Anglican Grammar School, tí ó sì jẹ́ ọ̀kan lára àwọn akẹ́kọ̀ọ́ tí ó ma ń ṣeré ìtàgé nígbà náà. Ó tún lọ sí ilé-ẹ̀kọ́ Fásiti ti UNI BEN, láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa eré-oníṣe Theatre Arts.[5]. Ó tún lọ sí Fásitì ti University of Lagos láti kẹ́kọ̀ọ́ nípa ìmọ̀ òfin ní ọdún 1997ó ṣe tán ní ọdún 2004.[1][6]
Iṣẹ́ rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Lẹ́yìn tí ó jáde ní fásitì, ó bẹ̀rẹ̀ eré sinimá ọlọ́sọ̀ọ̀sẹ̀ tí wọ́n pe àkòrí rẹ̀ ní Ripples. Ṣáájú ìg à náà, ó ti ń ṣiṣẹ́ pẹ̀lú Ìwé-ìròyìn Concord [7] àti Metro Magazine. [8] gẹ́gẹ́ bí olùjábọ̀ ìròyìn. Ní ọdún 2005, ó di ìlú mọ̀ọ́ká látàrí Out of Bounds tí ó jẹ́ kó gbayì gidi.[5][9]
Ipa rẹ̀ nínú ìṣèlú
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Wọ́n yan Mofẹ́ gẹ́gẹ́ bí olùdámọ̀ràn pàtàkì lórí àṣà àti ìgbafẹ́ sí Gómìnà Emmanuel Uduaghan ní ọdún 2008, tí ó sì padà di Kíṣọ́nà fún àṣà àti ìgbafẹ́ fún gbogbo Ìpínlẹ̀ Delta ní ọdún 2009 tí ó kúrò nípò ní ọdún 2015..[10][2][11].
Ìgbé ayé rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Mofẹ́ ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú arábìnrin May Ellen-Ezekiel tí gbogbo èyàn mọ̀ sí(MEE) tí ó jẹ́ olóòtú àti oníṣẹ́ ìròyìn. Ìyàwó rẹ̀ yí papòdà ní ọdún 1996, tí Mofẹ́ sì tún ṣe ìgbéyàwó pẹ̀lú Jùmọ̀bí Adégbẹ̀san tí òun jẹ́ olóòtú ètò orí ẹ̀rọ amóhù-máwòrán.[12]. Moẹ́ bí àwọn ọmọ mèrin, méjì láti ọ̀dò olóògbé tí méjì tókù wá láti ọ̀dọ̀ ìyàwó rẹ̀ tuntun. [13]
Àwọn àṣàyàn fíìmù rẹ̀
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Film | Role | Notes |
---|---|---|---|
1997 | Out of Bounds | with Bimbo Akintola & Racheal Oniga | |
Hostages | |||
1998 | Scores to Settle | with Liz Benson & Omotola Jalade-Ekeinde | |
Diamond Ring | with Liz Benson | ||
1999 | Freedom | ||
The Price | with Eucharia-Anunobi EKWU | ||
2003 | When God Says Yes | with Pete Edochie & Stella Damasus-Aboderin | |
The Richest Man | |||
The Return | with Segun Arinze | ||
The Intruder | with Stella Damasus-Aboderin & Rita Dominic | ||
Soul Provider | with Omotola Jalade-Ekeinde | ||
Romantic Attraction | with Stella Damasus-Aboderin, Chioma Chukwuka & Zack Orji | ||
Private Sin | Pastor Jack | with Genevieve Nnaji, Stephanie Okereke, Olu Jacobs & Patience Ozokwor | |
Passions | with Genevieve Nnaji & Stella Damasus-Aboderin | ||
Love | with Genevieve Nnaji & Segun Arinze | ||
Keeping Faith: Is That Love? | with Genevieve Nnaji & Joke Silva | ||
I Will Die for You | with Omotola Jalade-Ekeinde & Segun Arinze | ||
Emotional Pain | with Stella Damasus-Aboderin | ||
Ayomida | |||
2004 | The Mayors | with Sam Dede & Segun Arinze | |
True Romance | with Rita Dominic & Desmond Elliot | ||
The Legend | with Kate Henshaw-Nuttal | ||
Standing Alone | with Stella Damasus-Aboderin & Tony Umez | ||
Sisters' Enemy | |||
Queen | with Stella Damasus-Aboderin | ||
Little Angel | |||
Kings Pride | with Stella Damasus-Aboderin | ||
I Want Your Wife | |||
Indecent Girl | Charles | with Ini Edo | |
Indecent Act | with Rita Dominic | ||
I Believe in You | with Rita Dominic | ||
Engagement Night | with Stella Damasus-Aboderin | ||
Deadly Desire | |||
Danger Signal | with Desmond Elliot | ||
Critical Decision | with Genevieve Nnaji & Stephanie Okereke | ||
Burning Desire | with Stella Damasus-Aboderin & Mike Ezuruonye | ||
Critical Assignment | The President | with Hakeem Kae-Kazim | |
2005 | The Bridesmaid | with Chioma Chukwuka, Kate Henshaw-Nuttal & Stella Damasus-Aboderin | |
Darkest Night | with Genevieve Nnaji, Segun Arinze & Uche Jombo | ||
Bridge-Stone | with Liz Benson & Zack Orji | ||
Behind Closed Doors | with Stella Damasus-Aboderin, Desmond Elliot & Patience Ozokwor | ||
Baby Girl | with Pete Edochie | ||
2006 | Angels of Destiny | ||
2007 | Caught in the Middle | ||
2014 | 30 Days in Atlanta | Kimberley's father | |
2016 | Dinner | with Iretiola Doyle | |
The Wedding Party | Felix Onwuka | with Sola Sobowale, Ireti Doyle & Adesua Etomi | |
The Grudge | with Doyle and Funmi Holder[14] | ||
