Èdè Ọ̀kọ́

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Ọ̀kọ́
Sísọ níNàìjíríà
AgbègbèÌpínlẹ̀ Kogí
Èdè ìbátan
Àwọn àmìọ̀rọ̀ èdè
ISO 639-3oks

Ọ̀kọ́ jẹ́ èdè ní Nàìjíríà (ní àwọn Ìpínlẹ̀ Kogí).[1]

Vocabulary[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

See also: Oko word list (Wiktionary)

Èdè Ọ̀kọ́, Èdè Yorùbá:[1]

No. Èdè Gẹ̀ẹ́sì (English) Èdè Yorùbá Èdè Ọ̀kọ́
16 woman obìnrin íyárú
17 man ọkùnrin íforó
18 person ènìyàn orokorò
19 fish ẹja ayɛ́rɛ́
20 bird ẹyẹ ónéne
21 dog ajá úwó
22 louse iná ótí
23 tree igi esáma
24 seed èso íbírè
25 leaf ewé émúmú
26 root gbòngbò, ìpilẹ̀sẹ̀ ẽ̂ɲɛ̃́
27 bark èpo igi
28 skin (human) ara íwúkpè
28b hide (animal skin) awọ èkpò
29 flesh ẹranko ɔ́né
30 blood ẹ̀jẹ̀ ɛ́ŋɔ̂
31 bone egungun ófú
32 grease ìpara ɛ̃́rɔ̃́
33 egg ẹyin éjí
34 horn ìwo ɛ̀kpànɛ̀
35 tail ìrù óshɛ̃̌
36 feather ìyẹ́ ásɛ̃́sɛ̃́
37 hair irun ɛ́pɛ̃́
38 head orí ɛ́páŋ
39 ear etí ɔ́tɔ̃́
40 eye ojú áɲẽ́
41 nose imú ɔ́mɔ́dɔ́rɛ̀
42 mouth ẹnu ówó
43 tooth eyín írú
44 tongue ahọ́n ɛ́làárɛ́
45 nail èékáná ìgbòbò
46 (foot), leg ẹsẹ̀ ɔ́ʃɛ̃́
47 knee orókún íkwĩ́
48 hand, arm ọwọ́ úbá
49 belly inú, ikùn épúrú
50 neck ọrùn ɛ́gɛ́rɛ́
51 breast(s) ọmú ébá
52 (heart), chest ọyọ̀n; (ọkàn) êgbã̌
52b inside inu úlokô
53 liver ẹ̀dọ̀ ɛ́yɛ́
54 drink! mu
55 eat! jẹ
56 bite! jẹ, jẹ kurû
57 see! balé
58 hear! gbọ́
59 know! mọ̀ dĩ̂
60 sleep sùn bue
61 die!
61b death úfó
62 kill! pa ŋwã́ɲà
63 swim! wẹ̀ bori
64 fly! pirî
65 walk! rìn kijéjẽ
66 come! keʃá
67 lie (down)! dùbúlê buê
68 sit! jókó mã́ǎ
69 stand! dúró, dìde, nàró furáa
70 give me! fi fún, fi bùn, jìn vá mɔ
71 say , sọ
72 sun òrù éyí
73 moon òṣùpá ɔ́ʃɛ̃̂
74 star ìràwọ̀ ɛʃɛ́kpɛ́nɛ́
75 water omi ébí
76 rain òjò òsì
76b rain water odò òsì bì
77 stone òkúta ɔ́tárɛ́
78 sand yanrìn áʃéʃɛ̃́
79 earth ilẹ̀ ijê
80 cloud òsòsì
81 smoke éfí ã́ã̀rã́
82 fire iná ɛ́rá
83 ash eérú éwurṹ
84 burn! sún kɛnɛ̂
85 path ọ̀nà ɔ́ríkpókpó
86 mountain òkè gíga ɔ́rɛ́
87 red pupa óɲáɲà
88 green aláwọ̀ ewé kakɔrɔ
88b raw ójíjɛ̀
89 yellow
90 white funfun ókúkúrù
91 black ṣú orĩ̂rĩ́
92 night òru
93 hot ta ěfí
93b heat ófífi
94 cold tutù fũ̌ũ
94b cold (n.) ófũfṹ
95 full kún
96 new tuntun ówówó
97 good rere rómuro
98 round òbìrìkìtì (?) koòrò
99 dry gbẹ yéyí
100 name orúkọ íwúrù
101 year ọdún ɛ́ɲɛ́
102 chin àgbọ̀n akã̂
103 finger ɛ́bɛ́bɛ̀rɛ
104 navel ìdodo ibòbò
105 forehead íʃí
106 back of head ífúmúrù
107 side ẹ̀gbẹ́ ɛ̀fɛ̀
108 back ẹ̀yìn ábárɛ̀
109 thing ɛ́pɛ̃̂
110 market ọjà éjî
111 basket ùgì
1 ọ̀kan ɔɔ́rɛ
2 éjì ɛ̀bɔ̀rɛ̀
3 ẹ̀ta ɛtá
4 ẹ́ẹ̀rin ɛná
5 áàrún upí
6 ẹ́ẹ́fà ɔ̀pɔ́nɔɔ́rɛ
7 éèje ufômbɔ̀rɛ̀
8 ẹ́jọ ɔnɔ́kɔ́nɔkɔ́nɔ
9 ẹ́ẹ̀sán ubɔ́ɔ̀rɛ̀
10 ẹ́ẹ̀wá fɔ̂
11 efɔ̃kɔɔ́rɛ
20 ɔgbɔ̀lɔ̀
21 ɔgbɔ̀lɔ̀ kutó
22 ɔgbɔ̀lɔ̀ ketúbɔ̀rɛ̀
30 ɔgbɔ̀lɔ̀ kǎkɔ́rɔfɔ́
40 íbɔ̀rɛ̀
50 íbɔ̀rɛ̀ kǎkɔ́rɔfɔ́
60 íta
61 íta kutó
80 igbófú
100 ípi
200 ɛ́párɛ́
1000 ífúrúfɔ
2000 ípipi ɔ̀rɔgbɔ̀lɔ̀

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

  1. 1.0 1.1 Jungraithmayr, Herrmann. 1973. Eine Wortliste des Ọkọ, der Sprache von Ogori (Nigeria). Africana Marburgensia 6: 58-66.