Jump to content

Ìṣọ̀kan Áfríkà

Lát'ọwọ́ Wikipedia, ìwé ìmọ̀ ọ̀fẹ́
(Àtúnjúwe láti Ìrẹ́pọ̀ Áfríkà)
Flag of Ìṣọ̀kan Áfríkà الاتحاد الأفريقي (Lárúbáwá)African Union (Gẹ̀ẹ́sì)Union africaine (Faransé)União Africana (Potogí)Unión Africana Àdàkọ:Sp iconUmoja wa Afrika (Swàhílì)
Àsìá
An orthographic projection of the world, highlighting the African Union and its Member States (green).
Dark green: AU member states
Light green: Suspended states
Political capitalsEthiópíà Addis Ababa
Gúúsù Áfríkà Midrand
Àwọn èdè oníbiṣẹ́De jure gbogbo àwọn èdè Áfríkà;
de facto Arabic, English, French, Portuguese, Spanish, Swahili[2]
Member States
Àwọn olórí
Paul Kagame
Jean Ping
Idriss Ndele Moussa
AṣòfinIlé Aṣòfin gbogbo ọmọ Áfríkà
Ìdásílẹ̀
25 May 1963
3 June 1991
9 July 2002
Ìtóbi
• Total
29,757,900 km2 (11,489,600 sq mi)
Alábùgbé
• 2011 estimate
967,810,000
• Ìdìmọ́ra
32.5/km2 (84.2/sq mi)
GDP (PPP)2010 estimate
• Total
US$ 2.849 trillion[4][5]
• Per capita
$2,943.76
GDP (nominal)2019 estimate
• Total
US$2.227 Trillion[6][7] }
• Per capita
$1,681.12
OwónínáSee list
Ibi àkókòUTC-1 to +4
Àmì tẹlifóònùSee list
Website
au.int

Ìṣọ̀kan Áfríkà (Gígékúrú bí AU ní èdè Gẹ̀ẹ́sì tàbí UA jẹ́ ẹgbẹ́ ìṣọ̀kan tó ní àwọn Orílẹ̀-èdè Olómìnira Adúláwọ̀ márùnléláàádọ́ta (55) bí ọmọ ẹgbẹ́.[Morocco]] nìkan ni orílẹ̀-èdè Olómìnira tí kìí ṣe ọmọ ẹgbẹ́ àjọ Ìṣọ̀kan Adúláwọ̀ . Ìṣọ̀kan Afrikà jẹ́ dídásílẹ̀ ní ọjọ́ Kẹsàn án oṣù Keje, ọdún 2002 (9-7-2002),[8] Àjọ (AU) ni ó kalẹ̀ sí ìlú Addis Ababa, ní orílẹ̀-èdè Ethiopia.


Àwọn ọmọ ẹgbẹ́

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]

Àwọn orílẹ̀-èdè ìsàlẹ̀ wọ̀nyí ni ọmọ ẹgbẹ́ Ìṣọ̀kan Áfríkà:[9]



Àwọn Ìtọ́ka sí

[àtúnṣe | àtúnṣe àmìọ̀rọ̀]