Túndé Ìdíàgbọn

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Jump to navigation Jump to search
Babatunde Idiagbon
6th Chief of Staff, Supreme Headquarters
In office
31 December 1983 – 27 August 1985
ÀàrẹMuhammadu Buhari as Military Head of State
AsíwájúAlex Ekwueme as civilian Vice President of Nigeria
Arọ́pòEbitu Ukiwe
Governor of Borno State
In office
July 1978 – October 1979
AsíwájúMustapha Amin
Arọ́pòMohammed Goni
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí(1942-09-14)14 Oṣù Kẹ̀sán 1942
Ilorin, Kwara, Nigeria
Aláìsí24 March 1999(1999-03-24) (ọmọ ọdún 56)
Ilorin, Kwara, Nigeria
Ọmọorílẹ̀-èdèNigerian
Ẹgbẹ́ olóṣèlúNone (military)
(Àwọn) olólùfẹ́Biodun Idiagbon
Alma materNigerian Military School
Pakistan Military Academy
Nigerian Defence Academy
Naval Postgraduate School
Military service
Allegiance Nigeria
Branch/service Adigun Nàìjíríà
Years of service1962–1985
RankMajor General

Babatunde Baku Abdul Idiagbon (14 September 1942 - 24 March 1999) jẹ́ ọmọ ológun ará ilẹ̀ Naijiria. Ní ọdún 1983 ó kópa nínú ifipágbàjoba lọ́wọ́ Ààrẹ Shehu Shagari, lẹ́yìn èyí ó di Ọ̀gá Gbogbo Ọmọṣẹ́ ológun ní ibùjókó tógajùlọ ní I Ológun ilẹ̀ Nàìjíríà, ipò yí dúró gẹ́gẹ́ bí igbákejì ààrẹ sí Muhammadu Buhari tó di ààrẹ orílẹ̀-èdè. Idiagbon di ipò yí mú lati 31 December, 1983 titi di 27 August, 1987 ti Ibrahim Babangida náà fi fipágbàjoba.[1]


Àwọn ìtọ́kasí[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. Inamete, Ufot (2001). Foreign Policy Decision-making in Nigeria. Susquehanna University Press. pp. 131.