Jump to content

Chizzy Alichi

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Chizzy Alichi
Chizzy Alichi
Ọjọ́ìbíChigozie Stephanie Alichi
23 Oṣù Kejìlá 1993 (1993-12-23) (ọmọ ọdún 30)[1]
Enugu
Orílẹ̀-èdèNaijiria
Iṣẹ́Osere fiimu/ Awose
Ìgbà iṣẹ́2010–lowolowo
Websitechizzyalichi.com

Chigozie Stephanie Alichi (tí a bí ní ọjọ 23 Oṣù kejìlá ọdún 1993), tí a mọ̀ ní Chizzy Alichi, jẹ́ òṣèré fiimu tí Ìlu Nàìjíríà.

Chizzy Alichi wá láti Ezza Nkwubor Nike ní Enugu East, ìjọba agbègbè kan Nàìjíríà. Enugu, Nàìjíríà. Àbìkẹ́hìn ló jẹ́ nínú àwọn méjì tí òbí rẹ́ bí. Ìròyìn rẹ̀ kàn jákèjádò nígbà tí ó kọ́ ilé ńlá fún àwọn òbí rẹ̀ ní ọdún 2017.[2][3][4][5][6] Ó ń gbé ní Asaba, Ìpínlẹ̀ Delta.[7]

Ó darapọ̀ mọ́ Nollywood ní ọdún 2010 láìrò tẹ́lẹ̀ . Ó darapọ̀ mọ́ Actors Guild of Nigeria. Ó tọrọ fún ààyè láti kópa nínú fíìmù kan, wọ́n sì ṣe àfihàn rẹ̀ nígbà àkọ́kọ́ gẹ́gẹ́ bí òṣèré nínú fíìmù Magic Money tí Mercy Johnson àti Bob-Manuel Udokwu náà kópa nínu rẹ̀.

Ìṣẹ̀lẹ̀ gbòógì tó ni ipa rere nìdíí iṣẹ́ rẹ̀ ni eré Akaraoku, tó túmọ̀ sí *àkàrà gbígbóná", ní 2016. Yul Edochie ló darí rẹ̀. Ìwé ìpolówó rẹ̀ ló gbalẹ̀ kan lórí ìkànnì ìbánidọ́rẹ̀ẹ́ káàkiri tí àwọn èèyàn fi lérò wí pé alákàrà ni lóòótọ́. Èyí fún ní àǹfààní láti kópa nínú àwọn eré mìíràn sí ní ọdún 2017.

̀ ni eré Akaraoku, tó túmọ̀ sí *àkàrà gbígbóná", ní 2016. Yul Edochie ló darí rẹ̀. Ìwé ìpolówó rẹ̀ ló gbalẹ̀ kan lórí ìkànnì ìbánidọ́rẹ̀ẹ́ káàkiri tí àwọn èèyàn fi lérò wí pé alákàrà ni lóòótọ́. Èyí fún ní àǹfààní láti kópa nínú àwọn eré mìíràn sí ní ọdún 2017.


[8][9]

Àwọn ìfarahàn rẹ̀ nínu orin

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọduń Orin Akọrin Àfikún
2016 "Mmege[10][11] Flavour N'abania
Ọdún Ẹ̀bùn Ẹ̀ka Àbájáde Àfikún
2017 City People Entertainment Awards".[12] Oṣere Tuntun Ti Odun Ti o dara julọ (Gẹẹsi) Wọ́n pèé
Nigeria Achievers Award.[13] Oṣere ti o ni atẹle Gbàá

