Òmìnira ilẹ̀ Áfríkà
Ìrísí
Òmìnira ilẹ̀ Áfríkà jẹ́ ǹkan tí ó ṣẹlẹ̀ láàrin àwọn ọdún 1950s sí 1975 nígbà Cold War, tí ọ̀pọ̀lopọ̀ orílẹ̀ èdè sì gba òmìnira. Ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìṣẹ̀lẹ̀ yìí ló mú wàhálà àti àìsimin dání, díè nínú wọn ni Mau Mau rebellion ní British Kenya, Algerian War ní French Algeria, Congo Crisis ní Belgian Congo, Angolan War of Independence ní Portuguese Angola, Zanzibar Revolution ní Sultanate of Zanzibar, àti Ogun Abele Nàìjíríà tí Biafra àti ìjọba Nàìjíríà jà.[1][2][3][4][5]
Bí àwọn orílẹ̀-èdè náà ṣe gba òmìnira
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Tábìlì yí sọ bí àwọn orílẹ̀ èdè méjìdínlógọ́ta ṣe gba òmìnira.
Àwọn Ìtọ́kasí
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ John Hatch, Africa: The Rebirth of Self-Rule (1967)
- ↑ William Roger Louis, The transfer of power in Africa: decolonization, 1940-1960 (Yale UP, 1982).
- ↑ Birmingham, David (1995). The Decolonization of Africa. Routledge. ISBN 1-85728-540-9.
- ↑ John D. Hargreaves, Decolonization in Africa (2014).
- ↑ for the viewpoint from London and Paris see Rudolf von Albertini, Decolonization: the Administration and Future of the Colonies, 1919-1960 (Doubleday, 1971).
- ↑ wucher King, Joan (1989). Historical Dictionary of Egypt. Books of Lasting Value. American University in Cairo Press. pp. 259–260. ISBN 978-977-424-213-7.
- ↑ "A/RES/289(IV) - E - A/RES/289(IV)". undocs.org. Retrieved 2020-07-23.
- ↑ Robert O. Collins, A History of Modern Sudan Archived 18 October 2022 at the Wayback Machine.
- ↑ Independent Benin unilaterally annexed Portuguese São João Baptista de Ajudá in 1961.
- ↑ UN General Assembly Resolution 34/37 and UN General Assembly Resolution 35/19
- ↑ UN resolution 2145 terminated South Africa's mandate over Namibia, making it de jure independent. South Africa did not relinquish the territory until 1990
Àṣìṣe ìtọ́kasí: <ref>
tags exist for a group named "lower-alpha", but no corresponding <references group="lower-alpha"/>
tag was found