Johnson Aguiyi-Ironsi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti JTY Aguyi-Ironsi)
Jump to navigation Jump to search
Ogagun-Agba Johnson Aguiyi-Ironsi
AguiyiIronsi.JPG
2ji Aare ile Naijiria (ekeji)
In office
January 16, 1966 – July 29, 1966
Asíwájú Nnamdi Azikiwe
Arọ́pò Yakubu Gowon
Personal details
Ọjọ́ìbí (1924-03-03)Oṣù Kẹta 3, 1924
Umuahia, Abia State, Nigeria
Aláìsí July 29, 1966(1966-07-29) (ọmọ ọdún 42)
Lalupon, Nigeria
Nationality Nigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlu kòsí (iṣẹ́ ológun)

Johnson Thomas Umunnakwe Aguiyi-Ironsi (March 3, 1924 - 29 July, 1966) je ologun omo orile-ede Naijiria. Leyin ti ologun gba ijoba ni 15 January, 1966, Aguiyi-Ironsi di Olori Orile-ede Naijiria titi di 29 July, 1966 nigbati won dote si ijoba re ti won si pa.

Igba ewe[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

A bi ni ilu Umuahia to wa ni Ipinle Abia loni ni ojo keta osu keta odun 1924 fun Mazi ati Ezugo Aguiyi. Nigba to pe omo odun mejo Aguiyi-Ironsi ko lo si odo egbon re obinrin Anyamma eni to je aya Theophilius Johnson to je osise asoju ijoba fun ile Sierra Leone ni Umuahia. Nigbato to omo odun mejidinlogun Ironsi bo si ise ologun Naijiria botilejepe egbon re lodi si.


Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]