Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ìjọba Àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà President of the Federal Republic of Nigeria | |
---|---|
Executive Branch of the Federal Government | |
Style | Mr. President His Excellency |
Member of | Federal Executive Council National Security Council |
Residence | Aso Villa |
Seat | Abuja, F.C.T. |
Appointer | Direct popular election |
Iye ìgbà | Four years, renewable once |
Constituting instrument | Òfin-ìbágbépọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà |
Ẹni àkọ́kọ́ | Nnamdi Azikiwe |
Formation | Àdàkọ:Date and age |
Deputy | Vice President of Nigeria |
Owó osù | ₦14,000,000 annually[1] |
Website | statehouse.gov.ng |
Àyọkà yìí jẹ́ ìkan nínú àwọn àyọkà nípa ìṣèlú àti ìjọba ilẹ̀ Nàìjíríà |
---|
Adájọ́
|
|
Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ìjọba Àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà tàbì Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà lásán ni olórí orílẹ̀-èdè àti olórí ìjọba Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ìjọba Àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà.[2] Ààrẹ ilẹ̀ Nàìjíríà náà tún ni Aláṣẹ pátápátá àwọn ológun Nàìjíríà. Àwọn ará Nàìjíríà ún dìbò yan ààrẹ fún ọdún mẹ́rin. Àwọn ipò ààrẹ, àwọn agbára, àti àwọn oyè olórí orílẹ̀-èdè àti olórí ìjọba jẹ́ dídàpọ̀ sí ipò ààrẹ lábẹ́ Òfin-Ibágbépọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà odún 1979. Ààrẹ lọ́wọ́lọ́wọ́, Bola Tinubu, bọ́ sí orí àga ní 29, osù karùn, o̩dún 2023, gẹ́gẹ́bí ààrẹ 16k Orílẹ̀-èdè Olómìnira Ìjọba Àpapọ̀ ilẹ̀ Nàìjíríà.[3]
Itan
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Nigbati Naijiria di ile apapo oselu olominira ni odun 1963 larin Awon Orile-ede Ajoni, o diwo mo ona ijoba igbimo asofin ti o jogun lat'owo ile Britani. Nnamdi Azikiwe ti o je Gomina Agba nigbana di Aare,[4] ipo to je fun ayeye, nigbati ti Abubakar Tafawa Balewa si di ipo Alakoso Agba mu.[4]
Àkójọ àwọn Olórí Ìjọba Ológun àti Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà Láti Ọdún 1963-1966
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ààrẹ orílẹ̀ èdè Nàìjíríà (1963-1966)
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oruko | Ojoibi-Ojoalaisi | Igba ijoba bere | Igba ijoba pari | Egbe oloselu |
---|---|---|---|---|
Nnamdi Azikiwe | 1904 - 1996 | 1 October 1963 | 16 January 1966 (deposed) | NCNC |
Àwọn Olórí Ìjọba Ológun orílẹ̀ èdè Nàìjíríà (1966-1979)
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Oruko | Ojoibi-Ojoalaisi | Igba ijoba bere | Igba ijoba pari | Egbe oloselu |
---|---|---|---|---|
Ogagun Agba Johnson Aguiyi-Ironsi | 1924 - 1966 | 16 January 1966 | 29 July 1966 (deposed and murdered | Ologun |
Ogagun Yakubu Gowon | 1934 - | 1 August 1966 | 29 July 1975 (deposed) | Ologun |
Ogagun Murtala Mohammed | 1938 - 1976 | 29 July 1975 | 13 February 1976 (assassinated) | Ologun |
Ogagun Olusegun Obasanjo (1st time) | 1937 - | 13 February 1976 | 1 October 1979 | Ologun |
