Èdè Àhàn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Àhàn
Sísọ níNàìjíríà
AgbègbèÌpínlẹ̀ Òndó
Èdè ìbátan
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-3ahn

Àhàn jẹ́ èdè ní Nàìjíríà (ní àwọn Ìpínlẹ̀ Òndó).[1]

Vocabulary comparison[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

See also: Ayere-Ahan word lists (Wiktionary)

Èdè Àhàn, Èdè Ayere, Èdè Yorùbá:[1]

Èdè Gẹ̀ẹ́sì (English) Èdè Yorùbá Èdè Àhàn Èdè Ayere
head orí éri ago
eye ojú ewú ɛ́jɛ́
nose imú owũ ówṹ
ear etí éndi éndí
mouth ẹnu arũ anu
tooth eyín eɲĩ éyĩ́
tongue ahọ́n irɛ̃́ únú
neck ọrùn unkɔ̃́rɔ̃́ ìgɔ̀gɔ̀
chin àgbọ̀n ũndɛ̃ amgbehe
jaw àgbọ̀n àngbà àngbà
arm ọwọ́ àkà ɔkà
hand ọwọ́ ɔɔ ɔ́wɔ́
leg ẹsẹ̀ esè ehè
thigh itan unta úntá
knee orókún égú àtekú
nail (finger/toe) èékáná ɛ̀kĩ̀kà ìrɛnrɛǹ
female breast ọmú ɛmũ ɛ́mɔ́
stomach ikùn duduruku ifu
belly asi ahi
navel ìdodo ùwɔ̀ úgó
back ẹ̀yìn àun ànjáùn
skin ara idʒì awɔla
hair irun itu itu
beard ihĩndɛ ìndàún
liver ẹ̀dọ̀ ɛ̀jɔ̀ ɛ̀jɔ̀(r)
bone egungun igbegbe egbe
blood ẹ̀jẹ̀ èsè èʃwè
saliva itọ́ itó ĩto, únta
faeces ìgbẹ́ ímĩ aɲinku
body ara àgbè ɔlá
water omi oɲĩ oyin
oil epo ékpú ekpú
salt iyọ̀ owû
soup/stew ɔndɔ ɔndɔ̀
palm-wine ọtí ɔntɛ ɔntɛ̀
fish (generic) ẹja eðu emeʃwi

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]