Àwọn àsàyàn eré rẹ̀

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
Ọdún Fiimu Ipa Àfikún
2018 Do Good Nwakpaka Pẹ̀lu kíkópa Ebele Okaro
My Story
Power of Madness Pẹ̀lu kíkópa Nonso Diobi,Ngozi Ezeonu
2017 Point & Kill Pẹ̀lu kíkópa Nonso Diobi
Tears of Victory Pẹ̀lu kíkópa Yul Edochie
Power in The palace Pẹ̀lu kíkópa Chioma Chukwuka
Obudu The Evil Shrine Pẹ̀lu kíkópa Ebele Okaro
Teckno In The Village
Little Oath Pẹ̀lu kíkópa Chiwetalu Agu,Ken Erics
Beautiful Mmege Pẹ̀lu kíkópa Ebele Okaro
The King's Wealth Pẹ̀lu kíkópa Clem Ohameze
Teri Teri Pẹ̀lu kíkópa Rachael Okonkwo
Virgin Justice Pẹ̀lu kíkópa Regina Daniels
Fada Fada Pẹ̀lu kíkópa Yul Edochie
Financial Woman Pẹ̀lu kíkópa Yul Edochie
Ajebo America Pẹ̀lu kíkópaKen Erics,Nonso Diobi
2016 Akaraoku Akara Oku Pẹ̀lu kíkópaYul Edochie
2015 Vanity Pẹ̀lu kíkópaNgozi Ezeonu
Attitude Joan
2014 Idemmili Pẹ̀lu kíkópa Pete Edochie,Patience Ozokwor,Yul Edochie
The Motherless Pẹ̀lu kíkópa Ini Edo
Old Soldier Pẹ̀lu kíkópa Nkem Owoh,Osita Iheme,Chinedu Ikedieze,Ime Bishop Umoh
The Three Blind Pẹ̀lu kíkópa Chika Ike
2013 Cry of a Witch Ifeoma
2011 Double Barrel Pẹ̀lu kíkópa Francis Odega,Amaechi Muonagor
Sherikoko Pẹ̀lu kíkópa John Okafor,Funke Akindele
2010 Forgive Me Father Pẹ̀lu kíkópa Nkem Owoh,Osita Iheme
Magic Money Pẹ̀lu kíkópa Mercy Johnson, Bob-Manuel Udokwu

Àwọn ìtọ́kasí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]
  1. "Upcoming Nollywood actress releases photos to mark birthday". Pulse. Retrieved 18 March 2018. 
  2. "CHIZZY ALICHI: Why I don’t kiss just anybody on set". The Nation. Retrieved 18 March 2018. 
  3. "Nollywood Actress, Chizzy Alichi Builds House For Her Parents". Naija News. Retrieved 18 March 2018. 
  4. "Nollywood Actress, Chizzy Alichi Builds A House For Her Parents (Photos)". Naijaloaded. Retrieved 18 March 2018. 
  5. "Nollywood actress chizzy Alichi builds a mansion for her parents". Naij. Retrieved 18 March 2018. 
  6. "Meet Nollywood Actress who Does not Wear Expensive Clothes". Modern Ghana. Retrieved 18 March 2018. 
  7. "I’m praying for a man –Chizzy Alichi, actress". The Sun. Retrieved 18 March 2018. 
  8. "Chizzy Alichi: How Kenneth Okonkwo saved my life on set of my first movie". Naija Gists. Retrieved 18 March 2018. 
  9. "CHIZZY ALICHI: ‘Why I’m still single". The Nation. Retrieved 18 March 2018. 
  10. "Flavour features pretty actress in new video". Naij. Archived from the original on 6 August 2018. Retrieved 18 March 2018. 
  11. "Beautiful Nollywood Actress, Chizzy Alichi Featured In Flavour’s "Mmege" Video". The Info NG. Archived from the original on 15 August 2018. Retrieved 18 March 2018. 
  12. "List Of Winners At The 2017 City People Movie Awards". Concise News. Archived from the original on 19 March 2018. Retrieved 17 March 2018. 
  13. "NIGERIA ACHIEVERS AWARDS 2017 NOMINEES LIST". Concise News. Retrieved 17 March 2018. 

Àwọn ìtakùn Ìjásóde

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]