Jump to content

Frederik Willem de Klerk

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti F. W. de Klerk)
Frederik Willem de Klerk
7th Aare Orile-ede ile Guusu Afrika
In office
15 August 1989 – 10 May 1994
AsíwájúPieter Willem Botha
Arọ́pòNelson Mandela
Gege bi Aare ile Guusu Afrika
1st Deputy President of South Africa
In office
10 May 1994 – 30 June 1996
Serving with Thabo Mbeki
ÀàrẹNelson Mandela
AsíwájúOffice Established
Arọ́pòThabo Mbeki (solely)
Àwọn àlàyé onítòhún
Ọjọ́ìbí18 Oṣù Kẹta 1936 (1936-03-18) (ọmọ ọdún 88)
Johannesburg, Transvaal, Union of South Africa
Aláìsí11 November 2021
Fresnaye South Africa
Ọmọorílẹ̀-èdèSouth African
Ẹgbẹ́ olóṣèlúNational Party
New National Party
(Àwọn) olólùfẹ́Marike Willemse (1959-1998)
Elita Georgiades (1998-Present)
Àwọn ọmọJan de Klerk
Willem de Klerk
Susan de Klerk
Alma materPotchefstroom University
OccupationPolitician
ProfessionAttorney

Frederik Willem de Klerk (ojoibi 18 March 1936 - Oṣu kọkanla ọjọ 11, Ọdun 2021), to je mimo si F. W. de Klerk, lo je Aare Orile-ede keje ati igbeyin ni orile-ede Guusu Afrika ni igba iselu eleyameya, o wa loripo lati September 1989 de May 1994.