Jump to content

Àkójọ àwọn ìlú ní Nàìjíríà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
Àwòrán tó ń ṣe àfihàn Nàìjíríà.
Ikeja , Olú-ìlú Lagos State; ìlú kìíní tí ó ní ọ̀pọ̀ olùgbé.
Kano, Olú-ìlú Kano State; ìlú kejì tí ó ní ọ̀pọ̀ olùgbé.
Ibadan, Olú-ìlú Oyo State; ìlú kẹta tí ó ní ọ̀pọ̀ olùgbé.
Port Harcourt, Olú-ìlú Rivers State; ìlú kẹrin tí ó ní ọ̀pọ̀ olùgbé.

Àkójọpọ̀ Àwọń Ìlú Ní Nàìjíríà

Èyí ni àkójọpọ̀ àwọn ìlú àti olú-ìlú ni Orílẹ̀-èdè Olómìnira ilẹ̀ Nàìjíríà. Àwọn ìlú mẹ́rìnlá tí ó ní ọ̀pọ̀ olùgbé ni a ṣe àfihàn wọn dáadáa.

Itokasi[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]