2017 | 10 Days in Sun City | Otunba Ayoola Williams | with Ayo Makun & Adesua Etomi |
2017 | |||
The Wedding Party 2 | Felix Onwuka | with Sola Sobowale, Ireti Doyle & Adesua Etomi | |
2019 | God Calling [15] | ||
Love Is War | Dimeji Phillips | with Omoni Oboli |
Awards and nominations
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Year | Event | Prize | Recipient | Result |
---|---|---|---|---|
Gbàá | ||||
2009 | 5th Africa Movie Academy Awards | Best Film In Nigeria | State of The Heart | Yàán |
2012 | 2012 Best of Nollywood Awards | Special Recognition Award | Himself | Gbàá |
2015 | 2015 Africa Magic Viewers Choice Awards | Best Supporting Actor | 30 days in Atlanta | Yàán |
2016 | 12th Africa Movie Academy Awards | LifeTime Achievement Award | Himself | Gbàá |
2017 | 2017 Africa Magic Viewers Choice Awards | Best Actor in Leading Role | Oloibiri | Yàán |
Africa Movie Academy Awards | Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀ | |||
2017Nigeria Entertainment Awards | Best Supporting Actor | Iṣẹ́ ń lọ lórí ẹ̀ |
Àwọn ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ 1.0 1.1 Akande, Victor (28 November 2009). "New world of A-list stars blacklisted in 2005". The Nation (Lagos, Nigeria: Vintage Press Limited). http://thenationonlineng.net/web2/articles/26859/1/New-world-of-A-list-stars-blacklisted-in-2005/Page1.html. Retrieved 24 August 2010.
- ↑ 2.0 2.1 "Delta State Government swears in two new Commissioners". Archived from the original on 13 October 2020. Retrieved 26 January 2010.
- ↑ Ekechukwu, Ferdinand (27 October 2018). "For RMD, It's Good News from Kigali". Thisday Live (Lagos, Nigeria). https://www.thisdaylive.com/index.php/2018/10/27/for-rmd-its-good-news-from-kigali/. Retrieved 22 April 2019.
- ↑ Ekpai, Joan (14 June 2016). "RMD receives Lifetime Achievement award from Pete Edochie (AMAA 2016)". Nollywood Community (Lagos, Nigeria). https://nollywoodcommunity.com/rmd-receives-amaa-life-time-achievement-award-from-pete-edochie/. Retrieved 22 April 2019.
- ↑ 5.0 5.1 Ogunbayo, Modupe. "Richard Mofe-Damijo: An Actor's Actor". Newswatch (Lagos, Nigeria: Newswatch). Archived from the original on 13 October 2020. https://web.archive.org/web/20201013033028/https://www.newswatchngr.com/editorial/allaccess/special/10112232035.htm/. Retrieved 24 August 2010.
- ↑ Balogun, Sola. "Acting on stage is my greatest passion". Daily Sun (Lagos, Nigeria: The Sun Publishing Limited). http://www.sunnewsonline.com/webpages/features/showtime/2009/jan/09/showtime-09-01-2009-001.htm. Retrieved 24 August 2010.
- ↑ "After Concord Newspaper died, it felt like I lost a baby –Mike Awoyinfa".
- ↑ "Richard Mofe-Damijo: Profile of an iconic Nollywood actor". P.M. News. 8 May 2020.
- ↑ "Richard Mofe-Damijo – Profile". New York City: African Film Festival. Archived from the original on 13 October 2020. Retrieved 24 August 2010.
- ↑ "Special Adviser or not im still an actor RMD". thenigerianvoice.com. Retrieved 29 August 2019. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Comedian mocks RMD". AllAfrica.com. Retrieved 29 August 2019. Unknown parameter
|url-status=
ignored (help) - ↑ "Remembering May Ezekiel, 21 years after". Archived from the original on 2020-10-21. Retrieved 2020-10-19.
- ↑ "RMD: Two Decades of Screen Romance". Archived from the original on 17 August 2010. Retrieved 26 January 2010.
- ↑ "FUNMI HOLDER: The Nigerian Actress Who Went Back in Time". 19 January 2020.
- ↑ "God Calling Movie". IMDb. Retrieved 13 June 2019.
Àwọn Ìtàkùn ìjásóde
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- Pages with citations using unsupported parameters
- Àwọn ọjọ́ìbí ní 1967
- Best Actor Africa Movie Academy Award winners
- Àwọn ènìyàn alààyè
- Delta State politicians
- University of Lagos alumni
- Male actors from Warri
- Political office-holders in Nigeria
- 20th-century Nigerian male actors
- 21st-century Nigerian male actors
- Nigerian actor-politicians
- University of Benin (Nigeria) alumni
- Male actors in Yoruba cinema