Abdullahi Ibrahim (ológun)

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Abdullahi Ibrahim

Wing Commander (o ti feyinti) Abdullahi Ibrahim je Alamojuto Ijoba Ologun akoko Ipinle Nasarawa, Nigeria larin August 1996 ati August 1998 leyin idasile ipinle yi lati inu Ipinle Plateau nigba ijoba ologun Ogagun Sani Abacha.[1]

Ìgbésíayé

Wọn pé Ibrahim sí iṣẹ agbẹjọro ti awọn ilu ọba ni ọdún 1963, atun pe sí iṣẹ agbẹjọro ni ilẹ Nàìjíríà ni ọdún 1964. Oṣiṣẹ gẹgẹ bíi olugbani nimoran ọrọ òfin àti olugbamoran agba ni ìyá àríwá ile Nàìjíríà. O da ile iṣẹ tirẹ silẹ ti o pe ni Abdullahi Ibrahim and company ni ọdún 1973 gege bi alabaṣepọ ìṣàkóso. Abdulahi Ibrahim náà ni wọn fi jẹ olugbani nimoran ọrọ òfin ni ile iṣẹ New Nigeria Development Company Limited, (NNDC), o tun pada di Alaga ile iṣẹ yìí. Ni ọdún 1992, wọn gbà gege bii lọya agba ni Nàìjíríà, eleyii si mu ki ọ jẹ akọkọ ninu awọn ara ìyà Ariwa ni ilẹ Nàìjíríà tí ọ kọkọ jẹ ipò naa. Ọ jẹ alága awọn Body of Benchers titi di ọdún 2001. O tun jẹ ara ẹgbẹ Notary Public, Chartered Institute of Arbitrators, Permanent Court of Arbitration at the Hague ati alaga egbe Nigerian Bar Association Legal Practitioners Disciplinary Committee.[2]



Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. "Nigeria States". WorldStatesmen. Retrieved 2010-06-03. 
  2. , 2 Mar 2007 https://en.m.wikipedia.org/wiki/Abdullahi_Ibrahim#cite_note-self-1, retrieved 1 Mar 2022  Missing or empty |title= (help)