Ààrẹ orílẹ̀ Nàìjíríà (1979-1983)
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọrúkọ | Ọjọ́ìbí-Ọjọ́aláìsí | Ìgbà bẹ̀rẹ̀ | Ìgbà parí | Ẹgbẹ́ olóṣèlú |
---|---|---|---|---|
Shehu Shagari | 1925 - 2018 | 1 October 1979 | 31 December 1983 (deposed) | NPN |
Alaga Igbimo Ologun Togajulo ile Naijiria (1983-1985)
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọrúkọ | Ọjọ́ìbí-Ọjọ́aláìsí | Ìgbà bẹ̀rẹ̀ | Ìgbà parí | Ẹgbẹ́ olóṣèlú |
---|---|---|---|---|
Muhammadu Buhari | 1942 - | 31 December 1983 | August 27 1985 (deposed) | Ologun |
Aare Igbimo Ile-ise Ologun ile Naijiria (1985-1993)
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọrúkọ | Ọjọ́ìbí-Ọjọ́aláìsí | Ìgbà bẹ̀rẹ̀ | Ìgbà parí | Ẹgbẹ́ olóṣèlú |
---|---|---|---|---|
General Ibrahim Babangida | 1941 - | 27 August 1985 | 26 August 1993 (resigned) | Ologun |
Olórí orílẹ̀-èdè ìjọba fìdíhẹ orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (1993)
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọrúkọ | Ọjọ́ìbí-Ọjọ́aláìsí | Ìgbà bẹ̀rẹ̀ | Ìgbà parí | Ẹgbẹ́ olóṣèlú |
---|---|---|---|---|
Ernest Adegunle Oladeinde Shonekan | 1936 - | 26 August 1993 | 17 November 1993 (deposed) | Koni |
Alaga Igbimo Ijoba Igba Pato ile Naijiria (1993-1999)
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọrúkọ | Ọjọ́ìbí-Ọjọ́aláìsí | Ìgbà bẹ̀rẹ̀ | Ìgbà parí | Ẹgbẹ́ olóṣèlú |
---|---|---|---|---|
General Sani Abacha | 1943 - 1998 | 17 November 1993 | 8 June 1997 (died in office) | Ologun |
General Abdulsalami Abubakar | 1942 - | 8 June 1998 | 29 May 1999 | Ologun |
Àwọn Ààrẹ Orílẹ̀-èdè Nàìjíríà (1999-Oni)
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]Ọrúkọ | Ọjọ́ìbí-Ọjọ́aláìsí | Ìgbà bẹ̀rẹ̀ | Ìgbà parí | Ẹgbẹ́ olóṣèlú |
---|---|---|---|---|
Olusegun Obasanjo (2nd time) | 1937 - | 29 May 1999 | 29 May 2007 | PDP |
Umaru Yar'Adua | 1951 - 2010 | 29 May 2007 | 5 May 2010 (died in office) | PDP |
Goodluck Jonathan | 1957 - | 5 May 2010 | 29 May 2015 | PDP |
Muhammadu Buhari | 1942- | 29 May 2015 | 29 May 2023 | APC |
Bola Tinubu | 1952- | 29 May 2023 | APC |
Àyọkà yìí tàbí apá rẹ̀ únfẹ́ àtúnṣe sí. Ẹ le fẹ̀ jù báyìí lọ tàbí kí ẹ ṣàtúnṣe rẹ̀ lọ́nà tí yíò mu kúnrẹ́rẹ́. Ẹ ran Wikipedia lọ́wọ́ láti fẹ̀ẹ́ jù báyìí lọ. |
Itokasi
[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]- ↑ Ibeh, Nnenna (30 May 2015). "Buhari to earn N14 million as annual salary, allowances". Premium Times. http://www.premiumtimesng.com/news/headlines/184046-buhari-to-earn-n14-million-as-annual-salary-allowances.html.
- ↑ Orjinmo, Nduka (2022-06-08). "Bola Tinubu - the 'godfather' who has been sworn in as Nigeria's president". BBC News. Retrieved 2023-06-12.
- ↑ "Bola Tinubu". Encyclopedia Britannica. 2023-03-15. Retrieved 2023-06-12.
- ↑ 4.0 4.1 "Nnamdi Azikiwe - Biography & Facts". Encyclopedia Britannica. 1998-07-20. Retrieved 2023-06-12. Àṣìṣe ìtọ́kasí: Invalid
<ref>
tag; name "Encyclopedia Britannica 1998" defined multiple times with different content